YO/Prabhupada 0341 - One Who is Intelligent, He will Take this Process
Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com
Lecture on BG 9.1 -- Melbourne, June 29, 1974
Prabhupada: Hm?
Madhudviṣa: O bere wipe kini imoye ti Krsna fun Arjuna?
Prabhupada: Beeni. Krsna sofun pe "Iwo oniranu yi teriba funmi" Asiwere ni gbogbo yin e teriba fun Krsna, ile aye yin ma ni ilosiwaju. Ipinnu ilana Krsna niyen.
- sarva-dharmān parityajya
- mām ekaṁśaraṇaṁ vraja
- (BG 18.66)
Arjuna ni kanko ni Krsna n'bere, On bere lowo gbogbo wa na, awon asiwere. pe " teba fe da nkan to ma fun yin ni idunu, inu yin o le dun. Sugbon teba teriba funmi mole se kin inu yin dun." Imoye Krsna niyen, otan. Ila kan soso. Ean to ba logbon a si gba ilana yi, pe, " moti gbiyanju lati jeki inu mi dun, sugbon ko bosi. Nisin mofe tertiba si Krsna. "Otan.