YO/Prabhupada 0624 - The God is also Eternal and We are also Eternal



Lecture on BG 2.13 -- Pittsburgh, September 8, 1972

Beena agbodo gba imoye yi lati awon olori. Krsna lon soro nibi. Oun l'olori. Awa ti gba Krsna: Eledumare. Imoye re wa ni pipe. O mo oun toti sele seyin, nisin ati l'ojowaju. Nitorina, oun lon ko Arjuna, "Arjuna mi, emi towa ninu ara eda yi ma wa tayeraye." Otooro niyen. gege bose yemi, Mowa teletele, mowa nisin, beena mosi mawa loojowaju. Awon asiko akoko meta towa leleyi, asiko toti koja, isin, ati ojo waju. Nibomi ati ka ninu Bhagavad-gita wipe, na jāyate na mriyate vā kadācit. Awon eda o le ni ibimo; kode le ku. Itumo Na jāyate niwipe kole ni ibimo. Na jāyate na mriyate, kode le ku. Nityaṁ śāśvato 'yam, na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). O ma wa tayeraye, śāśvata. Na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). Ti ara eda yi ba pari gan, emi wa o le ku. Awon Upanisads, Veda ti jeerisi: nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām eko bahūnāṁ vidadhāti kāmān. Oluwa wa tayeraye, awa na wa tayeraye. Nkankanna laje pelu Oluwa. Gege bi wura ati erunrun wura; wura ni awon mejeeji na. Botilejepe erunrun nimi, erunrun wura tabi emi, emi nimi. Beena awa ti ni imoye yi pe Olorun ati awa na, awon eda, awa tayeraye. Nityo nityānām, tayeraye nitumo nitya.

Beena awon oro meji towa niyen. Ikan je eleyo, nitya, tayeraye, ikeji ju ikan lo, nityanam. Beena awa na ju ikan lo. Awon oonka tonju ikan lo won wa tayeraye. Awa o mo nkan t'agbara won eda laye yi je. Wanti juwe won bi asankhya. lai siro iye won nitumo Asaṅkhya. Aimoye. Kini iyato laarin awon ookan eleyo ati opolopo? Awon onka opolopo farale awon onka eleyo. Eko bahūnāṁ vidadhāti kāmān. Onka eleyo yi lon fun onka opolop yi ni gbogbo nkan tofe, awon eda. Otooro niyen, ati yeewo pelu ogbon wa. NInu awon iye 8,400,000 eda orisirisi towa, awon eda eyan awa la kere ju. sugbon awo iyoku, won poju wa lo. Gege bi omi. Jalajā nava-lakṣāṇi. eda 900,000 lowa ninu omi. Sthāvarā lakṣa-viṁśati; ati 2,000,000 irisi orisirisi ninu ijoba awon ewe, igi at'eso. Jalajā nava-lakṣāṇi sthāvarā lakṣa-viṁśati, kṛmayo rudra-saṅkhyayaḥ. Ati awon kokoro, won to 1,100,000 eda orisirisi. Kṛmayo rudra-saṅkhyayaḥ pakṣīṇāṁ daśa-lakṣaṇam. ati awon eye, won pe 1,000,000 eda Awon eranko, paśavas triṁśa-lakṣāṇi, 3,000,000 orisirisi eranko pel'ese merin. catur-lakṣāṇi mānuṣaḥ, awon eda eyan won to 400,000. Ninu won, opolopo niwon o laju.