YO/Prabhupada 0717 - My Father Was a Devotee, and He Trained Us



Room Conversation -- January 26, 1975, Hong Kong

Prabhupada: Lati ibere aye wa gege bi Prahlada Mahraja se se, kaumāra ācaret prājño dharmān bhāgavatān iha (SB 7.6.1). Omo odun marun loje, lati ibere aye re loni imoye Krsna, Asi ko awon egbe re npa imoye Krsna. Prahlada Maharaja, ni ile eko re, ma sewaasu si awon omode beena egbiyanju lati tele, mahājano yena gataḥ sa panthāḥ (CC Madhya 17.186). E tele awon eyan pataki bi Prahlāda Mahārāja, Dhruva Mahārāja. Omode lon je; sugbon wan si di olufokansi pataki. Awon ton po gan siwa. Awon Kumara, awon ni olufokansi to gaju. beena agbodo gbiyanju. Esu nla ni Baba Prahlāda Mahārāja je. Sugbon Prahlada Maharaj si gbo latenu Narada Muni nigbato wa ninu oyn mama re. Narada Muni sin ko iya re, Sugbon Prahlada Mahraja wa ninu oyn iya re si gbo gbogbo nkian ti Narada Muni so. beena koto jade ninu oyun iya re oti ni ye nipa imoye Bhagavata. Lati ibere aye re loje bhagavta. Olufokansi nitumo Bhagavata.

Ale tele Prahlada Maharaj, Dhruva Maharaja. Niotoror, awon obi na gbodo ran wa lowo. Bibeko, tawa ba se bhagavata-dharma tabi bhati -yoga lati ibere aye wa, ile aye wa ma ni ilosiwaju. Awa si l'orire lati gbo awon eto bhagavata-dhama latigba ta kere. Olufokansi ni baba mi je, osi ko wa. Ise awon obi ni lati ko awon omode ni bhagavata-dharma. Lehin na ile aye wa ma ni ilosiwaju. Bibeko ile aye wa o le se aseyori. A le subu leyikeyi asiko. Pe eyan subu itumo re ni wipe a kuro lori ipo mimo tawa o ba se, a le subu kadi awon eranko. Orisirisi eda lowa laye yi. Eti ri fun ara yin. Eyan le d'ologbo tabi aja na. Sayensi nla leleyi je, sugbon awon eyan o mo, wan o si ko won ninu awo ilem-eko, tabi ile eko giga. Wan o si mo, awon oluko wanyi, kosi ikan ninu won to mo.

Egbiyanju gan lati mo nipa imoye Krsna yi kesi korin Hare Krsna maha-mantr teba lasiko die. O dami loju pe eyin lasiko lati se. Ibeere mi leleyi. nkan tan sewaasu fun leleyi ni gbogbo agbaye.