YO/Prabhupada 0650 - Get Out from this Entanglement by this Perfect Yoga of Krishna Consciousness



Lecture on BG 6.2-5 -- Los Angeles, February 14, 1969

Olufokansi: Ninu ile aye yi, eyan gbodo wa labe okan ati iye ara re. Looto, emi wa ti loopo ninu ile aye yi nitoripe igberaga okan wa tofe ni idari lori gbogbo agbaye. Nitorina, agbodo ko okan wa leeko beena koleni ife fun awon nkan aye yi. bayi ele fun emi aye yi nigbala. Eyan o godo f'arale wole pelu ifarasi awon oun elo iye ara. Teyin ba se ni ifarasi awon iye ara wanyi, beena leyin se ma loopo sinu ile aye yi. Ona to daju lati jade kuro nini iloopo yi ni lati sise fun Krsna. Oro ton fi tenu mo ninu ede Sanskrti ni "hi", itumo re niwipe, eyan gbodo se bayi. Wanti salaye wipe: Fun awon okurin, okan wa ni'di fun iloopo wa, oun na nidi fun ominiran wa. T'okan yin ba feran awon iye ara wanyi, idi fun idimu yin niyen toba si gbokan kuro idi fun ominiran re niyen. Nitorina lati ni ominiran agbodo f'okan wa sinu imoye Krsna."

Prabhupada: Beeni. Ko s'aye kankan. Okan wa gbodo wa ninu imoye Krsna nigbogbo'gba, koni s'ona fun lati sise ninu imoye Maya. Taba se lo okan wa si ninu imoye Krsna, beena lase ma bosinu ina orun, kosi beyin sele wonu okunkun. bi Ilana yi seri niyen. Bese fe nani. Ele joko sinu okunkun ninu yara,m tabi ke jade sinu ina orun Beba sefe si . Sugbon teyin ba bosinu ina orun kosi besele waonu okunkun. Ina ma yo gbogbo okunkun na kuro, sugbon kosi bi okunkun sefe yo ina kuro. Kasowipe eyin wa ninu yara to dudu. Teyin ba mu atupa kan wole, Okunkun na titan. Sugbon teyin bamu nkan to dudu wonu ina orun, oma yoo kuro. Beena kṛṣṇa sūrya-sama māyā andhakāra. Ina orun ni Krsna je, ni okunkun ni maya je. Kini okunkun fe se ninu ina orun? E duro sinu ina orun. Kosi b'okunkun se fe mu yin. Ilan imoye Krsna niyen. E sise ninu imoye Krsna nigbogbo'gba. Maya o le fowokan yin. Nitoripe kosi b'okunkun sefe sise ninu ina. Nkan ti Śrīmad-Bhāgavatam so niyen. Pe nigbati Vyasadeva, pelu itosona oluko mimo re Narada, pel'ona bhakti-yoga: bhakti-yogena praṇihite samyak, praṇihite 'male. Bhakti-yogena manasi (SB 1.7.4). Okan kanna, okan nitumo manasi toba jisoke pelu bhakti-yoga, ina-bhakti, bhakti-yogena manasi samyak praṇihite amale. Leyin igbati gbogbo idoti okan wa ba tan. Bhakti-yoga lole se iru nkan bayi. Bhakti-yogena manasi samyak praṇihite 'male apaśyat puruṣaṁ pūrṇam. O ri Eledumare. Māyāṁ ca tad-apāśrayam. O si ri maya yi leyin re. Apasrayam. Ina ati okunkun, pelu. gege bi ina se wa nibi. Okunkun na si wa, niwonba die beena okunkun yi wa labge ina. sugbon ina o le wa labe okunkun. Beena Vyasadeva ri Krsna, Eledumare, pelu maya, okunklun yi, labe re. Tani maya yi? wanti salaaye. Yayā sammohito jīva. maya kanna, agbara itanraeni kanna ton bo awon eda wanyi. awon wo lon wa labe idimu yi? Yayā sammohito jīva ātmānaṁ tri-guṇātmakam (SB 1.7.5). Botilejepe emi wa dabi ina Krsna tabi Oluwa, sugbon iwonba kekere ni. sugbon osin parapo pelu ie aye yi. Yayā sammohitaḥ, itanraeni niyen. T'awa bati ni asepo pelu ohun elo aye yi. Yayā sammohito jīva ātmānaṁ tri-guṇātmakam, paro 'pi manute 'nartham. Botilejepe owa ni pipe, osin huwa kuwa wanyi. Paro 'pi manute 'narthaṁ tat-kṛtaṁ cābhipadyate. maya sin p'ase fun ise re. Wanti salaaye awon nkan wanyi ninu Srimad-Bhagavatam ninu Iwe kini, apa keje. Bi ipo wa seri niyen. Ina mimo laje, ina sana. Sugbon nisin idaabo agbara aimokan ti bowa, māyā. asin se gbogbo nkanti māyā ba sofun wa, beena ati loopo ninu aye yi. Agbodo jade kuroo ninu idimu yi pelu yoga tabi yoga pipe t'imoye Krsna. Ilana yoga niyen.