YO/Prabhupada 0198 - Egbudo fi awon iwa tio d ayi sile ke si korin Lori awon ileke yi, Hare Krishna mantra

Revision as of 19:12, 14 October 2018 by Vanibot (talk | contribs) (Vanibot #0023: VideoLocalizer - changed YouTube player to show hard-coded subtitles version)
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Temple Press Conference -- August 5, 1971, London

Oniroyin obirin: iwonba awon elesin melo leni ninu gbogbo agbaye tabi kole se ka...?

Prabhupada: fun gbogbo nkan to daju, awon onigbogbo ninu e o kin saba po, sugbon awon nkan iranu opolopo awon eyan lon tele.

Oniroyin Obirin: Nkan ti mo fe bere ni awon elesin melo tonti tẹbọmi...

Prabhupada: wan to ẹgbẹ́ẹdógún. Oniroyin obirin: S'on posi nigbogbo 'gba?

Prabhupada: Beeni, die die lon tesiwaju. Nitoripe awa sini awon ofin to po gan. Awon eyan o de feran awon ofin.

Onirohin Obirin: Beeni. Nibo ni awon elesin yin ti po gan? Se ninu Orile-ede America?

Prabhupada: Ni America, ni Europu ati Canada, ni Japan, Australia. Ati ni Orile-ede India wan po repete, awon eyan egbe yi po gan. Afi India ninu awon orile-ede imi iwonba die die lonwa. Sugbon ni orile-ede India wan to Adaadọta-Ọkẹ.

Oniroyin Okurin: Seyin rowipe egbe yi ni ona kan soso to wa lati fi mo Olorun?

Prabhupada: Kini yen?

Elesin: Seyin rowipe egbe yi ni ona kan soso lati fi mo nipa Olorun?

Prabhupada: Beeni.

Oniroyin Okurin: Bawo leyin se mo?

Prabhupada: Lati awon oludari, lat'Olorun, Krsna. Kṛṣṇa sowipe, sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66).

Oniroyin Okurin: Sugon telomi ba sowipe Olorun so bayi bayi s'oun seyin na ma gba?

Śyāmasundara: Kon sepe awa o ni'gbagbo ninu awon ilana awon esin to yato si tawa.

Prabhupada: Rara, awa ni'gbagbo ninu awon ilana iyoku. Gege bi awon abagunke. teba fe gunke papata ni ile-giga, egbudo gba awon abagunke. Awon ile imi le ni abagunke to po to aadọta, imi le ni to ọgọrun sugbon lati de oke patapata, agbudo gun to abagunke egberun.

Oniroyin Okurin: Seyin ti gun awon abagunke egberun wanyi?

Prabhupada: Beeni.

Oniroyin Obirin: Ti ikan ninu wa nibi laaro yi fe di elesin kilo ye ka se tabi kama e?

Prabhupada: Ni alakoko egbudo fi imoako ati abo sile.

Oniroyin Obirin: Seyen wipe awa o gbudo ni asepo kankan mo tabi...?

Prabhupada: Huh?

Oniroyin Obirin: Kinitumo o lodi?

Prabhupada: imo ako ati abo .. laisi igbe yaw, laisi awon ofin, imo to yi sodi niyen.

Oniroyin obirin: Gege na eyan le ni asepo pelu oko re tabi iyawo re, sugbon koma lo s'ita.

Prabhupada: Imo ako ati abo bi awon eranko niyen. Gege bi awon eranko, kosi ibasepo kankan laarin wan sugbon wan ni imo ako ati abo yi. Sugbon ninu awujo awon eda eyan awon ofin wa. Ni gbogbo orile-ede, tabi esin gbogbo wa ni ilana tonfi se igbeyawo. Laisi igbeyawa, eyan o gbudo se imo ako ati abo.

Oniroyin obirin: Sugbon a le se taba ti fe ara wa tan.

Prabhupada: Beeni,.. Oniroyin Obirin: Kilo tun ku teyan gbudo m'ase.

Prabhupada: Eyan gbudo fi gbogbo awon oti sile. Oniroyin Obirin: Se awon ogun ati oti?

Prabhupada: Orisirisi awon ogun tole jeke yo.

Śyāmasundara: pelu tii gan.. Prabhuada: tii, ciga. Gbogbo wan lon le po wa lori.

Oniroyin obirin: Se oti, taba lile, tii. Kilo tun ku?

Prabhupada: beeni. Agbudo fi gbogbo awon ounje pelu eran. gbogbo ounje tol'eran. Eran, eyin, eja, bayi bayi lo. Agbudo ma ta tete mo. Oniroyin obirin: Sa gbudo fi awon ebi sile? Mo rowipe gbogbo awon eyan yi lon gbe ninu ile-ijosin, abi se beeko?

Prabhupada: OH, beeni. Afi teyan ba fi awon iwa elese yi sile kosi basele teboomi.

Oniriyin Obirin: Se agbudo fi awon ebi wa sile na>?

Prabhupada Ebi? Oniroyin Obirin: lati le... beeni.

Prabhupada: beeni, ebi. Awon ebi wanyi o kan wa, awon eyan na lo kan a> teyan ba fe se iteboomi nini egbe imoye Krsna yi ogudo fi gbogbo awon ise elese yi sile.

Oniroyin Obirin: Sema fi awon ebi yin sile na.

Syamasundara: Rara, rara, kosidi pe ke fi awon ebi yin sile.

Oniroyin Obirin: Sugbon kasowipe mofe di elesin nisin. Se dandan ni ko pe mo gbudo wa gbe pelu yin?

Syamasundara: Rara.

Prabhupada: dandan ko loje.

Oniroyin Obirin: Mole wa ni ile mi?

Prabhupada: Oh, beeni.

Oniroyin Obirin: Ise mi nko? So ye kin fisile?

Prabhupada: egbudo fi awon iwa tio d ayi sile ke si korin Lori awon ileke yi, Hare Krsna mantra. Otan.

Oniroyin Obirin: Se dandan ni kin fun yin ni iranlowo pelu owo?

Prabhupada: Rara, bose wuniyin niyen. Teba funwa, o da. Bibeko kosi wahala.

Oniroyin Obirin: Edakun, koye mi.

Prabhupada: Awa o fe, bi awon eyan seni to le je. Awa si gbokan le Olorun, tabi Krsna.

Oniroyin Obirini: Gege na kon se dandan kin fun =yin lowo.

Prabhupada: Rara.

Oniroyin Obirin: Se iru nkan bayi ni iyato laarin awon guru eke ati guru gidi?

Prabhupada: Beeni. Onisowo ko ni guru gidi je.