YO/Prabhupada 0115 - Owo mi ko ju lati se ijise Olorun fun awon eniyan: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0115 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1971 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0023: VideoLocalizer - changed YouTube player to show hard-coded subtitles version)
 
Line 5: Line 5:
[[Category:YO-Quotes - Lectures, General]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, General]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Los Angeles]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Los Angeles]]
[[Category:YO-Quotes - in USA]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0114 - Okurin eni jeje kan tí orúkọ rẹ jẹ Olorun,O si nse akoso gbogbo eniyan|0114|YO/Prabhupada 0116 - Ema fi iyé aye yin sofo|0116}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 14: Line 18:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|YH7qFW_s4XM|My Business is Only to Convey the Message Of Kṛṣṇa - Prabhupāda 0115}}
{{youtube_right|B1gye0hrXq0|My Business is Only to Convey the Message Of Kṛṣṇa - Prabhupāda 0115}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/710711LE-LA_clip.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/710711LE-LA_clip.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->



Latest revision as of 18:59, 14 October 2018



Lecture -- Los Angeles, July 11, 1971

Nitorina, inumi dun pe awon omo-okurin wonyi si n ranmi lowo ni itankale isokan Olorun yi, Olorun yio si bukun wọn. Emi o jamo nkankan. Mi o si l'agbara. Owo mi ko ju lati se ijise Olorun fun awon eniyan. O kan da bi olufiwe-ranse : owo re ni lati pin awon leta. Kole ṣeduro fun nkan towa ninu leta Esi... Leyin kika leta na, eniti won ko leta si le ni ero kan, sugbon iyen kii se idalohun ti olufiwe-ranse. Bákan náà, ojuse mi ni, ohun ti mo ti gba l'atowo d'owo awon ojise, lat'odo Oluko mi. Mo kan nse afihan ohun kanna, sugbon laisi eyikeyi idaru-dapo. Owo mi niyen. Ojuuṣe mi niyen Mo gbọdọ se afihan awon nǹkan ni ọna kanna ti Olorun se gbekalẹ gangan bi Arjuna se gbekalẹ, bi awon ācāryas wa ti gbekalẹ, Oluwa Caitanya, ati ni ìkẹyìn Oluko igbala mi, Bhaktisiddhānta Sarasvatī Gosvāmī Mahārāja. Nítorí náà, bakanna, ti e ba gba isokan egbe Olorun pelu emi kanna, ti e ba pin fun awon eniyan miiran , fun awon ara orile-ede yin, o dájú pé yio je munadoko, nitori ko si idaru-dapo nibẹ. Ko si igberaga. Ko si iyanje. O jẹ ẹmí ifokansin mimo. Ki e kan fi se iwa wu ati ki e si pin kà. Aye yin yio si wa lógo.