YO/Prabhupada 0188 - Ona abayo tayeraye si gbogbo isoro aye: Difference between revisions

 
(Vanibot #0023: VideoLocalizer - changed YouTube player to show hard-coded subtitles version)
 
Line 2: Line 2:
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]]
[[Category:1080 Yoruba Pages with Videos]]
[[Category:Prabhupada 0188 - in all Languages]]
[[Category:Prabhupada 0188 - in all Languages]]
[[Category:YO-Quotes - Unknown Date]]
[[Category:YO-Quotes - 1969]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Srimad-Bhagavatam]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Srimad-Bhagavatam]]
[[Category:YO-Quotes - in USA]]
[[Category:YO-Quotes - in USA]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Los Angeles]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Los Angeles]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0187 - E duro s'abe ina nigbogbo igba|0187|YO/Prabhupada 0189 - Efi awon Olufokansi lori awon guna meta|0189}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 15: Line 18:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|6qWWV8B6NIs|The Ultimate Solution of all the Problems of Life - Prabhupāda 0188}}
{{youtube_right|iGO035PzWkM|Ona abayo tayeraye si gbogbo isoro aye<br />- Prabhupāda 0188}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/690712SB.LA_clip.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/690712SB.LA_clip.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 27: Line 30:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Visnujana: Prabhupada, eti salaaye wipe Olorun ni'idi fun gbogbo nkan, sugbon koseni to mo Olorun, bawo ni awon lesele mowipe wan ni idari lori wan? Bawo lonsele mowipe wan labe enikan tio basi eni to mo Krsna oun de ni orisun gbogbo nkan? Bawo lonsele mo wipe nitori Krsna ni gbogbo nkan sen sele?  
Visnujana: Prabhupāda, eti salaaye wipe Olorun ni'idi fun gbogbo nkan, sugbon koseni to mo Olorun, bawo ni awon lesele mowipe wan ni idari lori wan? Bawo lonsele mowipe wan labe enikan tio basi eni to mo Krsna oun de ni orisun gbogbo nkan? Bawo lonsele mo wipe nitori Krsna ni gbogbo nkan sen sele?  


Prabhupada: Bawo losele mo wipe o wa labe ijiba? Bawo losele mo?  
Prabhupāda: Bawo losele mo wipe o wa labe ijiba? Bawo losele mo?  


Visnujana: ijoba ni iwe ofin.  
Visnujana: ijoba ni iwe ofin.  


Prabhupada: Nitorina awa na ni awon iwe ofin. Anādi bahirmukha jīva kṛṣṇa bhuli gelā, ataeva kṛṣṇa veda-purāṇe karilā. Nitoripe etii gbagbe Krsna, Krsna ti funyin ni awon iwe to po, iwe mimo Veda. Nitorina ni monse salaaye ema lo asiko yin ni ilokulo lati ka awon iwe iranu wanyi. Ef'okan yin lori awon iwe Veda. Lehin na elemo. Kilode ti awon iwe yi se wa n'be? nLati ranyin leti pe egbudo tele awon ofin wanyi. Sugbon teyin o ba gba anfaani yi ni pataki, lehin na ilokulo lema lo aye yin. Ise iwaasu yi, itejade awon iwe yi, awon iwe, awon iwe iroyin, egbe imoye Krsna, gbogbo awon nkan yi wa lati ranwa leti pe awa labe awon nkan, tani oludaru to gaju yi, bi aye yin sele ni ilosiwaju, besele ni igbala lati ile-aye ton so, Besele ni'gbala. Egbe yi niyen. Idi fun egbe imoye Krsna yi niyen; bibeko kini iwulo egbe yi? Kon se awon ejo nla nla lati je ki inu awon eyan dun fun igba die. Ona abayo tayeraye si gbogbo isoro aye wa, egbe imoye Krsna yi. orin kiko yi loma jeki okan wa legba iwaasu yi. Ceto-darpaṇa-mārjanam ([[Vanisource:CC Antya 20.12|CC Antya 20.12]]), fifo okan wa. Lehin na ele ri iwaasu yi gba. Gege na ilana wa daju gege bi sayensi, enikeni to ba le se, die die loma ri wipe, oun tin ni ilosiwaju. Kosi iyemeji lori oro yi.
Prabhupāda: Nitorina awa na ni awon iwe ofin. Anādi bahirmukha jīva kṛṣṇa bhuli gelā, ataeva kṛṣṇa veda-purāṇe karilā. Nitoripe etii gbagbe Krsna, Krsna ti funyin ni awon iwe to po, iwe mimo Veda. Nitorina ni monse salaaye ema lo asiko yin ni ilokulo lati ka awon iwe iranu wanyi. Ef'okan yin lori awon iwe Veda. Lehin na elemo. Kilode ti awon iwe yi se wa n'be? nLati ranyin leti pe egbudo tele awon ofin wanyi. Sugbon teyin o ba gba anfaani yi ni pataki, lehin na ilokulo lema lo aye yin. Ise iwaasu yi, itejade awon iwe yi, awon iwe, awon iwe iroyin, egbe imoye Krsna, gbogbo awon nkan yi wa lati ranwa leti pe awa labe awon nkan, tani oludaru to gaju yi, bi aye yin sele ni ilosiwaju, besele ni igbala lati ile-aye ton so, Besele ni'gbala. Egbe yi niyen. Idi fun egbe imoye Krsna yi niyen; bibeko kini iwulo egbe yi? Kon se awon ejo nla nla lati je ki inu awon eyan dun fun igba die. Ona abayo tayeraye si gbogbo isoro aye wa, egbe imoye Krsna yi. orin kiko yi loma jeki okan wa legba iwaasu yi. Ceto-darpaṇa-mārjanam ([[Vanisource:CC Antya 20.12|CC Antya 20.12]]), fifo okan wa. Lehin na ele ri iwaasu yi gba. Gege na ilana wa daju gege bi sayensi, enikeni to ba le se, die die loma ri wipe, oun tin ni ilosiwaju. Kosi iyemeji lori oro yi.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 19:11, 14 October 2018



Lecture on SB 2.3.17 -- Los Angeles, July 12, 1969

Visnujana: Prabhupāda, eti salaaye wipe Olorun ni'idi fun gbogbo nkan, sugbon koseni to mo Olorun, bawo ni awon lesele mowipe wan ni idari lori wan? Bawo lonsele mowipe wan labe enikan tio basi eni to mo Krsna oun de ni orisun gbogbo nkan? Bawo lonsele mo wipe nitori Krsna ni gbogbo nkan sen sele?

Prabhupāda: Bawo losele mo wipe o wa labe ijiba? Bawo losele mo?

Visnujana: ijoba ni iwe ofin.

Prabhupāda: Nitorina awa na ni awon iwe ofin. Anādi bahirmukha jīva kṛṣṇa bhuli gelā, ataeva kṛṣṇa veda-purāṇe karilā. Nitoripe etii gbagbe Krsna, Krsna ti funyin ni awon iwe to po, iwe mimo Veda. Nitorina ni monse salaaye ema lo asiko yin ni ilokulo lati ka awon iwe iranu wanyi. Ef'okan yin lori awon iwe Veda. Lehin na elemo. Kilode ti awon iwe yi se wa n'be? nLati ranyin leti pe egbudo tele awon ofin wanyi. Sugbon teyin o ba gba anfaani yi ni pataki, lehin na ilokulo lema lo aye yin. Ise iwaasu yi, itejade awon iwe yi, awon iwe, awon iwe iroyin, egbe imoye Krsna, gbogbo awon nkan yi wa lati ranwa leti pe awa labe awon nkan, tani oludaru to gaju yi, bi aye yin sele ni ilosiwaju, besele ni igbala lati ile-aye ton so, Besele ni'gbala. Egbe yi niyen. Idi fun egbe imoye Krsna yi niyen; bibeko kini iwulo egbe yi? Kon se awon ejo nla nla lati je ki inu awon eyan dun fun igba die. Ona abayo tayeraye si gbogbo isoro aye wa, egbe imoye Krsna yi. orin kiko yi loma jeki okan wa legba iwaasu yi. Ceto-darpaṇa-mārjanam (CC Antya 20.12), fifo okan wa. Lehin na ele ri iwaasu yi gba. Gege na ilana wa daju gege bi sayensi, enikeni to ba le se, die die loma ri wipe, oun tin ni ilosiwaju. Kosi iyemeji lori oro yi.