YO/Prabhupada 0003 - Obirin na L'okurin je

Revision as of 13:49, 26 March 2015 by YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0001 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1975 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

Lecture on CC Adi-lila 1.13 -- Mayapur, April 6, 1975

Prabhupāda:

tām eva toṣayām āsa
pitṛyeṇārthena yāvatā
grāmyair manoramaiḥ kāmaiḥ
prasīdeta yathā tathā
(SB 6.1.64)

Ni igbati o ri obinrin naa, o gba gbogbo okan re, ni osan ati ni oruu, ni pa oro yi, awon ero okan ife jati jati. Kāmais tais tair hṛta-jñānāḥ (BG 7.20). Ni igbati okan eni bati ni ero ife ti o damoran, iye re o si pa re Gbogbo aye nyi lo lori ero ife asagbere. Ile aye ni yi Ati nitori pe mo nse agbere, iwo na nsagbere, oni ka lu ku wa, l'owo ti ero okan mi o ba ti se amu se, ti ero okan re na ti bo si, nigba na mo yo e lota, iwo na a si yo mi lota Ko te mi lorun lati ri wipe o un te siwaju gidi gan. Inu iwo naa o dun, lati ri wipe mo ntesiwaju gidi gan. Igbesi aye ni yi, ijowu, ero agbere, kāma, krodha, lobha, moha, mātsarya. Eyi ni ipile ile aye yi.

Ntorina o ti di... Eko re ni wipe o un se eko lati di asaju ninu oro emi śamo, dama, sugbon ilosiwaju re ni abode nitori wipe obirin ti faa lokan. Nitorinaa, gegebi ilaju aye Vedic, obinrin je gegebi igbeko fun ni ni ilosiwaju ti emi Gbogbo ilana ilaju ko nse nkan miran ju wipe bawo ni a o se fara ye... Obirin... Ma se ro wipe obirin nikan ni obirin Obirin ni okunrin naa. Ma ro wipe obirin ni a da lebi; pe ko je be fun okunrin. Obinrin tumo si pe ka je aye, okunrin naa si tumo si jaye jaye. Iru okan yi, okan yi ni a da lebi. Ti mo ba ri obinrin fun igbadun, eyi je wipe okunrin ni mi Ti obinrin naa ba ri okunrin fun igbadun, eyi je wipe okunrin ni oun naa. Obinrin tumo si igbadun, okunrin naa si tumo si eni ti oun gbadun. Bee na enikei to ba ti ni emi igbadun, a ka kun si okunrin. Nisinyi awon mejeji loko-labo ni won se fun... Olu kalu ku njero, "Bawo ni mo se ma gbadun?" Nitorina ni oun je purusa, lai loju lowo. Bibeko, ni isedale, gbogbo wa ni prakriti, jiva, bi o je okunrin tabi obinrin. Aso ara ni ele yi.