YO/Prabhupada 0218 - Guru ma laa oju yin
Lecture on SB 6.1.55 -- London, August 13, 1975
Eda eniyan ni wa, nkankan na ni wa pelu Krsna Gege bi ina ati awọn erunrun ton jade latinu ina. tabi õrùn ati awon erunrun ilana didan ton se asepo lati di itansan oorun itansan oorun ti awan man ri lojojumo ìkaánnà ko lo je, awon erunrun kekere ton dan wa ninu wan gege bi awa na se ri ni yen Gege bi awon átọ̀mù se wa gegena ni awa na se wa Melo la je, koseni to le ka. Asaṅkhyā. itumo Asaṅkhyā ni nkan ti eyan o le ka. awon eda eyan repete gege na erunrun kekere la je asi ti wa sinu ile-aye yi gege bi awon Arakunrin ilu Yuroopu, ti won lati ilu si ilu lati le gba ijoba lowo awon omo orile-ede lehin na wan si mu gbogbo èròjà iṣẹ́ fun ara wan nikan nigbati wan ṣàwárí Orile-ede America awon arakurin lati yuropu si lo si be ni alakoko wan fe lo si be lo .... Niisin wan fe lo si oṣupa lati wo boya wan le gbe ni be àsà eda eyan leleyi je wan si ti wa sinu aye yi . Kṛṣṇa bhuliya jīva bhoga vāñchā kare. itumo purusa ni bhokta.
Bhokta. Itumo bhokta ni Krsna Bhoktāraṁ yajña-tapasām (BG 5.29). awa fe fi ara we Krsna. Ipo wa ni yen Gbogbo eyan fe di Krsna Awon Māyāvādīs, ton ti gba orisirisi awe wan sin tele awon ofin nipa ti ẹmi sugbon nitoripe wan wa labe ise māyā, wan si ronu pe wan ti di Olorun. Itumo purusa ni bhokta. Pe..Krsna ni mo je ..." Bhoktāraṁ yajña... lehin igba ti won ti se itesiwaju pelu gbogbo awe ton gba, ati ofi ton tele sugbon maya si l'agbara gan awon eyan yi won si ro pe " Alagbara ni mi" wan si ro pe alagbara bi ti Krsna lon je Paraṁ brahma paraṁ dhāma pavitraṁ paramaṁ bhavān, puruṣam śāśvata: (BG 10.12). Purusa le je. Sugbon māyā si l'agbara gan lehin gbogbo aye atunwa ti awon eyan yi ti wa wan si ro nu pe " alagbara ni mo je" aarun aye ni yi.
Gege na iwe mimo so wi pe eṣa prakṛti-saṅgena puruṣasya viparyayaḥ Ile-aye re bere lati pe wan ronu pe " Alagbara ni mo je" ko si le fi ironu bayi si le lati aye kan si ikeji.. nitoripe awon eda se nkaana pelu Olorun, Olurun si je sac-cid-ānanda-vigrahaḥ (Bs. 5.1), sac-cid-ānanda-vigrahaḥ ni awa na je, sugbon sac-cid-ānanda-vigrahaḥ kekere Sugbon prakrti ni ipo wa, kon se purusa Gege bi Rādhā ati Kṛṣṇa, nkankan na ni wan Rādhā-kṛṣṇa-praṇaya-vikṛtir hlādinī-śaktir asmāt. nkankan ni wan, sugbon prakrti ni Rādhā gege na purusa ni Kṛṣṇa Bakanna, botilejepe nkan ni wa pelu Krsna, sugbon prakrti si ni wa. Krsna ni purusa awan ro pe a le di purusa, nkan ton pe ni maya tabi viparyayah ni yen. Iwe mimo si ti so wi pe. Evaṁ prakṛti-saṅgena puruṣasya viparyayaḥ. Itumo Viparyayah ni wi pe O lati gbadun pelu purusa ti purusa ati prakrti gban gbadun, awon meejeji lon gbadun sugbon ikan je purusa ikeji je prakrti bakanna, Purusa ni Krsna je, prakrti de ni wa ti awa ba gbadun pelu Krsna igbana ni sac-cid-ānanda ma wa sugbon ati gbagbe, asi fe di purusa bakan tabi awon miran, ipo yi ti bo sinu aye wa. Ipo pe a fe di purusa ki wa ni abajade na? Esi na ni wi pe lati aye kan si ikeji awa seto lati le gbadun awon nkan aye sugbon ko le bosi sugbon awon eyan seto lati le gbadun. Ipo wa ni yen.
Bawo le se le fi ipaari si ijaakadi yi e ba fe pada si ipo yin? Sa eva na cirād īśa-saṅgād vilīyate. Agbudo fi ipaari si ìròiyè inú pe purusa ni wa bawo? Īśa-saṅga, pelu asepo pelu Oluwa, Īśa. Itumo Īśa ni oludari. Īśa-saṅga. Nibo ni Īśa wa? mi o leri Īśa. Īśa ni Krsna, Oluwa sugbon mi o leri Krsna wan bi. Afoju ni e. Kilode ti wo o leri? Nitorina eyin o leri. Egbudo laaju Ise guru(Oluko) niyen. Guru ma laaju yin.
- ajñāna-timirāndhasya
- jñānāñjana-śalākayā
- cakṣur unmīlitaṁ yena
- tasmai śrī-gurave namaḥ
- (Gautamīya Tantra)
Bawo ni Krsna a se laaju yin? jñānāñjana-śalākayā. ninu òkunkun awa o le ri nkankan sugbon te ba ni isana, te ba detan ale ri ran bakanna ise gur(Oluko) ni lati si oju wa lati si oju wa A fi ye wa pe, awa o kin se Purusa. Prakrti la je Imo ohun Krsna leleyi.