YO/Prabhupada 0286 - Ifekufe laarin eyin ati Krishna

Revision as of 15:15, 11 April 2015 by YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0286 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1968 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

Lecture -- Seattle, September 30, 1968

Ko si isoro. Agbudo ko basele ni'fe fun Krsna ilana tele gba fi se de tiwa awa de fe sise fun yin asi ti ran gbogbo awon Okurin wa lati jadi lo pe yin wa teba si gba anfanni ta gbe wa, ile-aye yin ma ni ilosiwaju Premā pum-artho mahān, nitoripe ile-aye yi wa lati le ni'fe Oluwa nitoripe gbogbo wa la ni'fe ninu aye wa ati nife fun, awon omo wa, tabi iyawo wa, tabi awon eye wa Ife wa. Kosi iwulo lati bere sini ko awon eranko bon sele nife fun awon omo wan koni wuol, nitoripe nkan adayeba loje lati nife fun ile, fun Ilu tewa, fun Oko tefe, fun awon omo tebi, fun iyawo yin,..iru ife bayi si wa ninu ijoba awon eranko sugbon iru ife bayi kosi bosele fun yin ni itelorun Ibanuje lo ma bayin, nitoripe fun igbadie ni ile-aye yi nitorina gbogbo awon ife yi fun igba die na lon je, ife aye yi de n wan ife to yisodi lon je, oyato si ife larin eyin ati Olorun, Krsna teba fe ni itelorun tabi alaafia ti eyan o ba fe ni idamu, ogbudo ko bon sen nife Krsna ise to wa niyen. Ile aye yin ma ni ilosiwaju imoye Krsna yi kon se nkan ton da lati fi po inu awon eyan Imoye ton ti fun l'ase Awon Iwe mimo Veda, gege bi Bhagavad-gītā, Śrīmad-Bhāgavatam, Vedānta-sūtra, Purāṇas, opolopo awon alufaa lon de tin sise yi apeere to da gan ni Caitanya Teba ri aworan re, O sin jo egudo ko ise yi, ile-aye yin ani ilosiwaju koyeke ma se igbaradi fun awon nkan atowoda eyin si ni iwa lati nife fun awon eyan iwa adayeba loje sugbon ati nife fun nkna ti oye gege na ati ni ibanuje. Ti eyan oba feni idamu Teeba fe ni ibanuje, egbudo gbiyanju lati nife fun Krsna lehin na ema ri pe ema ni alaafia ati idunnu nigbogbo nkan teba fe.

Ese pupo