YO/Prabhupada 0145 - Agbudo gba tapasya die sara



Lecture on SB 3.12.19 -- Dallas, March 3, 1975

ko rorun lati ni Ominira. gege bi eyin seni aisan. teba ni'iba tabi inira, nitorina egbudo gba inira die s'ara gege bi eyan toba l'ewo l'ara. Inira to po gan niyen. teba fe se'wosan fun, egbudo gba iṣẹ abẹ Nkan tawan pe ni tapasā niyen. Inira ni itumo tapa. gege na teba tanna soke titi de ìpele 110, kosi besele faramo. Nitoripe inira to po gan loje. awa gan taje omo-ilu India ti oorun ba koja ogorun a sooro lati faramo. kawa ma so tryin? Ton bi yin sinu ojo-oju to tutu. sugbon kosi basele yi oru yi lole. toba si kere ju aadota lo, kosi basele faramo na. gege na orisirisi oju-ojo lowa. Ni Orile-ede Canada awon eyan le faramo otutu to koja ti yinyin lo. Oro iyato laarin aye orisirisi. sugbon awa ti baramo: oru tabi otutu. sugbon ale ko lati faramo orisirisi nkan taye ba funwa. awa si l'agbara yi. osi ni owe Bengali kan, śarīre na mahāśaya ya sahabe taya saya, itumo re niwipe, ara wa le farama orisirisi nkan teba le ko". Egbudo mo besele faramo orisirisi nkan laye yi.

laye isin koseni ton lo mo. Sugbon laye-atijo awon eyan man losi ori-oke Himalaya. nipa eto tapasya... Osini besele ko: Ninu oorun to po gan, awon ẹni mimọ wansi tanna repete. Oorun towa si po gan sugbon wansi tonna to tobi gan, kon to gbadura. Itumo tapasya niyen. Oru towa sin mu gan sugbon wansi tonna ti otutu to koja yinyin bawa, wansi wonu omi lo, lati je ki ara wan baramu pelu otutu yi konto gbadura. itumo tapasya niyen. Lati ni oye nipa Olorun teletele, awon eyan man se orisirisi nkan toje inira fun wan, sugbon lasiko tawayi, awan eyan yoole gan toje pe o le gan lati tele awon ofin merin tani? so le gan? awa ti fun yin ni tapasya, " ema se awon nkan bayi mo. Ema se asepo laarin okurin ati obirin, ema moti, ema jeran, ema ta tete." awon nkan to wa ninu tapasya niyen tole jeka ni ilosiwaju ninu imoye Krsna. So le gan? Ko le rara. teyan ba le wonu omi tutu, seyen le ju pe koma ni asepo laarin okurin at'obirin, ati koma jeran ati wipe koma moti? Kon sepe awan sowipe ema ni imo ako tabi abo, sugbon e se pelu iyawo yin tabi Oko yin nikan. Kilo le nibe? sugbon aye yi ti baje tojepe, tapasya die sooro lati se. kilo le nibe.

Sugbon teba fe monipa Olorun bose so nibi, tapasaiva, kosona mi afi tapasya, ona soso tele gba lati fi mo nipa re niyen. Bibeko ko s'ona mi. Bibeko kolesese. Nitorina lonse lo oro na, tapasaiva. Tapasā eva: " ko s'ona afi tapasya." Ko s'ona mi. Tapasā eva param. Itumo Param ni oun to Gaju lo. Teba fe monipa Eni to gaju, egbudo faramo awon tapasya die. Bibeko kolesese. egbudo gba tapasya die nibere. gege bi ekādaśī. iru tapasya kan na loje. ni oto-oro ni ojo ekādaśī koye ka jeun, tabi ka momi gan. sugbon ninu egbe wa awa osi je ko le ju. awa ma sofun yin pe ni ojo Ekādaśī, eje eso, kemu war die si." tapasya niyen. Kilode tawa o le se tapasya yi? Ti awa o ba le se tapasya die yi, bawo lase fe pada losi ijoba orun? Rara, kole sese. Nitorina wan se sowipe, tapasaiva, tapasā eva. Dandan ni itumo Eva. Egbudo se. besen s tapasya yi, seyin tini ipadanu kankan? Olofo koni yin. Nisin awon eyan ton wa si egbe wa, gbogbo wan lon sowipe awon okurin ati obirin yin wan dan. Nijokan nigbati mon lo si Los Angeles lati Hawaii, oni àlùfáà kan to ri mi. osi wa bami ninu oko-afefe. Lehin o bere lowo, " semo le bayin soro?" Beeni, se kosi?" Ibeere alakoko to sofunmi niwipe " moti ripe awon akéköô yin sini oju ton dan gan. Bawo lonse se?" Eyan to feran ooto loje. Ibo ni ipadannu wa ninu oro yi? Kini nkan tasonu base fi awon nkan iranu yi sile. Awa si fe gbe aye to rorun . Ale joko si ilele, ale sun si ilele. Awa si fe awa aga to po, tabi aso toaso topo. Dandan niwipe agbudo se tapasya die taba feni ilosiwaju ninu aye mimo wa, agbudo gba tapasya die sara. Ni aye Kali-yuga, o le gan lati gba awon tapasya to sooro sara, taba wonu omi, lati korin Hare Kṛṣṇa eyan ku ninu e Kole sese mo. sugbon agbudo se tapasya. Oyeko yewa wipe tabafe ni ilosowaju nipa eto Olorun agbudo gba tapasya die sara. Nkan tafe niyen.