YO/Prabhupada 0727 - I am the Servant of the Servant of the Servant of Krishna



Lecture on SB 7.9.28 -- Mayapur, March 6, 1976

Bhaktivinoda Ṭhākura ti korin yi śarīra avidyā-jāl, jaḍendriya tāhe kāla. ejo nitumo Kala, kala-sarpa. Kāla-sarpa, ole je wa je leyikeyi asiko, otan niyen. On je wa je , sugbon ore-ofe Krsna lon toju wa. Bibeko, awon iye ara wanyi le pa wa, Kāla-sarpa Ibi ti wa po gan, kāla-sarpa-paṭalī protkhāta-daṁstrāyate. Olufokansin kan sowipe, " awon ejo to po wa pelu mi, ko buru sugbon mole kan eyin won danu." Kilon pe? eyin ejo? Teba yo kuro, kole se nkankan mo. Alebu ara re ti tan ti eyin re ba ti yo. Beena protkhāta-daṁstrāyate. Śrī Prabodānanda Sarasvatī said, kāla-sarpa-paṭalī protkhāta-daṁstrāyate (Caitanya-candrāmṛta 5): Beeni, moti ni awon kala-sarpas mi, sugbon pelu ore-ofe Caitanya Mahaprabhu moti kan eyin won danuu, aya mi o ja mo." Bawo lese se?Pelu Ore ofe Caitanya Mahāprabhu gege bi eteyin ba ka eyin ejo yi.. nitoripe wan man lo mejele ejo fun awon ogun,wan yo jade. lehin na ko wule mo. Sugbon a tun hu. teba yo eyin ejo kuro, a tun hu pada wanti salaaye nibi, bawo lasele se? Kāmābhikāmam anu yaḥ prapatan prasaṅgāt. Ele yo kuro , sugbon toba tun kegbe kegbe, atun hu pada. Kāmābhikāmam. Kama kan lon je ki imi jade, awon ifekufe okan wa. Bayi ni gbogbo nkan wanyi sele. Idi fun iyika ibimo ati iku ile-aye wa. Bhūtva bhūtvā pralīyate (BG 8.19). Beena tawa bafe gba ona bhakti yi, agbodo fi gbogbo eleyi sile. Anyābhilāṣitā-śūnyam (Brs. 1.1.11). Anyābhilāṣitā-śūnyam.

Bawo ni mosele fi gbogbo e sile? Eda nimi. Nigbogbo gba nimon ronu orisirisi nkan." won sowipe nitori awa o mo bi eda aye yi seri nitorina lasen sowipe kon fi gbogbo nkan sile. Kolese se. Awa o le wa ka ma ni ife okan. Nitoripe eda nimo je mo gbodo ni ife kan lokan. nitorina agbosoyi awon ife wanyi si mimo. nkan tafe niyen. eyin o le paare. Kolese se. Sarvopādhi-vinirmuktaṁ tat-paratvena nirmalam (CC Madhya 19.170). Bi ipo wa se je beena ni ife okan wa seri. Hindu nimi, musulman nimi, kilode tefe kin gba imoye Krsna yi?" Nitoripe ipo bayi bayi nimo ni, Hindu nimi, musulman nimi, kilode tefe kin gba imoye Krsna yi?" Olorun awon Hindu ni Krsna. lati Ilu India ni Krsna n=tiwa. Kilode tefe kin gba Krsna s'okan?" Rara. " egbodo yo gbogbo iranu yi kuro lori yin. pe hindu nimi, musluman nimi, krsiteni nimi, omo ilu India nimi, nkan bayi nimi." agbodo ya si mimo. Ogbodo ye wa pe gopī-bhartur pada-kamalayor dāsa (CC Madhya 13.80). Iranse awon iranse Krsna nimi." Iyasi imo niyen. lehin na ele ni ife okan. Lehin na eyin o le ni ife okan afi fun nkan Krsna. Ipo to gaju niyen. Lehin na ema wa sori ipo, nigbateyin o ni fe ju ke sise fun Krsna, fun wakati merilelogun, lehin na eti nigbala niyen. Sarvopādhi-vinirmuktaṁ tat-paratvena nirmalam (CC Madhya 19.170). eti di nirmalam niyen, lai ni idinmu aye yi. ninu ipo yi nikan, hṛṣīkena hṛṣīkeśa-sevanaṁ bhaktir ucyate. iye ara mi asi wanbe; konse pe mo ma di oniranu. Rara. Iye ara mi ma wa. Wan sise. Wan sise fun Krsna, Nkan ta fe niyen. Beena eleyi sese afi teba di iranse Krsna. Bibeko, kolese se.

Ese pupo.

Olufokansi: Jaya Prabhupāda. (ipaari)