YO/Prabhupada 0736 - Give up all These So-called or Cheating Type of Religious System



Arrival Lecture -- Calcutta, March 20, 1975

Esin ko ni Śrīmad-Bhāgavatam yi je o sowipe, " esin gbodo je ti'ipo kini," sa vai puṁsāṁ paro dharmaḥ, " to gaju." Awon Hindu, Musluman, Kristeni, prakrta, iranu. Sugbon agbodo koja gobgbo eleyi Hindu nimi, Musluman nimi, Kristeni nimi." Wura ni wura je. Ein o le sowipe Wura Hindu tabi Wura Kristiani, tabi Wura Musluman. Nitoripe wura na wa lowo eni toje Hindu, tabi Musluman, koseni toma sowipe, wura musluman niyen, tyabi wura Hindu." gbogbo eyan ma sowipe " wura niyen." Agbodo wa wura yi- ema wa wura hindu tabi wura musluman tabi wura Kritsteni. Nigbati Olorun Krsna sowipe, sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66), Ko sofun awon esin Hindu tabi Musluman. Isasoto ni gbogbo eleyi. Agbodo wa sori ipo yi, ipo mimo, tio ni awon isastoto wanyi. Ahaṁ brahmāsmi: Nkankana nimo je pelu Krsna." Esin gidi leleyi. Laisi ironu bayi, prkrta ni esin ma je. Kole ni ipo mimo yi.

Beena egbe imoye Krsna yi wa lori ipo giga, paro dharmah. Sa vai puṁsāṁ paro dharmaḥ. Lori nitumo Para, lori awon esin iranu wany. Awa ko la da sile. Gege bose wa ninu Srimad-Bhagavatam niyen ni ibere, dharmaḥ projjhita-kaitavaḥ atra: "gbogbo awon kaitavah, nkan eke, aimokan," kaitavah. Iyanje nitumo Kaitavah. " Iru Esin ton tan awon eyan je agbodo junu, projjhita. Prākṛṣṭa-rūpeṇa ujjhita. gege bi awa sen gbale, ama mu idoti to wa a sin sonu, beena, lati ni imoye Krsna itumore niwipe ati fi gbogbo awon iranu ati esin eke wanyi sile. Nitoripe pelu ijerisi wa ati ri wipe ninu gbogbo awon esin wanyi, koseni toti de ipo lati ni fe fun Olorun. Koseni toti deebe. Ijerisi wa niyen. Śrī Kṛṣṇa Caitanya Mahāprabhu, lo daale. Sugbon Oluwa Krsna na ti salaaye wipe Esin to daju leleyi, mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja. Esin leleyi." Awon esin iyoku, ti o le ko awon elesin lati nife Olorun, esin Itanje lasan niyen. Caitanya Mahāprabhu sowipe, premā pum-artho mahān. Ati Bhagvata nkankan loje. Ilosiwaju gidi ni basele nife Olorun tabi Krsna. Ipo to gaju laye yi leleyi.