YO/Prabhupada 0739 - We Shall Try to Construct a Very Nice Temple for Sri Caitanya Mahaprabhu



Lecture on CC Adi-lila 1.6 -- Mayapur, March 30, 1975

Akowe Caitanya-caritāmṛta, Kṛṣṇadāsa Kavirāja Gosvāmī, ti salaaye idi fun ifarahan ti Sri Caitanya Mahaprabhu. Krsna fe mo " kilo wa ninu Radharani?" Madana -mohana l'oruko re. Gbogbo eyan loni ifarasi Krsna, ati orisa ife gan, Madana. Gbogbo eyan ni ifarasi Madana, sugbon oun ni Madana-mohana. Radharani ni Madana-mohana-mohini, itum re niwipe oun lo fa Madana-mohana s'ara. Nitorina Krsna fe ni oye yi, "Kilo wa ninu Radharabni toje pe moni ifarasi? Gbogbo agbaye yi ni ifarasi mi, sugbon oun lon fa mi." Pelu ironu yi, Śrī Caitanya Mahāprabhu, tad-bhāvāḍhyaḥ lobhāt. aawon itan ife to gaju leleyi. Lobhat: anfaani lati ni oye na. Tad-bhāvādhyaḥ samajani: " Osi farahan ninu oyun Saci." Samajani śacī-garbha-sindhau harīnduḥ. Hari, Olorun dabi Osupa. Beena ati da ile-ajosin yi sile, Māyāpur-candrodaya. Sri Caitanya Mahaprabhu dabi osupa. Sri Caitanya Maharabhu farahan ni ile Mayapur, nitorina lon sen pe l'Osupa." Nitorina lasen so candra, Mayapur-candra. Nisin Sri Mayapur-candra ti jade... On jade itumo re niwipe on pin ina osuoa yi fun gbogbo agbaye. Anfaani to wa niyen, ina osupa. Śreyaḥ-kairava candrikā-vitaraṇam. Śreyaḥ-kairava. Caitanya Mahāprabhu to so fun ara re. Ema fi Sri Caitanya Mahāprabhu sinu yara yin, kesi gba owo. Awa o fe yen. Egbodo jeki Sri Caitanya Mahaprabhu dide soke si ki ina osupa yi ba letan ni gbogbo agbaye. Nkan tafe niyen. Nitorina ni awon ile-ajosin yi se wa. Asi fe ko il-ajosin to da fun Sri Caitanya Mahaprabhu. Laaro yi asi ronu nipa oro na. Lati ibi ina osupa yi ma jade, Sri Caitanya Mahaprabhu, ke pin Śreyaḥ-kairava-candrikā-vitaraṇaṁ vidyā-vadhū-jīvanam. Egbe Hare Kṛṣṇa Śrī Caitanya Mahāprabhu Paraṁ vijāyate śrī-kṛṣṇa-saṅkīrtanam. Oro ti Śrī Caitanya Mahāprabhu so fun ara te leleyi. Ceto-darpaṇa-mārjanam bhava-mahā-dāvāgni-nirvāpaṇaṁ śreyaḥ-kairava-candrikā-vitaraṇaṁ vidyā-vadhū-jīvanam (CC Antya 20.12). Vidyā-vadhū-jīvanam. imoye to daju leleyi. Awon eyan ni gbogbo agbaye wa ninu okunkun. Ina Osupa yi ma tan. Ode ni awon eyan yi, mudha. Wanti salaaye ninu Bhagavad-gita

na māṁ duṣkṛtino mūḍhāḥ
prapadyante narādhamāḥ
māyayāpahṛta-jñānā
āsuri-bhāvam āśritaḥ
(BG 7.15)

Awon eyan yi loasiko tawa yi.. Nkan ibanuje loje pe awon eyan yi sin se bi alakowe, oniselu, sugbon pelu oro Krsna ninu Bhagavad-gita, ode ati'oniranu nigbogbo won. Kilode? Na māṁ duṣkṛtino mūḍhāḥ pra... won o fe teriba fun Krsna. Krsna ti faraha, lori agbaye yi lati bere ke teriba. Sarva-dharmān parityajya mām ekam (BG 18.66). Sugbon won o se. Nitorina ni Śrī Caitanya Mahāprabhu, olufokansi Krsna... osi je Krsna fun ara re.

namo mahā-vadānyāya
kṛṣṇa-prema-pradāya te
kṛṣṇāya kṛṣṇa-caitanya-
nāmne...
(CC Madhya 19.53)

Krsna loje fun ara re. Krsna si l'aanu gan funwa. Ni alakoko owa bi Olorun Osi soro bi Olorun " E teriba", awon eyan o gba. Nitorina Krsna tunn oada wa bi Oloufokansi, kṛṣṇa-caitanya-nāmne, Oti wa funyin ni Krsna, pelu ife Krsna l'ofe. Egba ke pin lori gbogbo agbaye. Nkan tafe niyen. Ese pupo. Olufokansi: Jaya Śrīla Prabhupāda.(Ipaari)