YO/Prabhupada 0648 - By Nature We Are Living Entities, We Must Act



Lecture on BG 6.2-5 -- Los Angeles, February 14, 1969

Olufokansi: Alaye: " Teyin ban sise ninu ise pipe Oluwa, o le ni idunnu ni ara re, kode ni bosinu igbadun iye ara re tabi ise ijeere. Bibeko, eyan gbodo sise ninu igbadun iye ara re nitoripe kosi basele gbe lai gbadun ara wa."

Prabhupada: Beeni, koko oro to wa niyen. Agbodo ni ise gidi tanse. Awa o le fi ipaari si apeere kana. Eyin o le sofun omode ko ma sise mo. Iwa adayeba won eda niyen, agbodo ma sise. kolese se pe awa fe fi ipaari si awon ise wanyi. Beena geg bonse so," Ile ese esu ni Opolo tio ni nkankan se." Beena t'awa o ba ni nkan gidi se awa ma bere sini sise iranu. Gege bi omode, tio ba keeko, a bere sini huwa kuwa. Beena, ise meeji taniu: boya igbadun iye ara wa, tabi imoye Krsna, tabi bhakti-yoga, tabi yoga. Beena ti mio ba si ninu ilana yoga yi,, lehin na mogbodo gbadun ara mi. tinba wa ninu igbadun iye ara mi, kosejo fun yoga. Tesiwaju.

Olufokansi: Laisi imoye Krsna, eyan gbodo wa awon ise fun igbadun iye ara re. Sugbon eni toba ni imoye Krsna le se gbogbo nkan fun itelorun Krsna beena asi yo ara re kuro ninu igbadun iye ara re. Eni tio ba ni iru imoye yi, asi wa ona eke lati fi kuro ninu ife okan to ni koto le gunke lori abagunke toi yoga."

Prabhupada: Abagunke Yoga." Abagunke Yoga, wanti fi we abagunke lasan. Ninu ile oke giga awon abagunke wanyi wa. ilosiwaju ni gbogbo awon abgunke yi je, otoooro niyen. Beena a le pe gbogbo abagunke yi ni ilana yoga. Sugbon enikan le wa lori ipo kaarun, ki elomo wa lori ipo aadota, imi lewa lori ipo ogorun maarun, imi le wa lori oke ile na. Beena botilejepe ilana yoga loruko abagunke yi sugobn eni toba wa lori ipo kaarun, egbe ko loje si eni toba wa lori ipo aadota. Tabi eni to ba wa lori ipo aadota, eyin o le fiwe eni towa lori ipo ogorun marun. Beena, ninu Bhagavad-gita, eyin ma ri karma-yoga, jnana-yoga, dhyana-yoga, bhakti-yoga. Gbogbo won l'oruko yoga. Nitoripe gbogbo abagunke parapo pelu ile oke to gaju. Beena gbogbo awon ilana wanyi ni nkan se Pelu Krsna. sugbon iyen osowipe gbogbo awon okurion wa lori ipo to gaju Enito ba wa lori ipo to gaju, oun lole ni oye nipa imoye Krsna. Awon iyoko, won wa lori ipo karun, tabi aadota tabi ogorun maarun, bayi bayi lo. Abaghunke nigbogbo e je.