YO/Prabhupada 0643 - Those Who Are Advanced, They Have To Work For Krishna



Lecture on BG 6.1 -- Los Angeles, February 13, 1969

Prabhupāda: Beeni?

Olufokansi: Prabhupāda,wanti ko sinu Bhagavad-gita, ka sese ka nisin, pe tawa ba ni'gbagboo ninu Krsna oun na ma pese fun wa. beena ninu Gita wanti salaaye wipe Olorun ma ffun awon eyan ni iranlowo ton ran ara won lowo.

Prabhupāda: Beeni.

Olufokansi: Nisin, bawo lase le mo nkan ..?

Prabhupāda: Pe eyin bosabe Krsna, itumo pe eyin fun ara yin ni iranlowo niyen. Teyin ba rowipe, " Oh mole toju ara mi," lehin na eyin o fun ara yin ni iranlowo kankan. gege bi ekanna yi, toba wa dada ton sise dad, sugbon ti isoro kankan ba wa, mole na aimoye owo lori re. sugbon teyin ba ge ekana yi kuro lati owo mi, teyin ba si temole pelu ese yin pe mi o fe ekana yi mo. Beena iranlowo ara eni niwipe eyin maf'ara yin sinu ipo to da, bi nkankana pelu Krsna. Iranlowo to daju leleyi. Bibeko bawo leyin sele ni iranlowo na? Ekanna yi le fun ara re ni iranlowo to f'ara re si ipo to da lati sise fun ara yi. Ipo to da niyen. Ti ekanna na ba rowipe, " Mofe yo ara mi kuro l'atara eda yi kin fun ara mi ni iranlowo," o ma ku dannu. Beena lesekese teyin ba rowipe " mofe gbe loototo, lai ronu nipa Krsna," iku mi niyen, lesekse tinba sise fuin Krsna bi nkankana pelu re, aye mi niyen. Beena lati fun awon eyan ni iranlowo eyan gbodo mo ara re kosi sise beena. Iranlowo to wa niyen. Laimo nkan ti ipo ara re je, bawo losele ran ara re lowo? kolese se. Beeni?

Olufokansi: Lehin na agbodo sise pel'ogbon kasi gbiynaju lati sise fun Krsna nigbogbo'gba, konse pe Krsna ma sise funwa. Oye keyin ronu lati sise fun Krsna nigbogbo'gba, konse pe ema sowipe afe se nkan bayi bayi, Krsna ma ranwalowo.

Prabhupada: Eyin sise fun Krsna, nkan teyin se niyen. Sise nitumo ise. Kini itunmo pe eyin sise? Lootoro teyin ban sise fun enikan, seyin o se nkankan? Bawo l'Eyin sise fun Krsna? Teyin ba tin lo se iwaasu nipa imoye Krsna, teyin ban se ounje, teyin ban fo idoti, ounkoun teyin se yi. Sise nitumo pe eyin fun Krsna ni iranlowo. Eyin o le fun Krsna ni iranlowo teyin ba joko sibikan. Ise imoye Krsna niyen. Ounkoun teyin ba ni, elo lati fi sise fun Krsna. bhakti niyen. Nisin, ounkoun tabani? Awa sini okan wa. O dabee, elo fun Krsna. Awa ni owo yi - efi fo ile ajosin tabi kefi se ounje fun Krsna. Aw si ni imu - efi fi gbohorun awon idodo tonti fi s'adura si Krsna. Beena eyin le sise. beena itumo imoye Krsna yi niwipe eyin sise. Arjuna, kofe sise. Krsna sife ko sise. Gbogbo Bhagavad-gita leleyi. Aima sise ko nitumo imoye Krsna. Lati sise ninu imoye Krsna nitumo ise sise - fun Krsna. Krsna o sowipe, looto ninu apa iwe yi Krsna sowipe.... Ko sowipe, Ore mi Arjuna, ma ronu nipa ile aye yi. Joko ko gbo mi kosi sasaro le Mi." Seyin ri irun nkan bayi ninu Bhagavad-gita? Lati fi ipaari si gbogbo awon iranu wanyi nitumo sasaro yi, kejoko sibikan. Sugbon fun awon ton ni ilosiwaju ninu imoye Krsna, won gbodo sise fiun Krsna. Gege bi omode. Ton faajogbon ni ile. Iya re ma sowipe, " Omo mi, joko sibi kan." Sugbon teyin ba sise dada, " Oh beeni, iya re ba bere, " omo mi, se'wo lose nkan bayi bayi." Awon oniranu loye kon joko sibikan, awon t'ologon koye kan se. Fun iranu yi, toba se joko si beena koni se awon iranu wanyi mo, otan. Pe eyan o huwa iranu, konsepe onitoun je eni to da. Ise rere leleyi. Aimase ko kin se ile aye gidi. Ile aye to da. " Mase bayi," ile aye gidi ko ni o koniyen. " Se bayi," Ile aye to da niyen. Sugbon lati huwa dada o ni awon nkan tio ye ka se. " Aima se" ile aye gid ko niyen, " Se" ile aye gidi niyen. Gbogbo Bhagavad-gita wa lori eto se bayi. " Jagun funmi." Kosi nkankan " ne fait pas," Arjuna si fe, " Ma fi iru nkan bayi sinu okan mi," Krsna o si feran iru nkan bayi. " On soro bi awon eyan tio kinse Aryan," Kutas tvā kaśmalam idam. Anārya-juṣṭam (BG 2.2). " Iru awon oro bayi ni awon eyan tio kin se Aryan man so." Wansi pe leni tio kin se Aryan. Anarya. Beena lati joko sibi kan ko nitumo imoye Krsna, rara. Awa sini awon akoko idaray ti Krsna gbogbo e lo kun fun ise ti Krsna se. Teyin ba losi odo metalokan, Krsna sin n'jo nigbogbo'gba. Eyin ma jo, eyin ma tun jeun fun wakati merinlelogun. Igbawo leyin fe joko? Kosejo pe eyin fe joko. Seyin ti gbo pe awon gopi joko ton sasaro? Wan joko. ( erin) Seyin ti gbo ri? Krsna... Oluwa Caitanya Mahaprabhu? Kilo se? Ijo lon jo, Hare Krsna, se ri bayi? Seri bayi, emi leje, kosi beyin se fe dake? Kolese se. Arjuna o gba,... Eyin ma ri ninu apa iwe kan nigbaton sofun Arjuna, " Arjuna mi, joko ko sasaro." Lesekese lo ko. " Krsna mi, kolese se funmi. kolese se funmi." Otooro niyen. Bawo lose se fun? Onile loje,, osi fe ijoba re, osi fe d'olori ijiba na. Asiko wo loni lati fi sasaro? Ko gba rara. "Krsna mi, kolese funmi." O sowipe lati ni idari lo okan: vāyor iva suduṣkaram. " O si le gan bi eni to fe mu ategin dani." Otooro niyen. EYin gbodo fi okan yin lori Krsna. Lehin na o ma ni idari. Bibeko, eyin o le se fun ara yi. Kolese se. Nkan ti Arjuna so niyen, kama wa soro nipa awon elomi. Arjuna, tani Arjuna? Eni ton ba Krsna soro. Seyin rowipe eyan lasan niyen? Oun gan sowipe kolese se. Vāyor iva suduṣkaram (BG 6.34).

Ati funyin ni apeere yi. Cañcalaṁ hi manaḥ kṛṣṇa pramāthi balavad dṛḍham (BG 6.34). "Krsna mi, eyin fe kin ni idari lori okan mi. Osi lagbara toje wipe, kosile duru sibi kan, - " Mo rowipe osi rorun ju lati mu ategun dani ju." Ti ategun ban fe ga, seyin le daduro? Beena apeere to funwa niyen. Eyin leni idari lori okan teyin bafi okan yi sori ese Krsna. Otan. Iranu kankan o le wa sinu okan yin., Krsna nikan. Ipo to gaju lori eto sasaro niyen.