YO/Prabhupada 0732 - I Cannot Serve the Air or the Sky. I Must Serve a Person



Room Conversation with Yoga Student -- March 14, 1975, Iran

Prabhupada: kini itumo esin sufi? itumo?

Akeko Yoga: Nkanti bhakti je fun awon Hindu ni sufi je.

Prabhupada: Lati sise fun Olorun nituo Bhakti. Se itumo re niyen?

Akeko Yoga: Beeni.

Prabhupada: Beena taba sise f'Olorun, Ogbodo je wipe eyan loje; bibeko bawo lase fe sise fun?

Akeko Yoga: Ninu esin sufi awa ti ri apa Olorun toje pe o dabi eyan...

Prabhuapda: Afi toba j'eyan, bawo lese fe sise fun? Mio le sise fun ofurufu tabi ategun. Mo gbodo sise fun eyan. Kosi ife kankan l'afefe tabi l'ofururufu. Ogbodo jeyan. Okurin tab'Obirin, kosi wahala. bibeko nib ni ife yi wa? tale nife si?

Akeko Yoga: Awon sufi le ri ife ni awon nkan wanyi.. fun apeera, Sufi Ibn 'Arabi, lati oju obirin to lewa..

Prabhupada: lati oju obirin to lewa?

Akeko Yoga: Beeni.

Prabhupada: awon eyan ile aye yi na man ri nkankanna nibe.

Akeko Yoga: Apa ile aye yi niyen.

Prabhupada: Nitorina ninu esin Islam eyin o fe mo nipa irisi Olorun nitoripe iru nkan bayi lese le. lesekese teyin ba ronu nipa irisi wanyi, eyin ma ronu nipa oju obirin to lewa. Iwoo le niyen. Nitorina leyin o se fe mo nipa irisi kankan. Ironu Veda ko niyen. Apāni-pādaḥ javano grahītā: Kol'apa kol'ese." Wan o fe gba wipe irisi Olorun wa. O tun sowipe Veda sowipe javano grahita: " O le gbaoinkoun teba fun." Itumo re niwipe Olorun o ni irisi bi riu tawa, sugbon o ni ara re toyato, bibeko bawo lose fe gba? Bawo lose fe ni ife mi? beena nitorina ninu esin sufi talakoko an o fe gba irisi yi. ijuwe Veda niyen, o l'ara ati wipe kol'ara. Pe kol'ara niwipe ara re yato si tawa, pe o l;ara niwipe ara re je mimo, lee kana. gege bi emi ati eyin.. mowa ninu ara yi sugbon mio kin se ara mi. Emi ko l'ara yi. Sugbon nibo ni ara yi ti wa? Nitoripe mo si l'ara temi nitorina ni aso mi se ni ara na. Aso mi lon boo. Ti mio ba ni owo at'ese bawo ni aso na fe ni owo at'ese? Sokoto mi ko l'ese mi, ese mi wa ninu sokoto na. Beena ara mo ko leleyi; ara mi wa ninu aso yi. Ara gidi mi wa ninu, asmin dehe. Kon se t'aye yi. toba jepe eyin leri ara mi yi koni sejo kankan, emi sugbon won o le ri. Nitorin lon se sowipe " ko l'ara." TI ko ba l'ara bawo ni ara to wa ni ta se wa? Eniton ranso asi ranso pelu ara alaso. bi aso na se l'owo, a le mowipe alaso na lowo. bawo lesele sowipe ko l'ara? Isoro to wa niwipe awa kon wo irisi aso na, awa o le ri eyan ton wo aso na. Alebu to wa ninu oju mi niyen - kon se peu Olorun. Olorun o kin se eni tio l'ara.

Akeko Yoga: A le ri Olorun ni nu ara awon eyan mimo. A le ri Olorun ni nu ara awon eyan mimo.

Prabhupada: Huh? Imi ni yen. Sugbon Olorun fun ara re ni irisi re. Ipaari oro niyen. Sugbon awa o le ri pelu oju wa. Wanti salaaye, ataḥ śrī-kṛṣṇa-nāmādi na bhaved grahyam indriyaiḥ (Brs 1.2.234). Awon iye ara lasan wanyi... Nkankana loje, gege bi mosen ri eyin. Kini mon ri? Ara yin. Eyin na ri ara mi. Ti emi o ba si ninu ara mo, iyepe lasan loje. Ele ti jade koseni to ma soro. teyin ba fipa ti oku kosenito ma bere wipe "kilode teyin sen se bayi?" sugbon t'emi eyan ba wa ninu re, te fi ipa ti bayi, lesekese ni awon eyan ma bere " Kilode teyin sen huwa bayi?" Awon eyan wanyi oni imoye nipa irisi gidi yi. Nitorina lonse sowipe ko l'ara kankan.