YO/Prabhupada 0519 - Krishna Consciousness Persons, They are not after Will-o'-the-Wisp, Phantasmagoria: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0519 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1968 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in USA, Los Angeles]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Los Angeles]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0518 - The Four Functions of Conditional Life Means Birth, Death, Old Age, and Disease|0518|YO/Prabhupada 0520 - We are Chanting, We are Hearing, We are Dancing, We're Enjoying. Why?|0520}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/681202BG.LA_clip04.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/681202BG.LA_clip04.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 27: Line 30:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
gbogbo eyan lofemo nipa Olorun, bawo ni Olorun seje. awon eyan mi masowipe, kos'Olorun, awon mi wa sowipe Olorun ti ku. isiyemeji ni gbogbo eleyi. Sugbon nibi Krsna sowipe asaṁśaya, ema ni iseyemeji mo. Eyin na ma riwipe Krsna fun ara re wa nibi. Oun ni orisun gbogbo nkan. Olorun gbogbo nkan awon nkan bayi lema ko. Nkan t'alakoko niwipe kosi basele ni ilosiwaju ninu eto imoye mimo, taba ni awon iseyemeji, saṁśayah. egbudo yo gbogbo iseyemeji wanyi pelu imoye gidi, pelu abasepo, pelu awon ilana to daju. awon elesin imoye Krsna ti koja ipo awon eyan ton sinronrun. Rara wanni ilosiwaju to daju si Olorun gege bonse so ninu Brahma-saṁhitā, cintāmaṇi-prakara-sadmasu kalpa-vṛkṣa-lakṣāvṛteṣu surabhīr abhipālayantam (Bs. 5.29). Oni planeti tonpe ni cintāmaṇi-dhāma, Goloka Vṛndāvana. ninu dhāma... gege bi Bhagavad-gītā, se so mad dhāma. Ijobe re nitumo Dhama. Krsna sowipe, moni ijoba mi l'orun". Bawo lasefe jiyan? Bawo ni ijoba naseri? Wanti salaaye na ninu Bhagavad-gītā ati orisirisi iwe mimo. Yad gatvā na nivartante tad dhāma paramaṁ mama ([[Vanisource:BG 15.6|BG 15.6]]). ibikibi teba lo.. teba fe kelo Sputnik, tabi ibimo lasan. ibikibi teba lo...planet teba fe sugbon agbudo pada si planeti yi, nitoripe koi besele joko sibe. Omo-ilu America niyin sugbon fun igba melo lele wa bayi? koleye awon eyan yhi. Nijokan egbudo kuru nibi na. Kosi besel sowipe, " rara mi o lobi kankan. Moni Visa tibi tabi omo-ilu yi nimi." rara Kolesese. Nijoka iku ma de, asi sofun yin " Edakun ejade". "rara, sa, moni nkan timon se." "rara, iranu ni gbogbo nkan ton se. Bosibi. Setiri bayi? Sugbon teba losi Kṛṣṇaloka, Kṛṣṇa sowipe yad gatvā na nivartante, kosidii lati pada mo. Yad gatvā na nivartante tad dhāma paramaṁ mama ([[Vanisource:BG 15.6|BG 15.6]]).
gbogbo eyan lofemo nipa Olorun, bawo ni Olorun seje. awon eyan mi masowipe, kos'Olorun, awon mi wa sowipe Olorun ti ku. isiyemeji ni gbogbo eleyi. Sugbon nibi Krsna sowipe asaṁśaya, ema ni iseyemeji mo. Eyin na ma riwipe Krsna fun ara re wa nibi. Oun ni orisun gbogbo nkan. Olorun gbogbo nkan awon nkan bayi lema ko. Nkan t'alakoko niwipe kosi basele ni ilosiwaju ninu eto imoye mimo, taba ni awon iseyemeji, saṁśayah. egbudo yo gbogbo iseyemeji wanyi pelu imoye gidi, pelu abasepo, pelu awon ilana to daju. awon elesin imoye Krsna ti koja ipo awon eyan ton sinronrun. Rara wanni ilosiwaju to daju si Olorun gege bonse so ninu Brahma-saṁhitā, cintāmaṇi-prakara-sadmasu kalpa-vṛkṣa-lakṣāvṛteṣu surabhīr abhipālayantam (Bs. 5.29). Oni planeti tonpe ni cintāmaṇi-dhāma, Goloka Vṛndāvana. ninu dhāma... gege bi Bhagavad-gītā, se so mad dhāma. Ijobe re nitumo Dhama. Krsna sowipe, moni ijoba mi l'orun". Bawo lasefe jiyan? Bawo ni ijoba naseri? Wanti salaaye na ninu Bhagavad-gītā ati orisirisi iwe mimo. Yad gatvā na nivartante tad dhāma paramaṁ mama ([[Vanisource:BG 15.6 (1972)|BG 15.6]]). ibikibi teba lo.. teba fe kelo Sputnik, tabi ibimo lasan. ibikibi teba lo...planet teba fe sugbon agbudo pada si planeti yi, nitoripe koi besele joko sibe. Omo-ilu America niyin sugbon fun igba melo lele wa bayi? koleye awon eyan yhi. Nijokan egbudo kuru nibi na. Kosi besel sowipe, " rara mi o lobi kankan. Moni Visa tibi tabi omo-ilu yi nimi." rara Kolesese. Nijoka iku ma de, asi sofun yin " Edakun ejade". "rara, sa, moni nkan timon se." "rara, iranu ni gbogbo nkan ton se. Bosibi. Setiri bayi? Sugbon teba losi Kṛṣṇaloka, Kṛṣṇa sowipe yad gatvā na nivartante, kosidii lati pada mo. Yad gatvā na nivartante tad dhāma paramaṁ mama ([[Vanisource:BG 15.6 (1972)|BG 15.6]]).


dhama Krsna na leleyi nitoripe oun ni Olori gbogbo nkan Oro yi wipe, " awa la ni'le yi, America, " Iro nigbogbo eleyi, eyin ko leni ile yi. gege bi aye atijo, kasowipe odun ogorun merin tokoja, awon Indian pupa lonile yi. sugbon bakanna eti gba'le na. talole sowipe elomi na oni wa gba'le yi? iro nigbogbo anfanni yi. Krsna ni Onihun gbogbo nkan. Krsna sowipe sarva-loka-maheśvaram ([[Vanisource:BG 5.29|BG 5.29]]): " Emini Olori togaju, oludari gbogbo planeti". oun loni gbogbo nkan aye yi. Sugbon Krsna ti sowipe oun ni Olori gbogbo nkan aye yi. Gbogbo nkan to wanbi oun loni, kilode tefe fiwa pada? sugbon oti sofun wa pe yad gatvā na nivartante tad dhāma paramam ([[Vanisource:BG 15.6|BG 15.6]]).
dhama Krsna na leleyi nitoripe oun ni Olori gbogbo nkan Oro yi wipe, " awa la ni'le yi, America, " Iro nigbogbo eleyi, eyin ko leni ile yi. gege bi aye atijo, kasowipe odun ogorun merin tokoja, awon Indian pupa lonile yi. sugbon bakanna eti gba'le na. talole sowipe elomi na oni wa gba'le yi? iro nigbogbo anfanni yi. Krsna ni Onihun gbogbo nkan. Krsna sowipe sarva-loka-maheśvaram ([[Vanisource:BG 5.29 (1972)|BG 5.29]]): " Emini Olori togaju, oludari gbogbo planeti". oun loni gbogbo nkan aye yi. Sugbon Krsna ti sowipe oun ni Olori gbogbo nkan aye yi. Gbogbo nkan to wanbi oun loni, kilode tefe fiwa pada? sugbon oti sofun wa pe yad gatvā na nivartante tad dhāma paramam ([[Vanisource:BG 15.6 (1972)|BG 15.6]]).
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:08, 14 June 2018



Lecture on BG 7.1 -- Los Angeles, December 2, 1968

gbogbo eyan lofemo nipa Olorun, bawo ni Olorun seje. awon eyan mi masowipe, kos'Olorun, awon mi wa sowipe Olorun ti ku. isiyemeji ni gbogbo eleyi. Sugbon nibi Krsna sowipe asaṁśaya, ema ni iseyemeji mo. Eyin na ma riwipe Krsna fun ara re wa nibi. Oun ni orisun gbogbo nkan. Olorun gbogbo nkan awon nkan bayi lema ko. Nkan t'alakoko niwipe kosi basele ni ilosiwaju ninu eto imoye mimo, taba ni awon iseyemeji, saṁśayah. egbudo yo gbogbo iseyemeji wanyi pelu imoye gidi, pelu abasepo, pelu awon ilana to daju. awon elesin imoye Krsna ti koja ipo awon eyan ton sinronrun. Rara wanni ilosiwaju to daju si Olorun gege bonse so ninu Brahma-saṁhitā, cintāmaṇi-prakara-sadmasu kalpa-vṛkṣa-lakṣāvṛteṣu surabhīr abhipālayantam (Bs. 5.29). Oni planeti tonpe ni cintāmaṇi-dhāma, Goloka Vṛndāvana. ninu dhāma... gege bi Bhagavad-gītā, se so mad dhāma. Ijobe re nitumo Dhama. Krsna sowipe, moni ijoba mi l'orun". Bawo lasefe jiyan? Bawo ni ijoba naseri? Wanti salaaye na ninu Bhagavad-gītā ati orisirisi iwe mimo. Yad gatvā na nivartante tad dhāma paramaṁ mama (BG 15.6). ibikibi teba lo.. teba fe kelo Sputnik, tabi ibimo lasan. ibikibi teba lo...planet teba fe sugbon agbudo pada si planeti yi, nitoripe koi besele joko sibe. Omo-ilu America niyin sugbon fun igba melo lele wa bayi? koleye awon eyan yhi. Nijokan egbudo kuru nibi na. Kosi besel sowipe, " rara mi o lobi kankan. Moni Visa tibi tabi omo-ilu yi nimi." rara Kolesese. Nijoka iku ma de, asi sofun yin " Edakun ejade". "rara, sa, moni nkan timon se." "rara, iranu ni gbogbo nkan ton se. Bosibi. Setiri bayi? Sugbon teba losi Kṛṣṇaloka, Kṛṣṇa sowipe yad gatvā na nivartante, kosidii lati pada mo. Yad gatvā na nivartante tad dhāma paramaṁ mama (BG 15.6).

dhama Krsna na leleyi nitoripe oun ni Olori gbogbo nkan Oro yi wipe, " awa la ni'le yi, America, " Iro nigbogbo eleyi, eyin ko leni ile yi. gege bi aye atijo, kasowipe odun ogorun merin tokoja, awon Indian pupa lonile yi. sugbon bakanna eti gba'le na. talole sowipe elomi na oni wa gba'le yi? iro nigbogbo anfanni yi. Krsna ni Onihun gbogbo nkan. Krsna sowipe sarva-loka-maheśvaram (BG 5.29): " Emini Olori togaju, oludari gbogbo planeti". oun loni gbogbo nkan aye yi. Sugbon Krsna ti sowipe oun ni Olori gbogbo nkan aye yi. Gbogbo nkan to wanbi oun loni, kilode tefe fiwa pada? sugbon oti sofun wa pe yad gatvā na nivartante tad dhāma paramam (BG 15.6).