YO/Prabhupada 0600 - We are not Prepared to Surrender, This is our Material Disease: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0600 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1972 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in India, Hyderabad]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Hyderabad]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0599 - Krsna Consciousness is not Easy. You cannot have it Unless You Surrender Yourself|0599|YO/Prabhupada 0601 - Caitya-guru means Who gives Conscience and Knowledge from Within|0601}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:


<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK (from English page -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/721127BG-HYD_clip07.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/721127BG-HYD_clip07.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 33: Line 36:
:upadekṣyanti te jñānaṁ
:upadekṣyanti te jñānaṁ
:jñāninas tattva-darśinaḥ
:jñāninas tattva-darśinaḥ
:([[Vanisource:BG 4.34|BG 4.34]])
:([[Vanisource:BG 4.34 (1972)|BG 4.34]])


Beena afi teyin ba mura lati teriba... Ise tole gan loje fun awon eyan ile aye yi. Koseni tofe teriba. Awon eyan fe farawe. Awaon eyan si ara won, laarin awon ebi, laarin awon orile-ede, gbogbo eyan lonfe d'oga. Nibo ni ibeere pe wonfe teriba? Kosejo na. Beena aisan towa niyen. Nitorina Krsna ti sowipe lati ni iwosan ninu iwas were yi agbodo teriba. Sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja ([[Vanisource:BG 18.66|BG 18.66]]). "Lehin na?" Tinba teriba ti gbogbo eto yi badi ipaadanu? Ise mi, awon ero ti moni, gbogbo awon nkan timo ni...? Rara. " Masi toju yin. Masi toju yin." Ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo mokṣayiṣyāmi mā śucaḥ. "Ema jeki idamu muyin lokan." Beena awon oro aridaju wnayi si wa. Beena, awa ofe teriba. Aisan tani niyen. Nitorina Krsna ti wa bi olufokansi lati fihan wa. Caitanya Mahāprabhu. Kṛṣṇa-varṇaṁ tviṣākṛṣṇaṁ sāṅgopāṅgāstra-pārṣadam ([[Vanisource:SB 11.5.32|SB 11.5.32]]).
Beena afi teyin ba mura lati teriba... Ise tole gan loje fun awon eyan ile aye yi. Koseni tofe teriba. Awon eyan fe farawe. Awaon eyan si ara won, laarin awon ebi, laarin awon orile-ede, gbogbo eyan lonfe d'oga. Nibo ni ibeere pe wonfe teriba? Kosejo na. Beena aisan towa niyen. Nitorina Krsna ti sowipe lati ni iwosan ninu iwas were yi agbodo teriba. Sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja ([[Vanisource:BG 18.66 (1972)|BG 18.66]]). "Lehin na?" Tinba teriba ti gbogbo eto yi badi ipaadanu? Ise mi, awon ero ti moni, gbogbo awon nkan timo ni...? Rara. " Masi toju yin. Masi toju yin." Ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo mokṣayiṣyāmi mā śucaḥ. "Ema jeki idamu muyin lokan." Beena awon oro aridaju wnayi si wa. Beena, awa ofe teriba. Aisan tani niyen. Nitorina Krsna ti wa bi olufokansi lati fihan wa. Caitanya Mahāprabhu. Kṛṣṇa-varṇaṁ tviṣākṛṣṇaṁ sāṅgopāṅgāstra-pārṣadam ([[Vanisource:SB 11.5.32|SB 11.5.32]]).


Beena egbe imoye Krsna yi daju gan, osi se pataki pelu awon oye onii sayensi. Konse nkan tio daju, nkan ti awon eyan daale lati ironu okan. Nkan to daju leleyi, lori itosona Veda, bi Krsna se so, sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja ([[Vanisource:BG 18.66|BG 18.66]]). Beena awa fe ko awon imoye wanyi, pe.. Krsna, Krsna leleyi, Eledumara. Eyin sewaadi lati mo Oluwa. Eyin o le mo eni t'Oluwa je. Olorun leleyi, Krsna. Oruko re, ise re, gbogbo nkan wa ninu Bhagavad-gita. E gba ke teriba fun. Krsna si sowipe, man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru ([[Vanisource:BG 18.65|BG 18.65]]). Beena nkankana l'awa n'so. Bi won se so ninu Bhagavad-gita. Awa o le se isotunmo imi si. Awa o le ba gbogbo Bhagavad-gita yi je. Awa o kin se iwa ijogbon yi. Nigbami awon eyan man sowipe, " Swamiji, ise teti se yi iyanu loje." sugbon iyanu wo loje? Alagbara idan konimi. Oun toje ijeere mi niwipe moti salaye nipa Bhagavad-gita. Moti salaye boseje. Nitorina lose ni aseyori.
Beena egbe imoye Krsna yi daju gan, osi se pataki pelu awon oye onii sayensi. Konse nkan tio daju, nkan ti awon eyan daale lati ironu okan. Nkan to daju leleyi, lori itosona Veda, bi Krsna se so, sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja ([[Vanisource:BG 18.66 (1972)|BG 18.66]]). Beena awa fe ko awon imoye wanyi, pe.. Krsna, Krsna leleyi, Eledumara. Eyin sewaadi lati mo Oluwa. Eyin o le mo eni t'Oluwa je. Olorun leleyi, Krsna. Oruko re, ise re, gbogbo nkan wa ninu Bhagavad-gita. E gba ke teriba fun. Krsna si sowipe, man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru ([[Vanisource:BG 18.65 (1972)|BG 18.65]]). Beena nkankana l'awa n'so. Bi won se so ninu Bhagavad-gita. Awa o le se isotunmo imi si. Awa o le ba gbogbo Bhagavad-gita yi je. Awa o kin se iwa ijogbon yi. Nigbami awon eyan man sowipe, " Swamiji, ise teti se yi iyanu loje." sugbon iyanu wo loje? Alagbara idan konimi. Oun toje ijeere mi niwipe moti salaye nipa Bhagavad-gita. Moti salaye boseje. Nitorina lose ni aseyori.


Ese pupo. Hare Krsna. (opin)
Ese pupo. Hare Krsna. (opin)
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:15, 14 June 2018



Lecture on BG 2.23 -- Hyderabad, November 27, 1972

Beena Caitanya Mahaprabhu, nitoripe awon eyan o ni oye nipa Krsna... Krsna si bere ninu Bhagavad-gita pe " E teriba funmi." Kilo lese? Oluwa loje. Krsna loje. Nisin oti p'ase funyin: E teriba. M'a toju yin." Ahaṁ tvāṁ sarva-pāpe... sugbon awon eyan si fun ni isotunmo to yato. " Oh, kilode toye kin teriba si Krsna? Eda eyan na loje bi emi. Boya o se pataki die jumi lo. Sugbon kilode toye kin teriba Fun?" Nitripe ni ile aye yi aisan to wa niwipe, awon eyan o fe teriba. Gbogbo eyan lon ni igberaga: " Nkan bayi bayi nimi.." Aisan ile aye yi niyen. Nitorina lati ni iwosan ninu aisan ile aye yi, egbodo teriba.

tad viddhi praṇipātena
paripraśnena sevayā
upadekṣyanti te jñānaṁ
jñāninas tattva-darśinaḥ
(BG 4.34)

Beena afi teyin ba mura lati teriba... Ise tole gan loje fun awon eyan ile aye yi. Koseni tofe teriba. Awon eyan fe farawe. Awaon eyan si ara won, laarin awon ebi, laarin awon orile-ede, gbogbo eyan lonfe d'oga. Nibo ni ibeere pe wonfe teriba? Kosejo na. Beena aisan towa niyen. Nitorina Krsna ti sowipe lati ni iwosan ninu iwas were yi agbodo teriba. Sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66). "Lehin na?" Tinba teriba ti gbogbo eto yi badi ipaadanu? Ise mi, awon ero ti moni, gbogbo awon nkan timo ni...? Rara. " Masi toju yin. Masi toju yin." Ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo mokṣayiṣyāmi mā śucaḥ. "Ema jeki idamu muyin lokan." Beena awon oro aridaju wnayi si wa. Beena, awa ofe teriba. Aisan tani niyen. Nitorina Krsna ti wa bi olufokansi lati fihan wa. Caitanya Mahāprabhu. Kṛṣṇa-varṇaṁ tviṣākṛṣṇaṁ sāṅgopāṅgāstra-pārṣadam (SB 11.5.32).

Beena egbe imoye Krsna yi daju gan, osi se pataki pelu awon oye onii sayensi. Konse nkan tio daju, nkan ti awon eyan daale lati ironu okan. Nkan to daju leleyi, lori itosona Veda, bi Krsna se so, sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66). Beena awa fe ko awon imoye wanyi, pe.. Krsna, Krsna leleyi, Eledumara. Eyin sewaadi lati mo Oluwa. Eyin o le mo eni t'Oluwa je. Olorun leleyi, Krsna. Oruko re, ise re, gbogbo nkan wa ninu Bhagavad-gita. E gba ke teriba fun. Krsna si sowipe, man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65). Beena nkankana l'awa n'so. Bi won se so ninu Bhagavad-gita. Awa o le se isotunmo imi si. Awa o le ba gbogbo Bhagavad-gita yi je. Awa o kin se iwa ijogbon yi. Nigbami awon eyan man sowipe, " Swamiji, ise teti se yi iyanu loje." sugbon iyanu wo loje? Alagbara idan konimi. Oun toje ijeere mi niwipe moti salaye nipa Bhagavad-gita. Moti salaye boseje. Nitorina lose ni aseyori.

Ese pupo. Hare Krsna. (opin)