YO/Prabhupada 0070 - E ṣakoso awọn nkan dada

Revision as of 18:51, 14 October 2018 by Vanibot (talk | contribs) (Vanibot #0023: VideoLocalizer - changed YouTube player to show hard-coded subtitles version)
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Room Conversation -- April 22, 1977, Bombay

Prabhupāda: E di ilana wa mu, ke si ri wipe GBC wa nse isora pupo. Nigba na ni awon nkan ma lo dede, paapa ti mi o ba si nbe. E se yen. Iyen ni mo be yin. Ohunkohun kekere ti mo ba ti ko yin, e tele yen, ko si si eni ti o ma ni iponju. Ko si owo maya(Esu) ti o ma kan yin. Nisinyi Oluwa ti bukun wa, beni a ko ni ri ogun ailowo lowo. E te awon iwe ki e si ma ta won. Gbogbo nkan ti wa nbe. A ni awon abobo to dara kari aye. A ni ere to nwole. E di awon ilana wa mu, ki e si ma tele... Bi mo ti le se alaisi ni ojiji, e o lagbara lati s'abojuto. Ko ju yen lo. Bi mo se fe ni yen. E se akoso dara dara, ki e si je ki egbe yi ni ilosiwaju. E se eto na bayi. E ma se fasehin. E ma sora. Āpani ācari prabhu jīveri śikṣāya.