YO/Prabhupada 0117 - Hotẹẹli ofe ati ibugbe ofe: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0117 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1976 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0023: VideoLocalizer - changed YouTube player to show hard-coded subtitles version)
 
Line 5: Line 5:
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Srimad-Bhagavatam]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Srimad-Bhagavatam]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Mayapur]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Mayapur]]
[[Category:YO-Quotes - in India]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0116 - Ema fi iyé aye yin sofo|0116|YO/Prabhupada 0118 - Iwaasu wa ki se ohun ti o soro rara|0118}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 14: Line 18:

<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|F1x4RgM7iGs|Free Hotel and Free Sleeping Accommodation - Prabhupāda 0117}}
{{youtube_right|Sq6R2qEWLkI|Free Hotel and Free Sleeping Accommodation - Prabhupāda 0117}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/760302SB.MAY_clip.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/760302SB.MAY_clip.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 28: Line 32:
Eyi ni ero na, lati di iranṣẹ ati lati di iranṣẹ-binrin. Eleyi jẹ apẹrẹ ti ọlaju eniyan. Olukaluku awọn obirin yẹ ki o gbiyanju lati di iranṣẹbinrin ti ọkọ rẹ, o si yẹ ki gbogbo ọkunrin gbiyanju lati di iranṣẹ ti Olorun ni igba ọgọrun. Eleyi jẹ ọlaju India , ki se wi pe "Ọkọ ati iyawo, a wa dogba ninu awọn ẹtọ." Wipe, ni Yúróòpù, Amẹríkà, irunkan bayi sele. "idogba awọn ẹtọ." Iyen ki se ilana Vediki. Ilana aiye ọlaju Vediki ni pe ọkọ yẹ ki o je iranṣẹ olododo ti Olorun, ati ki awọn aya jẹ iranṣẹbinrin olododo ti awọn ọkọ.  

Nitorina nihinyi o ti wa wipe,, upanaya māṁ nija-bhṛtya-pārśvam ([[Vanisource:SB 7.9.24|SB 7.9.24]]). Eyi ni ibasepo ti o dara ju.. Nigba ti Nārada Muni ti nse apejuwe bi ọkunrin se yẹ ki o huwa, bi obinrin se yẹ ki o huwa ... A ti wa ni jíròrò bayi ninu ero agbohunsilẹ wa, e ma gbo nipa re. Wipe ko si iru ohun na bi lati di ọgá. Asan ni. Iwo ko le di ọgá. Ahaṅkāra-vimūḍhātmā kartāham iti manyate ([[Vanisource:BG 3.27|BG 3.27]]). Iwo ko le di ọgá. Jīvera svarūpa haya nitya kṛṣṇa dāsa (Cc. Madhya 20.108-109). Boya ọkunrin tabi obinrin, gbogbo eniyan ni iranṣẹ ti Olorun. A ni lati se oṣiṣẹ de bi wipe, bawo ni a se le di iranṣẹ ti o dara ju, iranse nikan ko, sugbon iranse ti awon iranse toku. Eyi ni a npe ni iranṣẹ paramparā. Iranse ni oluko igbala mi je fun oluko igbala re, iranse ni emi na si je fun oluko igbala mi. Bákan náà, a rò pé "iranṣẹ ti awọn iranṣẹ." Ko si ni ibeere ti di... Eyi ni aisan aye ([[Vanisource:CC Madhya 13.80|CC Madhya 13.80]]).  
Nitorina nihinyi o ti wa wipe,, upanaya māṁ nija-bhṛtya-pārśvam ([[Vanisource:SB 7.9.24|SB 7.9.24]]). Eyi ni ibasepo ti o dara ju.. Nigba ti Nārada Muni ti nse apejuwe bi ọkunrin se yẹ ki o huwa, bi obinrin se yẹ ki o huwa ... A ti wa ni jíròrò bayi ninu ero agbohunsilẹ wa, e ma gbo nipa re. Wipe ko si iru ohun na bi lati di ọgá. Asan ni. Iwo ko le di ọgá. Ahaṅkāra-vimūḍhātmā kartāham iti manyate ([[Vanisource:BG 3.27 (1972)|BG 3.27]]). Iwo ko le di ọgá. Jīvera svarūpa haya nitya kṛṣṇa dāsa ([[Vanisource:CC Madhya 20.108-109|CC Madhya 20.108-109]]). Boya ọkunrin tabi obinrin, gbogbo eniyan ni iranṣẹ ti Olorun. A ni lati se oṣiṣẹ de bi wipe, bawo ni a se le di iranṣẹ ti o dara ju, iranse nikan ko, sugbon iranse ti awon iranse toku. Eyi ni a npe ni iranṣẹ paramparā. Iranse ni oluko igbala mi je fun oluko igbala re, iranse ni emi na si je fun oluko igbala mi. Bákan náà, a rò pé "iranṣẹ ti awọn iranṣẹ." Ko si ni ibeere ti di... Eyi ni aisan aye ([[Vanisource:CC Madhya 13.80|CC Madhya 13.80]]).  

:kṛṣṇa bhuliya jīva bhoga vāñchā kāre
:kṛṣṇa bhuliya jīva bhoga vāñchā kāre

Latest revision as of 18:59, 14 October 2018

Lecture on SB 7.9.24 -- Mayapur, March 2, 1976

Eyi ni ero na, lati di iranṣẹ ati lati di iranṣẹ-binrin. Eleyi jẹ apẹrẹ ti ọlaju eniyan. Olukaluku awọn obirin yẹ ki o gbiyanju lati di iranṣẹbinrin ti ọkọ rẹ, o si yẹ ki gbogbo ọkunrin gbiyanju lati di iranṣẹ ti Olorun ni igba ọgọrun. Eleyi jẹ ọlaju India , ki se wi pe "Ọkọ ati iyawo, a wa dogba ninu awọn ẹtọ." Wipe, ni Yúróòpù, Amẹríkà, irunkan bayi sele. "idogba awọn ẹtọ." Iyen ki se ilana Vediki. Ilana aiye ọlaju Vediki ni pe ọkọ yẹ ki o je iranṣẹ olododo ti Olorun, ati ki awọn aya jẹ iranṣẹbinrin olododo ti awọn ọkọ.

Nitorina nihinyi o ti wa wipe,, upanaya māṁ nija-bhṛtya-pārśvam (SB 7.9.24). Eyi ni ibasepo ti o dara ju.. Nigba ti Nārada Muni ti nse apejuwe bi ọkunrin se yẹ ki o huwa, bi obinrin se yẹ ki o huwa ... A ti wa ni jíròrò bayi ninu ero agbohunsilẹ wa, e ma gbo nipa re. Wipe ko si iru ohun na bi lati di ọgá. Asan ni. Iwo ko le di ọgá. Ahaṅkāra-vimūḍhātmā kartāham iti manyate (BG 3.27). Iwo ko le di ọgá. Jīvera svarūpa haya nitya kṛṣṇa dāsa (CC Madhya 20.108-109). Boya ọkunrin tabi obinrin, gbogbo eniyan ni iranṣẹ ti Olorun. A ni lati se oṣiṣẹ de bi wipe, bawo ni a se le di iranṣẹ ti o dara ju, iranse nikan ko, sugbon iranse ti awon iranse toku. Eyi ni a npe ni iranṣẹ paramparā. Iranse ni oluko igbala mi je fun oluko igbala re, iranse ni emi na si je fun oluko igbala mi. Bákan náà, a rò pé "iranṣẹ ti awọn iranṣẹ." Ko si ni ibeere ti di... Eyi ni aisan aye (CC Madhya 13.80).

kṛṣṇa bhuliya jīva bhoga vāñchā kāre
pāsate māyā tāre jāpatīyā dhāre.

Lesekese ti aba ti ni igberaga - "Bayi emi yio di ọgá. Emi o kan ma pase. Emi o ni tele enikankan" - ise māyā niyen.

Beni aarun na se nlọ bẹrẹ lati ori Brahma s'isalẹ kan awọn eèrà. Prahlāda Mahārāja ti ni oye nkan ti a npe ni ipo igberaga asan a ti d'oga. O si wipe "Mo ni oye nipa igberaga eke yi" Edakun e funmi ni ise... Nija-bhṛtya-pārśvam. Itumo Nija-bhṛtya-pārśvam niwipe gege bi olukọṣẹ ọkunrin Olukọṣẹ, olukọṣẹ kan ma kose l'odo akọsẹmọsẹ ọkunrin. Bi ere bi ere, olukọṣẹ na kẹkọọnípa bawo ni lati ṣe awọn nkan. Nitorina o si wipe, nija-bhṛtya-pārśvam. Ki se wipe lẹsẹkẹsẹ emi o sì di iranṣẹ akọsẹmọsẹ gidigidi, ṣugbọn jẹ kí n ... Idi fun egbe wa niyen. teyan ba wasibi fun ounje ofe, ati yara ofe, wiwa re si ibasepo wa je asan. O si gbodo ko bi lati maa sise. Nija-bhṛtya-pārśvam. Awon ti won nsise, won... O yẹ ki o kọ ẹkọ lọdọ rẹ bi o ti n see se fun wakati merinlelogun; lẹhinna didarapo wa mo egbe yi yio jẹ aseyori. Ati ti a ba gbà a wipe "Eyi jẹ ẹya egbe ibi ti a ti le ni hotẹẹli ofe, ibugbe ofe, ati igbadun lofe", lẹhinna gbogbo egbe yoo wa ni ibaje. E ṣọra gan. Gbogbo awon GBC, won gbodo ṣọra gan ki iru iwa bayi ma se alekun. Eni kòòkan yẹ ki o ni itara gidigidi lati see se, lati ko bi won se nsee se. Nija-bhṛtya-pārśvam, Nigbana ni aye yio jẹ aseyori.

E ṣeun pupọ.