YO/Prabhupada 0666 - If The Sun Can Penetrate Within Your Room, Krishna Can Penetrate Within Your Heart?



Lecture on BG 6.13-15 -- Los Angeles, February 16, 1969

Tamal Krishna:"ijoba olorun wa ni ibi gbogbo,sugbon ni orun ati ofurufu-aye to wa wonpe ni paraṁ dhāma,abi ibubge onipelegiga

prabhupada: beni. aye iyonda yi na olorun lo daa ibiyi na ijoba olorun ni,sugbon ati gbagbe ee ati see bi pe olorun ti ku, nitorina ati so di orun-apadi sugbon ti aba gba olorun, ile aye yio di ijoba olorun,laifowoyi nitorina tempili yi ijoba olorun ni,ko kin se aye iyonda o ga ju ile aye iyonda lo,tesiwaju

Tamal Krishna:"akura yogi ti oni oye nipa olorun oba krsna olorun oba ti so funra re nibiyi le gba alaafia ti o gbehin gbe lo si ijoba olorun tabi Kṛṣṇaloka ti amo si goloka vrndavana ninu brahma-samhita won ti so kedere wipe biotilejepe olorun ngbe ni ijoba re ni gbogboigba ti onje goloka gbogbo brahman ati etiile paramatma naa

prabhupada: beni, ti oba rowipe ti krsna olorun ba wa ni ijoba re,goloka vrindavana bawo wani o wa see ro wipe ni tempili re ko si olorun nibe iroo. ninu brahman-samhita osowipe.....nitorina ani lati gboo lodo iya ti won ti fun ni asee brahman-samhita sowipe: goloka eva nivasaty akhilātma-bhūtaḥ (BS 5.37). biotilejewipe o n gbe ni ijoba olorun,goloka vrndavana,owa ni gbogbo ibikibi owani gbogbo ibi, bi apeere ti ale lo pee orun wa ni aadorun million,tabi nko be ,to jina gidi gidi fun wa sugbon ninu iyara ee, abi bowo lon se sooo. oh orun niyi ti orun ba le wo iyara wa,seeee krsna olorun oba agba owo le sinu okan ree ati gbogbo iyara ti owambe owa lasan owani gbogbo ibi,sugbon oni lati yeee bi osee wa ni gbogbo ibi ni ile aye yi, tesiwaju

Tamala Krishna:'kosi eyan Kankan to le de orun,tabi wole si ijoba olorun ti koba ti ni imo ati oye dada ninu olorun krsna,ati apero imugboroosi, visnu nitorina eniyan ti o se ise ninu ijira krsna olorun, ni pipe yogi nitoripe okan re wa ni gbogbo igba ni ironu aseyan-ise sise ti olorun krsna. ninu vedas won ko wa wipe eyan le bori ona ibibi ati iku,afi ti oba mo oye ti adajo eniyan ti olorun oba ni oro miiran,pipee eto yoga ni mimo alaafia lati ni ominira fun ile aye iyonda ere idan tabi are idaraya ni wan fi tann awan eyan ti ko mo owun Kankan,laijebi,

prabhupada: ese gidi gaan gbogbo e niyen opari