YO/Prabhupada 0575 - They are Kept in Darkness and Ignorance: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0575 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1973 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 6: Line 6:
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0574 - You cannot Kill the Body without Sanction. That is Sinful|0574|YO/Prabhupada 0576 - The Process should be How To Make Zero all these Propensities|0576}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:

<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/730825BG-LON_clip02.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/730825BG-LON_clip02.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 26: Line 29:

<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT (from DotSub) -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT (from DotSub) -->
Beena na jāyate na mriyate vā kadācit. eyikeyi asiko, seyin, nisin ati lojowaju nitumo Kadācit. Ati salaaye teletele wipe lasiko tokoja, ati wa laye ninu ara eda imi. Lasiko tawayi, asi wa, lojowaju na asi ma wa, boya ninu ara eda to yato. Boya rara. Tathā dehāntara-prāptiḥ ([[Vanisource:BG 2.13|BG 2.13]]), nitoripe lehin igba ton funwa ni ara eda yi, agodo gba ara eda imi. Nkan ton selle leleyi. Laini imoye nipa ara-eni ama wa ninu aimokan. Ninu eto ikeeko lori gbogbo agbaye kos'eto yi nibe. Won wa ninu aimokan ati okunkun, sugbon wonsin na owo repete ni awon ilu geesi nipataki. Won lowo, ile-iwe giga, sugbon kini ibajade to wa? Ode ati awon asiwere.Otan. Nitoripe awon eyan o mo. Won o ni ero nipa ara-eni. Imora-eni nitumo imoye yi, pe " Ara mi ko nimi, emi nimi." Imoye gidi niyen. imoye nipa basele jeun, sun, basele gbeja ara wa, basele ni imo ako ati abo, wande ti ko aimoye iwe mori awon eto wanyi, imoye ko ni awon eto wanyi. Awon ologbo ati aja gan mo. Awon ologbo ati aja gan tio ka imoye Freud, sugbon won mo bonsen gbadun imo ako ati abo.
Beena na jāyate na mriyate vā kadācit. eyikeyi asiko, seyin, nisin ati lojowaju nitumo Kadācit. Ati salaaye teletele wipe lasiko tokoja, ati wa laye ninu ara eda imi. Lasiko tawayi, asi wa, lojowaju na asi ma wa, boya ninu ara eda to yato. Boya rara. Tathā dehāntara-prāptiḥ ([[Vanisource:BG 2.13 (1972)|BG 2.13]]), nitoripe lehin igba ton funwa ni ara eda yi, agodo gba ara eda imi. Nkan ton selle leleyi. Laini imoye nipa ara-eni ama wa ninu aimokan. Ninu eto ikeeko lori gbogbo agbaye kos'eto yi nibe. Won wa ninu aimokan ati okunkun, sugbon wonsin na owo repete ni awon ilu geesi nipataki. Won lowo, ile-iwe giga, sugbon kini ibajade to wa? Ode ati awon asiwere.Otan. Nitoripe awon eyan o mo. Won o ni ero nipa ara-eni. Imora-eni nitumo imoye yi, pe " Ara mi ko nimi, emi nimi." Imoye gidi niyen. imoye nipa basele jeun, sun, basele gbeja ara wa, basele ni imo ako ati abo, wande ti ko aimoye iwe mori awon eto wanyi, imoye ko ni awon eto wanyi. Awon ologbo ati aja gan mo. Awon ologbo ati aja gan tio ka imoye Freud, sugbon won mo bonsen gbadun imo ako ati abo.

Beena imoye aja yi kole ranyin lowo, pe " Moni ara eda yi, mode fe gbadun imo ako ati abo na." Imoye aja niyen. Aja gan mo gbogbo awon nkan wanyi. Imoye toye keni ni besele fi imo ako ati abo sile. Imoy gidi niyehn. Tapo divyam ([[Vanisource:SB 5.5.1|SB 5.5.1]]). Tapasya. Ile aye yi wa fun Tapasya, lati fi igbadun iye ara wa sile. Imoye niyen je. Konsepe ka bere sini gbadun imo ako ati abo tabi igbadun iye ara wa. Awon ologbo at'aja gan mo bonsen se lai keeko, laisi imoye kankan. Imoye yi, pravṛttiḥ eṣaṁ bhūtānāṁ nivṛtes tu mahā-phalam.(?) Pravṛtti, gbogbo eda aye yi ni pravrtti, ifa okansi nitumo re. Kini yen? Igbadun iye ara wa. Loke vyavāya 'miṣa mada-sevā nityas tu jantuḥ.(?) Awon eda nitumo Jantuḥ. Nitya, nigbogbo'gba, o ni ifa okansi yi, vyavāya āmiṣa mada-sevā. Vyavāya. Imo ako ati abo nitumo Vyavāya ati eran jije nitumo āmiṣa. Vyavāya āmiṣa, mada-sevā, ati oti mimu. Awon iwa eda leleyi, awon kokoro gan ni awon iwa wanyi. Awon eyan ton ti kawe... awon kokoro feran oti mimu gan. Nitorina won feran adun, iyóìrèké òyìnbó. Bi oti amupara ni odun je Eyin na le mo pe lati iyoireke oyinbo lonti se oti. won ma po iyo ireke oyinbo pelu omikíkan, ati omikíkan sulphur. Oti niyen. Beena ewo loje lati nkan adun to poju.

<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:12, 14 June 2018

Lecture on BG 2.19 -- London, August 25, 1973

Beena na jāyate na mriyate vā kadācit. eyikeyi asiko, seyin, nisin ati lojowaju nitumo Kadācit. Ati salaaye teletele wipe lasiko tokoja, ati wa laye ninu ara eda imi. Lasiko tawayi, asi wa, lojowaju na asi ma wa, boya ninu ara eda to yato. Boya rara. Tathā dehāntara-prāptiḥ (BG 2.13), nitoripe lehin igba ton funwa ni ara eda yi, agodo gba ara eda imi. Nkan ton selle leleyi. Laini imoye nipa ara-eni ama wa ninu aimokan. Ninu eto ikeeko lori gbogbo agbaye kos'eto yi nibe. Won wa ninu aimokan ati okunkun, sugbon wonsin na owo repete ni awon ilu geesi nipataki. Won lowo, ile-iwe giga, sugbon kini ibajade to wa? Ode ati awon asiwere.Otan. Nitoripe awon eyan o mo. Won o ni ero nipa ara-eni. Imora-eni nitumo imoye yi, pe " Ara mi ko nimi, emi nimi." Imoye gidi niyen. imoye nipa basele jeun, sun, basele gbeja ara wa, basele ni imo ako ati abo, wande ti ko aimoye iwe mori awon eto wanyi, imoye ko ni awon eto wanyi. Awon ologbo ati aja gan mo. Awon ologbo ati aja gan tio ka imoye Freud, sugbon won mo bonsen gbadun imo ako ati abo.

Beena imoye aja yi kole ranyin lowo, pe " Moni ara eda yi, mode fe gbadun imo ako ati abo na." Imoye aja niyen. Aja gan mo gbogbo awon nkan wanyi. Imoye toye keni ni besele fi imo ako ati abo sile. Imoy gidi niyehn. Tapo divyam (SB 5.5.1). Tapasya. Ile aye yi wa fun Tapasya, lati fi igbadun iye ara wa sile. Imoye niyen je. Konsepe ka bere sini gbadun imo ako ati abo tabi igbadun iye ara wa. Awon ologbo at'aja gan mo bonsen se lai keeko, laisi imoye kankan. Imoye yi, pravṛttiḥ eṣaṁ bhūtānāṁ nivṛtes tu mahā-phalam.(?) Pravṛtti, gbogbo eda aye yi ni pravrtti, ifa okansi nitumo re. Kini yen? Igbadun iye ara wa. Loke vyavāya 'miṣa mada-sevā nityas tu jantuḥ.(?) Awon eda nitumo Jantuḥ. Nitya, nigbogbo'gba, o ni ifa okansi yi, vyavāya āmiṣa mada-sevā. Vyavāya. Imo ako ati abo nitumo Vyavāya ati eran jije nitumo āmiṣa. Vyavāya āmiṣa, mada-sevā, ati oti mimu. Awon iwa eda leleyi, awon kokoro gan ni awon iwa wanyi. Awon eyan ton ti kawe... awon kokoro feran oti mimu gan. Nitorina won feran adun, iyóìrèké òyìnbó. Bi oti amupara ni odun je Eyin na le mo pe lati iyoireke oyinbo lonti se oti. won ma po iyo ireke oyinbo pelu omikíkan, ati omikíkan sulphur. Oti niyen. Beena ewo loje lati nkan adun to poju.