YO/Prabhupada 0730 - Siddhanta Boliya Citte - Don't Be Lazy in Understanding Krishna



Lecture on SB 7.9.32 -- Mayapur, March 10, 1976

Prabhupāda: Olorun da nigbgbo igba, sugbon kolpe ye wa, tawa ba ri wipe on se nkan to dabi ese, ese koni yen; Nkan mimo ni. Apeere kann loje: tejīyasāṁ na doṣāya (SB 10.33.29). T'awa ba ya si mimo pelu kiko orin oruko re, bawo ni Olorun fu ara re se fe d'elese? Kolese se. Ogbon ori leleyi. Teyin ba korin oruko mimo re Hare Kṛṣṇa, Hare Kṛṣṇa...

Olufokansi: Kṛṣṇa Kṛṣṇa, Hare Hare/ Hare Rāma, Hare Rāma, Rāma Rāma, Hare Hare.

Prabhupāda: ta si y asi mimo, bawo ni Krsna se fe d'elese? kolese se. Pavitraṁ paramaṁ bhavān. Egbiyanju lati mo Krsna. Isotunmo leleyi, pe sthito na tu tamo na guṇāṁś ca yuṅkṣe. Krsna leleyi. Visnu leleyi, Krsna Awon egbe imi wa ton sowipe awa s'adura si Bala-Krsna, Krsna nigbato je omode." Nigbami won salaaye pe.. Pe " Krsna to da gbe ti ni asise nitori rasa-lila." Seyin ri iranu to wa yi! Krsna ni Krsna je. Oro iranu pe Krsna nigbato je omode da ju Krsna nigbato je agba, oro iranu. gege bi Krsn, nigbato toje omo de osu meta o si pa esu Putana to tobi. se omode osu meta le pa iru esu bayi...? Rara. Olorun ni Krsna je nigbogbo igba, koba je osu meta tabi oduh ogorun meta tabi egaaraun meta, nkankana lo je. Advaitam acyutam anādim ananta-rūpam adyaṁ purāṇa puruṣaṁ nava-yauvanaṁ ca (Bs. 5.33). Krsna niyen. Teba ko nipa Krsna, ele ni igbala. Egbodo ka awon ese iwe wanyi dada, kosi ye yin. lehin na ele ni oye nipa Krsna. Kaviraj Gosvami ti sowipe, siddhānta boliyā citte nā kara alasa, ihā haite kṛṣṇa lāge sudṛdha mānasa. Siddhanta, Kini Krsna, teba ka awon sastras, siddhānta boliyā citte...Ema yole lati ni oye nipa Krsna, nitoripe teba gbiyanju lati ni oye nipa Krsna - sādhu-śāstra-guru-vākyaṁ cittete kariya aikya, through the sādhu, śāstra ati guru - lehin na gbiyanju lati ni oye nipa Krsna, eni toje. Leyin na eyin o le mu bi eyan lasan, bi awon ode sen wo. Avajānanti māṁ mūḍhā mānuṣīṁ tanum āśritaḥ (BG 9.11). Mūḍhās, asiwere, wan rowipe Krsna je ikan bi awa. Eyin o ni je mudha. Eyin ma l'ogbon. Kini ibajade re? Krsna sowipe, janma karma ca divyaṁ me yo jānāti tattvataḥ. Teyin ba ni oye nipa Krsna dada... sugbon o ye wa pe koseni to le mo Krsna ni pipe. Ati kere ju lati mo nipa re nitoripe osi tobi gan. kolese se. Sugbin teyin ba ni oye nipa Krsna, bosele salaaye ninu Bhagavad-gita. Iyen tito lati ran yi lowo. Eyin o le mo nipa Krsna. Kolese se. Krsna gan o le mo nipa ara re Nitorina lose wa bi Caitanya lati mo nipw ara re. Beena kosi besele mo nipa Krsna, sugbon Krsna tin fun wa ni imoye nipa ara re, to le ye wa. Bhagavad-gita niyen. Beena egbiyanju lati ni oye nipa Krsna lati ilana ninu Bhagavad.... Caitanya Mahāprabhu ti funwa ni ominira, yāre dekha tāre kaha kṛṣṇa-upadeśa (CC Madhya 7.128). lati sewaadi nipa Krsna niidi fun ile aye eda eyan. Kosi ise imi. Teba sise yi, ile aye yin ma ni aseyori. Egbe imoye Krsna yi wa fu ise yi. Awa ti si awon ile-ajosin to po lori gbogbo agbaye emu ise yi ni ataki ke gbiyanju lati ni oye nipa Krsna ke ni aseyori l'aaye yin.

Ese pupo.

Oloufokansi: Jaya! ( ipaari)