YO/Prabhupada 0525 - Maya is Strong, as Soon as You are a Little Confident, Immediately there is Attack

Revision as of 12:38, 21 September 2017 by Vanibot (talk | contribs) (Vanibot #0005 edit: add new navigation bars (prev/next))
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Lecture on BG 7.1 -- Los Angeles, December 2, 1968

Tamāla Kṛṣṇa: Prabhupāda, tin ban sise fun funyin inumi man dun gan. sugbon tinba bere sini ronu nipa bi ise tinmon se seri, ibanuje ma gba gbogbo okan mi. Ewo loye kin ro?

Prabhupada: (erin) ibanuje wa lokan re?

Tamala Krsna: Beeni.

Prabhupada: Kilode? Igbawo ni ibanuje yi man wa?

Tamāla Kṛṣṇa: tin ba ri gbogbo awon asise ti mon se.

Prabhupada: nIgbami... Nkan toda niyen. Pe osi fe gba wipe ati se awon asise kan... Ti awon asise y o ba sinbe gan. Amuye ise towa lat'okan niyen. gege bi omode se niife baba re, beena ni baba se niife omode. ti omode na ba ni aisan die baba na ma bere sini ronu, " Oh omode yi le ku. Asi ku eminikan nibi." Ijerisi ife niyen. konsepe omode na maku sugbon oun ronu bayi Iyasoto. Seti ri? Ijerisi to da. Awa o gbudo rowipe nkan ti monse da gan. Oye ka ronu wipe " mio le se". Nkan to da niyen. Ema rope " emini mo daaju" Nitoripe maya si l'agbara gan, lesekese teba rowipe e lagbara gan, maya ma kolu yin. see ri bayi? ninu ipo aisan... gege bi eyan to leni awon gba isora, onitoun o le ni aisan yi mo. Nkan to da niyen. Agbudo ronu wipe, " boya nkan timon se o da." sugbon inu agbara wa lowa, ejeka sise wa dada, sugbon ema rowipe nkan teyin se da gan. Nkan to da niyen.