YO/Prabhupada 0217 - Obirin pataki ni Devahuti je

Revision as of 11:47, 21 September 2017 by Vanibot (talk | contribs) (Vanibot #0005 edit: add new navigation bars (prev/next))
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Lecture on SB 3.28.1 -- Honolulu, June 1, 1975

Gege na ọmọ alade to je ọmọbinrin ti Manu, O di iranse fun Kardama Muni NI Ile-yoga na (yoga asrama), ile kekere lo je. Ko si Ounje to da tabi awon iranse to si ise ni be. Ko de pe na ton bere si ni te si apa kan, omo alade to rewa lo si je. Kardama Muni beere si ni ronu, Baba iyawo mi si fun mi kin ba le to ju re, sugbon nisin ìlera re tin re sile. gege bi ọkọ re mo gbudo se nkan fun Pelu agbara idan re o si ko ilu to bi to si le fo bi ọkọ ofurufu Agbara idan ni ye, Kon se 747 (erin) Ilu na si tobi gan, O si ni omi adagun, ati ọgba, pelu awon iranse Ilu na si ni awon ile-giga to po, lehin na O si fi gbogbo isọgbe-oorun hon iyawo re te ba fe mo iyoku ele ka iwe na ni ipin kerin gege na bi alagbara to je o si te iyawo re lorun. Sugbon iyawo re si fe kon ni omo papo Gege na Kardama Muni si fun ni omo-obirin mesan ati omo-okurin kan sugbon pelu adehun pe " lesekese to ba ti ni awon omo re ma si fi e si le Mi o le gbe pelu ti lailai. Iyawo re si gba Gege na bo se bi awon omo na tan, ti omo okurin ninu wan je Kapiladeva, Nigbato dagba o si so fun iya re pe, " baba mi fi ile le, emi na mo tin lo" "te ba si fe gba ilana lowo mi kin to lo, ele bi mi ni ibeere te ba fe" gege na ko to kuro ni ile, O si fun iya re ni a won ilana to da.

Ipo Devahuti si hon wipe obirin pipe lo je. O si ni Baba to da, pelu oko to da, pelu omo-okurin to da na Obirin ni asiko meta laye re, sugbon Okurin ni asiko mewa Ni asiko t'akoko, ti Obirin na ma kere o gbudo gbepelu baba re gege bi Devahuti , bo se dagba O si so fun baba re" Mofe fe Okurin yi" Sugbon ko to di igba yi, ile baba re lon gbe sugbon nigbati o fe oko, o si lo si ile oko re O de si ni isoro to po, nitoripe omo-alade lo je Okurin alagbara yi, ko si ni ile, tabi ounje, ko si ni nkan nkan. Nitorina obirin na si jiya Sugbon ko si ijo to so wi pe " Omo-alade ni mo je, emei o le jiya bayi mo" Nisin mo ti ni oko ti o le fun mi ni ile to da, tabi ounje nitorina mo fe ikọrasilẹ rara. iyen o sele ri. Oun ko oun ti oko mi ba je, nitoripe mo ti gba sinu aye mi, oko mi lo je Mo gbudo toju e, oun ko oun ti ipo re ba je ma si gbe pelu re iṣẹ iyawo le yi je. Ilana awon iwe mimo Veda ni eyi je Ni ojo eni, lesekese ti isoro die ba de, ikorasile lo ma tele wa lo wa oko imi. Rara. Obirin eyi si duro ti oko re O de si bi omo to dara ju, Olorun fun ara re, Kapila Asiko meta ta ni leleyi je Obirin gbodo ni àfojúsùn, subon gege bi karma re se je oma ni baba to ye lehin na , asi ni Oko to ye, pelu omode to ye bi Kapiladeva.