YO/Prabhupada 0318 - Come to the Sunshine

Revision as of 12:04, 21 September 2017 by Vanibot (talk | contribs) (Vanibot #0005 edit: add new navigation bars (prev/next))
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Lecture on BG 4.22 -- Bombay, April 11, 1974

Awon vaisnava o kin se matsarah. Sridara Swami ti salaaye itumo Matsarah. Matsaratā parā utkarṣaṇam asahanam. Ninu ile aye yi, ti aburo eyan gan ba lowo, awon eyan ma jowu re, " Oh aburo mi ti lowo. Mi o sini>" Nkan ton sele niyen. Ijowu. Nitripe oti pe ta tin se lati Krsna gan. " Kilode toje wipe Krsna nikan lon gbadun." Ijowu yi ti bere. Gbogbo aye yi kun fun ijowu yi. Moni ijowu si yin, eyin ni simi. Ise ile aye yi niyen. Nibi wanpe ni vimatsarah, kosi ijowu kankan. Bawo leyan sele wa laini ijowu afi toba je elesin Krsna? O gbudo ni. Boseje niyen.

Nitorina ni Śrī Bhāgavata se sowipe dharmaḥ projjhita-kaitavo 'tra paramo nirmatsarāṇām, vāstavaṁ vastu vedyam atra (SB 1.1.2). Dharma... Orisiris eto esin lowa. Ijowu wa ninu wan. Wan esin ton fiku pa awon eranko. Kilode? Teyin ba l'okan to da, te ti Narayan ni bikibi, kilode teyin sen je orun awon eranko yi? Egbudo laanu si wan. Sugbon kosi beyan sele laanu tio ban se elesin, vimatsaraḥ. Nirmatsaraḥ.

Nitorina ni gbogbo wanyi se kun fun ijowu, matsarata. nkan ton pe ni kaitava-dharma niyen. Iyanje ni oruko esin. Gege na oye ko ye wa wipe imoye Olorun yi yato. O si la okan gan Titikṣavaḥ kāruṇikāḥ suhṛdaḥ sarva-bhūtānām (SB 3.25.21). Itumo egbe imoye Krsna yi niwipe afe d'ore si gbogbo awon eyan. Bibeko, ti elesin ninu imoye Krsna yi o ba ri bayi, Kilode to fe se iwaasu imoye Krsna yi ninu gbogbo agbaye? Vimatsarah. Agbudo mo wipe imoye Krsna yi si da gan, gbogbo gbudo gbadun e, ka si ni asepo pelu re.

Itumo imoye Krsna ni imoye Olorun. Awon eya jiya nitoripe kosi imoye Olorun kankan ninu aye wan. Idi fun ijiya wan leleyi.

kṛṣṇa-bahirmukha hañā bhoga vāñchā kare
nikaṭa-stha māyā tāre jāpaṭiyā dhare
(Prema-vivarta)

Ona abayo towa niyen. Lesekese tab gbagbe Krsna, maya ma wa. gege bi Orun ati okunkun, wan jo wa papo. teyin o ba wa sinu ina orun, ema wa ninu okunkun. teyin o ba si inu okunkun, ema wa sinu ina orun. Gege na tawa o ba gba imoye Krsna yi, agbudo gba imoye maya. tawa o ba gba imoye maya, agbudo gba ti Krsna. Legbegbe ara wan.

Itumo imoye Krsna niwipe a jade kuro ninu okunkun. Tamasi mā jyotir gama. Ilana Veda niyen, " Ejade kuru ninu okunkun." Kini okunkun yin? Ironu ara yi.