YO/Prabhupada 0231 -Bhagavan tumosi Olori gbogbo aye
Lecture on BG 2.1-5 -- Germany, June 16, 1974
Awon Olori si gba pe Oloru tabi Bhagavan ni Krsna Kini itumo Bhagavan? Itumo re ni eyan to ni àmúyẹ mefa nitoripe Bhagavan ni awon àmúyẹ yi laisi opin, oun ni eyan to lowo ju Aduro owo wi ni Bhagavan ni? asi ni igberaga nitoripe ani awon ile kekere kan, Bhagavan ni Olori gbogbo aye yi Nitorina oun ni eni to lowo ju. Gege na oun lo l'agbara ju gege oun lo gbon ju, be na lo se je eyan to lẹwa ju te ba ri eyan to je pe oun lo lowo ju, oun lo gbon ju, oun lo lewa ju, oun lo de l'agbara ju ni aye yi eti ri Olorun tabi Bhagavan ni yen Gege na nigbati Krsna wa si ile-aye osi fi han pe oni gbogbo amuye wonyi fun apeere, gbogbo eyan lon se igbeyawo. Sugbon Krsna gege bi Olorunt je o si fe iyawo to ju egberun merindilogun Sugbon kon se pe oni kan pere lo wan fun awon iyawo egberun merindilogun O seto fun gbo awon iyawo re ni ààfin ototo. wan si ko gbogbo ààfin na pelu okuta didan, awon ohun ọṣọ-ile ati ehin-erin lon ti se wan wan si fi owu fi se gbogbo awon ijoko awon pelu òdòdó si kun nu ogba na iyen ni kan ko, Osi so ara re soto lana egberun merindilogun gege na lo se gbe pelu gbo awon iyawo re Ko si le fun Olorun lati se, nitoripe Olorun wa ni ibikibi gege na to ba le wa ninu ile egberun merindilogun lasiko kan na, ki lo le fun a ti se?
Gege na Olori to ga ju si wi pe śrī-bhagavān uvāca Ounkooun to ba so, egbudo gba ni ooto oro nitoripe awa ninu ile-aye yi, gbogbo wa ni abàwonàbùkù merin a le se aṣiṣe, asi le ni itanran-ẹni, a feran lati yan iyanje, iye-ara wa osi daju na Imoye to ni soro lo ma wa lati eyan to ni awon abàwonàbùkù merin yin gege na ta ba gba imoye lati eyan to ko ja awon abàwonàbùkù merin wonyi, imoye to dara ni yen je awon oni sayensi eni, wan si so wi pe, "O da bi wipe", imoye to daju ko leleyi ti eyan ban rori wo pelu awon iye-ara to ni mẹhẹ, kini iwulo iru imoye bayi? imoye t'ẹgbẹkan lo ma je Nitorina imoye ti wa ni lati eyan ti o ni awon abàwonàbùkù merin lo ti wa Nitorina imoye wa ati Krsna loti wa, imoye na si niyi Bi omode Omode na le ma l'ogbon sugbon ti baba re ma so wipe, " Omo mi ìríranawòìwojú leleyi Ti omo ba de tun so " ìríranawòìwojú leleyi". Imoye to da ni yen Omode na ko si le se isoro ati waadi fun ara re A kan bi baba re, " baba ki leleyi"? Mama re asi so fun "nkan bayi ni yen"? Ipeere imi ta le wo ni t'omode ba fe mo eni ti baba re je ko ye ko se iwaadi kankan To ba fe se iwaadi lati wa baba re, ko ni le mo eyan ti baba re je sugbon to ba bi mama re, " tani baba mi", iya a si so fun " Eyan bayi ni baba re" Nitorina bawo lese fe ni imoye Olorun, eyan to ko ja ogbon yin. bawo lese fe mo? Nitorina egudo mo nipa Olorun lati Olorun fun ara re.
Gege na ni ibi, Krsna, Olorun sin sooro.. O si wi fun Arjuna aśocyān anvaśocas tvaṁ prajñā-vādāṁś ca bhāṣase: (BG 2.11) Ore mi Arjuna, osin sooro bi alakowe sugbo osin ke fun nkan ti o niyi Gatāsūn agatāsūṁś ca nānuśocanti paṇḍitāḥ. Ara ni itumo Gatāsūn Boya ara eyan wa laaye tabi osi ti ku, eto ara eyan ko si ni iwulo Eyan to keko o le mu ni pataki eto ara eda. Nitorina awon iwe mimo Veda so wi pe, eyan to mu bi pataki eto arare, ko ju eranko lo nitorina laye isin gbogbo eyan s'eto ara wan sugbon eto ara si wa laarin awon eranko awon aja tabi ologbo wan si ni igberaga to ba ti tobi si gege na ti eyan ba ni igberaga pe " Omo Orile-ede America ni mi, tabi Omo orile-ede Germany to ga ni mi, Ni wa ni iyato? Sugobn nkan ton sele ni yen> Nitorina wan ja bi aja ati ologbo Ni ola am tun soro si