YO/Prabhupada 0638 - That is the First-class Yogi, Who thinks of Krishna Always



Lecture on BG 2.30 -- London, August 31, 1973

Beena ninu gbogbo nkan lon ri Krsna. Premāñjana-cchurita-bhakti-vilocanena santaḥ sadaiva hṛdayeṣu vilokayanti (Bs. 5.38). Sadaiva. Nigbami awon eyan man bere, " Seti ri Oluwa?" Awon eyan tonje olufokansi, olufokansi giga, Krsna nikan lon ri, kori nkan imi. Premāñjana-cchurita-bhakti-vilocanena santaḥ sadaiva hṛdayeṣu (Bs. 5.38). nigbogbo'gba nitumo Sadaiva. Hṛdayeṣu vilokayanti. Yaṁ śyāmasundaram acintya-guṇa-svarūpaṁ govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi. Beena teyin base ni ilosiwaju si ninu imoye Krsna, eyin le ri Krsna. teyin ba ko lati ri Krsna nigbogbo'gba, sadā tad-bhāva-bhāvitaḥ... Yaṁ yaṁ vāpi smaran loke tyajaty ante kalevaram (BG 8.6). Yad yad bhāvam. Beena teryin ba ronu nipa Krsna.. itosona Krsna na niyen. Manmanā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65). "E ronu nipa mi nigbogbo'gba." yogi t'ipo kini leleyi, eni to ban ronu nipa Krsna nigbogbo'gba. Yoginām api sarveṣāṁ, mad-gatenāntar-ātmanā, bhajate yo māṁ, sa me yuktatamo mataḥ (BG 6.47). yogi lati'po kini loje. Bibeko, kilode toye ko ronu nipa Krsna? Man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī. Ikan, afi awon bhakta ni kan lole ronu nipa Krsna. Man-manā bhava mad-bhaktaḥ. Nitoripe bhakta mi leje , lati ronu nipa mi ni gbogbo'gba n'ise yin." Se nkan to le njyen? Eyin sin ri Krsna ninu ile ajosin. Beyin se ri Kṛṣṇa, Kṛṣṇa, Kṛṣṇa, Kṛṣṇa si, fun wakati merinlelogun ke wa ninu ise imoye Krsna itumore niwipe eyin ma ni adase lati ri Krsna nigbogbo'gba. Egbe imoye Krsna niyen. Eyin o le gbagbe Krsna fun iseju kan gan. Ilana to wa niyen. Man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65). Awon nkan merin. Ti irisi OLuwa ba wa ninu ile ajosin, Eyin le wo ko wole sinu okan yin. Teyin baje ninu ile ajosin tojepe eyin le ri ninu okan yin, eti ni ife fun Krsna. Bibeko, teyinba wa si ile ajosin "Idamu leleyi, e jekin gbagbe re." Nkan imi niyen. Sugbon gbogbo ilana yi wa lati ni ife fun Krsna. Sa vai puṁsāṁ paro dharmo yato bhaktir adhokṣaje (SB 1.2.6). Bhaktir adhokṣaje. Esin t'ipo kini. Esin to gaju. Imoye Krsna yi lo gaju, ninu gbogbo awon esin. Kilode? Nitoripe on ko awon eyan lati ronu nipa Krsna, Eledumare nigbogbo'gba. Pelu ife, ironu nikan ko. Kosi basele ronu nip'eyan afi teyin ba nife fun. Teyin ba nife enikan, lehin na ele ronu nipa re nigbogbo. Gege bi awon ololufe. Kasowipe omo-okurin at'obirin Beena won nife fun ara won. Beena wansi ma ronu ara won nigbogbo'gba. nigbawo latun ma pade, nigbawo latun ma pade?" Beena man-manā bhava mad-bhaktaḥ. Ele di elesein Krsna, ke ronu nipa Krsna nigbogbo'gba, boti jepe eyin ti nife fun Krsna. Premāñjana-cchurita-bhakti-vilocanena (Bs. 5.38). Pelu bhakti eyin le nife fun Krsna. Nkan t'afe niyen.