YO/Prabhupada 0734 - One Who Cannot Speak, He Becomes a Great Lecturer



Lecture on SB 7.7.19-20 -- Bombay, March 18, 1971

Imoye Sankhya nibi, ijuwe re wa nibi. Awon oun elo merinlelogun,Awon oun elo merinlelogun Nkan mejo t'ara ati t'emi, ati oun ton daa, awon iye ara mewa, iye ara ise, ati iye ara ogbon. mejidinlogun. Awon iye ara, marun. Mejidinlogun ati marun, metalelogun. ati atma, tabi emi. ohun elo merinlelogun, imoye Sankya, wan ti juwe re. Awon alakowe lati Europu wan feran imoye Sankhya yi, Nitoripe wanti juwe awon ohun elo merinlelogun wanyi dada. imoye sankhya. Dehas tu sarva-saṅghāto jagat. Ara mehi lowa, jagat ati tasthuh - ton rin ati eyi tio le rin. sugbon akojopo awon ohun elo merin lelogun wanyi. Atraiva mṛgyaḥ puruṣo neti netīty. Nisin, eyan gbodo wa atma ninu awon nkan merinlelogun wanyi nibo ni atam wa, nibo ni atam wa, nibo ni atam wa" Eyaqn le ri bayi toba tele awon ofin wanyi, ati ilana to wa. O lese se.

anvaya-vyatirekeṇa
vivekenośatātmanā
svarga-sthāna-samāmnāyair
vimṛśadbhir asatvaraiḥ

Ijuwe si, eto si le gan sugbon o se pataki gan. Prahlāda Mahārāja sin salaaye si awon ore esu toni. omo odun marun bawo losen salaaye imoye Sankhya? Nitoripe olufokansi loje, o de ti ko imoye lati awon Olori bi Narada Muni. Mūkhaṁ karoti vācālaṁ paṅguṁ laṅghayate girim. Nitorina wanti juwe ore-ofe oluko mimo, mūkhaṁ karoti vācālam. Odi nitumo Mukham, eyan tio le soro. Oti di elejo pataki. Odi loje sugbon oti di elejo pataki, mūkhaṁ karoti vācālam. Paṅguṁ laṅghayate girim, aro ti o lerin, o le gun ori oke ipata. Mūkhaṁ karoti vācālaṁ paṅguṁ laṅghayate... Yat kṛpā tam ahaṁ vande, pelu ore-ofer re ni iru nkan bayi leseles, mosi teriba fun. Param ānanda bhavam, Olorun, toni gbogbo indunnu aye yi. Pelu ore-ofe Krsna o lese se. Pely isiro aye yi, kole sese. Pelu isiro aye y, eyan ma bere wipe " Bawo losefe se? E sowie odi ti soro dada? Kolese se." Tabi Aro tin gun ore oke ipata? Kolese se. Sugbon pleu ore-ofe Krsna ati awon alabasepo re.... Gege bi Prahlāda Mahārāja, omo odun Marun, ton salaaye ni pa emi dada. Kilode? Nitioripe oti ni ore-ofe Nrada Muni, alabasepo Krsna. Nitorina o lese se.