YO/Prabhupada 0709 - Definition of Bhagavan: Difference between revisions
(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0709 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1973 Category:YO-Quotes - Le...") |
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists) |
||
Line 7: | Line 7: | ||
[[Category:YO-Quotes - in India, Bombay]] | [[Category:YO-Quotes - in India, Bombay]] | ||
<!-- END CATEGORY LIST --> | <!-- END CATEGORY LIST --> | ||
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE --> | |||
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0708 - The Difference Between the Life of the Fish and My Life|0708|YO/Prabhupada 0710 - We're Making Millions and Trillions of Ideas and Becoming Entangled in Those Ideas|0710}} | |||
<!-- END NAVIGATION BAR --> | |||
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK--> | <!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK--> | ||
<div class="center"> | <div class="center"> | ||
Line 19: | Line 22: | ||
<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page --> | <!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page --> | ||
<mp3player> | <mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/730113BG.BOMBAY_clip1.mp3</mp3player> | ||
<!-- END AUDIO LINK --> | <!-- END AUDIO LINK --> | ||
Line 29: | Line 32: | ||
Bhagavān. Isotunmo Bhagavān wa. Konsepe oniranun a sowipe Bhagavān loun je. Rara. Parasara Muni, baba Vyasadeva ti salaye nkan ti Bhagavān je. Ola nitunmo Bhaga, eni to l'ola yi nitumo van. gege bi awa na ti jerisi. Enikeni toba l'owo, gbogbo eyan lo feran re. A lewa. Awon eyan asi loba fun iranlowo. Eyan toba nipo gidi, eyan na ma lewa. Eni toba lokiki, eni na ma lewa. Eni toba logbon, oun na ma lewa. Enito ba gbo, oun na ma lewa. eni tioba nife fun awon nkan aye yi oun na ma lewa... Enito ni gbogbo nkan aye yi sugbon to fi gbogbo e sile, ti ko loo fun ara re. gege b'eyan ton se saara, ton fun awon eyan ni nkan. Oun na lewa. Beena awon ola mefa leleyi. Beena eni toba ni awon ola mefa wanyi ni pipe nitumo Bhagavān, eyan bayi ni Bhagavān. Kon se awon oniranu kan loju titi ton pera wan ni Bhagavān. Rara. Iyanje niyen. Awon eyna o mo itumo oro Bhagavān, nitorina lon sen gba awon oniranu wanyi bi Bhagavān. Aisvaryasya samagrasya. Ola. Awon olowo po ni ile Bombay, sugbon koseni tole sowipe " Emi nimo l'ola gbogbo aye. Gbogbo owo ninu awon ile-owo, emi nimo ni gbogbo e." Koseni tole sobe. Sugbon Krsna le sobe. Aisvarayasya samagrasya. Ola nitumo Smagra, iwonba kekere ko. Samagra. Aiśvaryasya samagrasya vīryasya. Agbara, ipo gidi. Viryasya. Yasasah, oruko re. gege bi Krsna se so Bhagavad-gita yi ni odun egberun marun seyin, sugbon tit d'ooni nigbogbo agbaye wansi lo oro na. Ninu orile India nikan ko, ni gbogbo agbaye. Wan mo nipa Bhagavad-gita ninu gbogbo awon orile ede aye yi, lai wo ede, tabi esin. Gbogbo awon eyan lon ka, awon eyan ton l'ogbon awon alakowe. Itumo re niwipe olokiki ni Krsna. gbogbo eyan lo mo. | Bhagavān. Isotunmo Bhagavān wa. Konsepe oniranun a sowipe Bhagavān loun je. Rara. Parasara Muni, baba Vyasadeva ti salaye nkan ti Bhagavān je. Ola nitunmo Bhaga, eni to l'ola yi nitumo van. gege bi awa na ti jerisi. Enikeni toba l'owo, gbogbo eyan lo feran re. A lewa. Awon eyan asi loba fun iranlowo. Eyan toba nipo gidi, eyan na ma lewa. Eni toba lokiki, eni na ma lewa. Eni toba logbon, oun na ma lewa. Enito ba gbo, oun na ma lewa. eni tioba nife fun awon nkan aye yi oun na ma lewa... Enito ni gbogbo nkan aye yi sugbon to fi gbogbo e sile, ti ko loo fun ara re. gege b'eyan ton se saara, ton fun awon eyan ni nkan. Oun na lewa. Beena awon ola mefa leleyi. Beena eni toba ni awon ola mefa wanyi ni pipe nitumo Bhagavān, eyan bayi ni Bhagavān. Kon se awon oniranu kan loju titi ton pera wan ni Bhagavān. Rara. Iyanje niyen. Awon eyna o mo itumo oro Bhagavān, nitorina lon sen gba awon oniranu wanyi bi Bhagavān. Aisvaryasya samagrasya. Ola. Awon olowo po ni ile Bombay, sugbon koseni tole sowipe " Emi nimo l'ola gbogbo aye. Gbogbo owo ninu awon ile-owo, emi nimo ni gbogbo e." Koseni tole sobe. Sugbon Krsna le sobe. Aisvarayasya samagrasya. Ola nitumo Smagra, iwonba kekere ko. Samagra. Aiśvaryasya samagrasya vīryasya. Agbara, ipo gidi. Viryasya. Yasasah, oruko re. gege bi Krsna se so Bhagavad-gita yi ni odun egberun marun seyin, sugbon tit d'ooni nigbogbo agbaye wansi lo oro na. Ninu orile India nikan ko, ni gbogbo agbaye. Wan mo nipa Bhagavad-gita ninu gbogbo awon orile ede aye yi, lai wo ede, tabi esin. Gbogbo awon eyan lon ka, awon eyan ton l'ogbon awon alakowe. Itumo re niwipe olokiki ni Krsna. gbogbo eyan lo mo. | ||
Beena aisvaryasya. nigbato wa lori aye yi, osi fi gbogbo ola re fihan. Narada Muni si fe ri bi Krsna sen toju awon iyawo 16, 108 toni. beena nigbat Narada Muni dey o wonu gbogbo awon ile oba. ile oba 16, 108 lo wa, gbogbo wan pelu okuta iyebiye Kosi idi fun ina lale, gbogbo ile oba yi lo kun fun awon okuta iyebiye. Pelu wura ati eyin erin lonfi se awon aga. Ola. Ogba wan kun fun igi parijata. Iyen nikon ko, Narada Muni si ri wipe Krsna wa pelu gbogbo awon iyawo re leekona, ton se orisirisi nkan . Nibomi o joko pelu iyawo at'omo re. Nibomi on s'ayeye pelu awon omo re. Orisirisi nkan. nkan ton pe l'ola niyen, owo. Konse pe enikan ni tola wura die, eni na ti d'Olorun. Rara. Bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ sarva-loka-maheśvaram ([[Vanisource:BG 5.29|BG 5.29]]), suhṛdam... Krsna ti salaye pe " Emi ni onigbadun to gaju." Bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ sarva-loka-maheśvaram. " Emi l'olori gbogbo isogbe aye yi. Ola niyen je. Agbara, lori eto yi, Krsna, nigbato kere pelu osu meta, lori ese mama re, o fiku awon esu to po ga. | Beena aisvaryasya. nigbato wa lori aye yi, osi fi gbogbo ola re fihan. Narada Muni si fe ri bi Krsna sen toju awon iyawo 16, 108 toni. beena nigbat Narada Muni dey o wonu gbogbo awon ile oba. ile oba 16, 108 lo wa, gbogbo wan pelu okuta iyebiye Kosi idi fun ina lale, gbogbo ile oba yi lo kun fun awon okuta iyebiye. Pelu wura ati eyin erin lonfi se awon aga. Ola. Ogba wan kun fun igi parijata. Iyen nikon ko, Narada Muni si ri wipe Krsna wa pelu gbogbo awon iyawo re leekona, ton se orisirisi nkan . Nibomi o joko pelu iyawo at'omo re. Nibomi on s'ayeye pelu awon omo re. Orisirisi nkan. nkan ton pe l'ola niyen, owo. Konse pe enikan ni tola wura die, eni na ti d'Olorun. Rara. Bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ sarva-loka-maheśvaram ([[Vanisource:BG 5.29 (1972)|BG 5.29]]), suhṛdam... Krsna ti salaye pe " Emi ni onigbadun to gaju." Bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ sarva-loka-maheśvaram. " Emi l'olori gbogbo isogbe aye yi. Ola niyen je. Agbara, lori eto yi, Krsna, nigbato kere pelu osu meta, lori ese mama re, o fiku awon esu to po ga. | ||
<!-- END TRANSLATED TEXT --> | <!-- END TRANSLATED TEXT --> |
Latest revision as of 00:24, 14 June 2018
Lecture on BG 7.1 -- Bombay, January 13, 1973
Bhagavān. Isotunmo Bhagavān wa. Konsepe oniranun a sowipe Bhagavān loun je. Rara. Parasara Muni, baba Vyasadeva ti salaye nkan ti Bhagavān je. Ola nitunmo Bhaga, eni to l'ola yi nitumo van. gege bi awa na ti jerisi. Enikeni toba l'owo, gbogbo eyan lo feran re. A lewa. Awon eyan asi loba fun iranlowo. Eyan toba nipo gidi, eyan na ma lewa. Eni toba lokiki, eni na ma lewa. Eni toba logbon, oun na ma lewa. Enito ba gbo, oun na ma lewa. eni tioba nife fun awon nkan aye yi oun na ma lewa... Enito ni gbogbo nkan aye yi sugbon to fi gbogbo e sile, ti ko loo fun ara re. gege b'eyan ton se saara, ton fun awon eyan ni nkan. Oun na lewa. Beena awon ola mefa leleyi. Beena eni toba ni awon ola mefa wanyi ni pipe nitumo Bhagavān, eyan bayi ni Bhagavān. Kon se awon oniranu kan loju titi ton pera wan ni Bhagavān. Rara. Iyanje niyen. Awon eyna o mo itumo oro Bhagavān, nitorina lon sen gba awon oniranu wanyi bi Bhagavān. Aisvaryasya samagrasya. Ola. Awon olowo po ni ile Bombay, sugbon koseni tole sowipe " Emi nimo l'ola gbogbo aye. Gbogbo owo ninu awon ile-owo, emi nimo ni gbogbo e." Koseni tole sobe. Sugbon Krsna le sobe. Aisvarayasya samagrasya. Ola nitumo Smagra, iwonba kekere ko. Samagra. Aiśvaryasya samagrasya vīryasya. Agbara, ipo gidi. Viryasya. Yasasah, oruko re. gege bi Krsna se so Bhagavad-gita yi ni odun egberun marun seyin, sugbon tit d'ooni nigbogbo agbaye wansi lo oro na. Ninu orile India nikan ko, ni gbogbo agbaye. Wan mo nipa Bhagavad-gita ninu gbogbo awon orile ede aye yi, lai wo ede, tabi esin. Gbogbo awon eyan lon ka, awon eyan ton l'ogbon awon alakowe. Itumo re niwipe olokiki ni Krsna. gbogbo eyan lo mo.
Beena aisvaryasya. nigbato wa lori aye yi, osi fi gbogbo ola re fihan. Narada Muni si fe ri bi Krsna sen toju awon iyawo 16, 108 toni. beena nigbat Narada Muni dey o wonu gbogbo awon ile oba. ile oba 16, 108 lo wa, gbogbo wan pelu okuta iyebiye Kosi idi fun ina lale, gbogbo ile oba yi lo kun fun awon okuta iyebiye. Pelu wura ati eyin erin lonfi se awon aga. Ola. Ogba wan kun fun igi parijata. Iyen nikon ko, Narada Muni si ri wipe Krsna wa pelu gbogbo awon iyawo re leekona, ton se orisirisi nkan . Nibomi o joko pelu iyawo at'omo re. Nibomi on s'ayeye pelu awon omo re. Orisirisi nkan. nkan ton pe l'ola niyen, owo. Konse pe enikan ni tola wura die, eni na ti d'Olorun. Rara. Bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ sarva-loka-maheśvaram (BG 5.29), suhṛdam... Krsna ti salaye pe " Emi ni onigbadun to gaju." Bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ sarva-loka-maheśvaram. " Emi l'olori gbogbo isogbe aye yi. Ola niyen je. Agbara, lori eto yi, Krsna, nigbato kere pelu osu meta, lori ese mama re, o fiku awon esu to po ga.