YO/Prabhupada 0518 - The Four Functions of Conditional Life Means Birth, Death, Old Age, and Disease

Revision as of 21:26, 26 July 2015 by Rishab (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0518 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1968 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

Lecture on BG 7.1 -- Los Angeles, December 2, 1968

teba fe yonju isoro aye yi pelu ona abayo latinu aye yi, oma le gan. wanti salaaye bayi. ninu Bhagavad-gītā wansowipe daivī hy eṣā guṇamayī mama māyā duratyayā (BG 7.14). Krsna ti juwe ile-aye bi "agbara re", mama māyā... agbara imi Krsna niyen. wanti salaaye gbogbo nkan ninu ese-iwe kesan. nitorina o le gan lati jade kuro ninu agbara yi. Ale ri fun ara wa? agbara wa si kere gan lati fipari si awon ofin aye yi. ilokulo asiko wa niyen. Kosi besele ni idunnu teba ni idari lori ile-aye yi. Nisin sayensi ti da orisirisi nkan sile. gege bi oko-ofurufu lati orile-ede India aimoye osu toma lo keyan tode ilu yin, sugbon pelu oko-ofurufu ale debi nijokan soso. awon anfanni bayi si wa. sugbon pelu gbogbo ilosiwaju wanyi, awon isoro wan si po gan. teba wa ninu oko-ofurufu, ten fo loke kosi besele mo igbati oko na le ni ìkùnà ele jabo inu omi, tabi ibikibi. nitorina kofi be daju. gege na gbogbo ona tawa ba daale lati fi ni idari lori iseda gbogbo wan loni wahala ton tele wan. Ofin aye yi niyen. ona abayo lati isoro aye yi koni yen. ona toye ka gba ni basele fiipaari si awon isoro merin wanyi. ibimo, iku, ojo-arugbo ati aisan. awon isoro merin tani Emi mimi nimi. Bhagavad-gītā ti salaaye.. emi wa o le ni ibimo tabi iku. lehin igbati ara re pa ni ipaari asi wa laaye. bi isana ni ara wa seri, sugbon fun iwonba odun die sugbon tobaya atan. die die lon ton lojojumo. gege bi moseje okurin pelu adorin odun tinba gbe sinu aye yi fun odun ogorin tabi ogorun, awon odun metaleladorin wanyi tokaoja, oti ku niwonba awon odun yi. Otan Asiko die loku funmi. lati igba ti wan ti bimi nimotin ku. oto-oro niyen Bhagavad-gītā ti funwa ni onaabayo fun gbogo isoro merin wanyi. Krsna de ti sofun wa wipe, mayy āsakta-manāḥ pārtha yogaṁ yuñjan mad-āśrayaḥ. teba teriba funmi, teba ronu mi nigbogbo igba ti okan yin ba kunfun awon iron nipa Krsna Krsna sowipe abajade towa niwipe, asaṁśayaṁ samagraṁ māṁ yathā jñāsyasi tac chṛṇu (BG 7.1). "lehin na ema ni oye nipa mi, kosejo mi">