YO/Prabhupada 0723 - Chemicals Come From Life; Life Does Not Come From Chemical

Revision as of 14:56, 15 August 2015 by Rishab (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0723 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1974 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

Lecture on BG 7.4 -- Bombay, February 19, 1974

Prabhupāda: Emi wa, ara eda na si wa ara emi na si wa. ei wa ni koko oro, sugbon lati ni ara yi, moti salaaye tele, nkan ton jade latinu baba asi papo pelu t'iaya wansi di nkan kekere bi eso. Latinu ato baba l'emi tin jade, ibi to wa niyen Ara na asi bere sini dagba. E gbiyanju ko ye yin. Nitoripe emi wa nitorina ni ara na sen dagba T'emi na o ba sin be, ara omode na o le dagba. Koni si idagba soke mo. Omo to ti ku kole dagba. Gbogbo eyan lo mo. Nitorina awon nka aye yi lat'emi lonti wa, kon se pe lati nkan aye yi l'emi ti wa. Beeko. Ilana iro leleyi. toba jepe lati nkan aye yi loti wa, kilode teyin o le d'aye sile ninu ile ise yin... ile aye yi wa nitoripe Olorun si fe ko wa, anumanta, Olorun lon p'ase - Oun lon funwa laaye lati wonu oyun mama wa, kasi dagba. Lat'emi ni gbogbo nkan wanyi ti wa Fun apeere... Ti ba mu awon kemika Nisin, emu igi osan, eda loje osin da omi osan to po. teba mu osan wewe aadota leni te mu aadota loola, tesi yo omi osan wewe na, ema ri omi osan na to po. nibo ni omi osan wewe yi tin wa? nitoripe eda na wa ninu igi O daju pe lat'emi ni omi osan yi tin wa; Aye o le ti kemika wa. t'aye ba le ti kemika jade, kilode teyi n o le d'aaye sile. ma fun yin ni awon kemika teba fe. gege bi teyin ban laagun. teba towo, ema riwipe, iy wan'be, nibo ni iyo yi tin jade? Iyo... Kil'oruko iyo? Sodium carbonate rara?

Olufokansi: Chloride.

Prabhupada: Sodium chloride. Sodium chloride. So sodium chloride, nibo loti wa? Lat'ara yin loti wa, lat'emi yin l'ara yin tin wa. Nitorina emi wa ni orisun sodium chloride yi. Beena beyin sele wo awon kemika lati ara igi, ati ara yin, beena seyin le fori ro aduru omi to wa ninu ara Krsna, virat purusa, aduru kemika to le da. Nitorina, ema rowipe awa kon fori ro. Krsna sowipe

bhūmir āpo 'nalo vāyuḥ
khaṁ mano buddhir eva ca
ahaṅkāra itīyaṁ me
bhinnā prakṛtir aṣṭadhā
(BG 7.4)

" Awon nka aye mejo wanyi, tita ati tinu, agbara mi niwon." Toba ti Krsna wa. Isokuso ko ni Krsna n'so. Kose igberaga kankan. Eyin tesi keko, kilode te sen ka Bhagavad-gita? Nitoripe o daju, Krsna lon soro. Otooro niyen. Olori to gaju. Agbodo gba imoye lati olori, awa o le da imoye wa sile. Imoye tio daju leleyi nitoripe iye ara wa o je pipe