YO/Prabhupada 0280 - Yiya si mimo ni itumo Ise ifarafun Oluwa: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0280 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1968 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0005 edit: add new navigation bars (prev/next))
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in USA, San Francisco]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, San Francisco]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0279 - Ni otooro gbogbo wa lan sise fun owo|0279|YO/Prabhupada 0281 - Eranko ni eda eyan, sugbon eranko oniipin lo je|0281}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 15: Line 18:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|IEuz0gvw1wQ|Devotional Service Means Purifying the Senses - Prabhupāda 0280}}
{{youtube_right|IEuz0gvw1wQ|Yiya si mimo ni itumo Ise ifarafun Oluwa<br />- Prabhupāda 0280}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/680911BG.SF_clip4.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/680911BG.SF_clip4.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->



Latest revision as of 11:58, 21 September 2017



Lecture on BG 7.2 -- San Francisco, September 11, 1968

Itumo imoye Krsna ni wipe agbudo so iye-ara wa si mimo. Otan Agbudo jade kuro ninu igabdun aye yi. agbudo so iye-ara wa di mimo Bawo lese fe jade kuro ni igbadun iye-ara? Nitoripe eda leje iye-ara yin si wan be sugbon ni asiko tawa yi, gbogbo wa ti doti pelu awon nkan aye yi. Kosi ba sele gbadun bi ase fe otooro sayensi leleyi gege na itumo Ise ifarafun Oluwa ni wipe agbudo ya iye-ara wa si mimo Sarvopādhi-vinirmuktaṁ tat-paratvena nirmalam (CC Madhya 19.170). Nirmalam: sodotun. bawo ni asele jeki iye-ara wa di tuntun? wan ti salaaye na ninu iwe Nārada-bhakti-sūtra. pe sarvopādhi-vinirmuktam. Iyasi mimo ara wa ni wipe a gbudo fi gbogbo nkan ile-aye yi ti o da Ile-aye wa si kun fun eto nipa yiyan gege bi mon se ronu pe, "Omo orile-ede India nimi, Sanyasi nimi" Eyin na ronu pe, "okurin nimi, obirin nimi, oyinbo nimi, eyan dudu nimi2 eti nipa yiyan pe ayasi mimo, itumo re niwipe, gbogbo eto ara wa na ma yasi mimo gege na, itumo oye Krsna niwipe, " Omo-orile India ko nimi, mio kin se omo Ilu America Nkankanna ni moje pelu Krsna mosi nigbagbo pe nkankanna nimo je pelu Krsna Imoye krsna niyen ati iyasimimo iye- ara wa gege boseje pe nkankanna laje pelu Krsna, agbudo di iranse Krsna Igbadun yin niyen gbogbo wa feni itelorun ara wa egbudo mowipe

Nkankanna leje pelu Krsna, lehin na ema s'ise fun itelorun Krsna, Govinda. teba sise lati te oluwa lorun, eyin na ma ni itelorun fun apeere - apeere ile-aye yini mo fe fun yin- gege bi asepo laarin Oko ati iyawo, onigbadun ni Okurin je, iyawo re ni eni ton gbadun ti iyawo ma se itelorun fun Oko re, ouna ma ni itelorun. ti ara banyún yin te si fi ekana ha be ekana yin na ma ni itelorun kon sepe ara tenyún ni kan lo ma ni itelorun sugbon gbogbo ara yin lo ma ni itelorun. Gege na, teba se nkan to ma te krsna lorun gbogbo agbaye ma ni itelorun Sayensi niyen. Tasmin tuṣṭe jagat tuṣṭa. apeere imi ni wipe, teba jeun dada, gbogbo ara loni itelorun ikun na asi fun e ni agbara lati gba ounje na s'ara ti ounje na ba wo ara, asi di eje, asi wole sinu ọkàn, lat'ọkàn yin awole si gbogbo ara yin ti eleyi ba sele, gbogbo ara riro teni loma tan.

Ilana imoye Krsna niyen sayeni imoye krsna niyen, Krsna de ti s'alaaye fun ara re teba ni imoye Krsna, kosi nkan to ma le lati mo ama ni oye gbogbo nkan. osi da gan