YO/Prabhupada 0219 - Efi ironu iranu yi si le, pe efe d'oga: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0219 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1976 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0005 edit: add new navigation bars (prev/next))
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in India, Mayapur]]
[[Category:YO-Quotes - in India, Mayapur]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0218 - Guru ma laa oju yin|0218|YO/Prabhupada 0220 - Nkankanna pelu Oluwa ni gbogbo awon eda|0220}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 15: Line 18:

<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|YSo2n7TuvgY|Give up This Nonsense Idea of Becoming Master - Prabhupāda 0219}}
{{youtube_right|YSo2n7TuvgY|Efi ironu iranu yi si le, pe efe d'oga<br />- Prabhupāda 0219}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/760302SB.MAY_clip2.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/760302SB.MAY_clip2.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 27: Line 30:

<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Ni Orile-ede yin, opolopo awon ni aaarun iba ki wa ni iyato? gege bi eyan ton s'iṣẹ oogun, kilode ten fi so wi pe aarun da ju ikeji lo? ko si iyato larin aarun. Eyin so wi pe ani aarun iba, sugbon ko ba ti da boba je pe syphilis la ni. rara. gege, boya Brahma tabi kokoro, aarun wa ni wi pe afe di Oga Krsna de ti wa lati fi ipaari si aarun yi Asiwere, ogo ko lo je, iranse ni ye. Teriba fun mi. iwosan aarun yin leleyi ti awa ba si gba pe awa o fe d'oga mo, āra nāre bapa iwosan ta gbudo gba ni yen  
Ni Orile-ede yin, opolopo awon ni aaarun iba ki wa ni iyato? gege bi eyan ton s'iṣẹ oogun, kilode ten fi so wi pe aarun da ju ikeji lo? ko si iyato larin aarun. Eyin so wi pe ani aarun iba, sugbon ko ba ti da boba je pe syphilis la ni. rara. gege, boya Brahma tabi kokoro, aarun wa ni wi pe afe di Oga Krsna de ti wa lati fi ipaari si aarun yi Asiwere, ogo ko lo je, iranse ni ye. Teriba fun mi. iwosan aarun yin leleyi ti awa ba si gba pe awa o fe d'oga mo, āra nāre bapa iwosan ta gbudo gba ni yen.

Nitorina Caitanya Mahāprabhu wi pe, gege bi Prahlāda Mahārāja ti so nija bhṛtya-pārśvam: ([[Vanisource:SB 7.9.24|SB 7.9.24]]) E fi mi se iranse to kere ju laarin awon iranse yin nkan na ni Caitanya Mahāprabhu so, gopī-bhartur pada-kamalayor dāsa-dāsa-anudāsaḥ ([[Vanisource:CC Madhya 13.80|CC Madhya 13.80]]). Bakanna egbe Krsna wa yi itumu re ni wi pe agbudo gbagbe eto pe afe di Oga Agudo ko lati di iranse Oluwa Sugbon iranse ni kan ko, agbudo di iransi si awon iranse Oluwa Nitorina Prahlāda Mahārāja so wi pe, O si ti ye mi pe agbudo fi gbogbo iranu pe afe di Oga si le Baba temi na seto lati di Oga. Ko si iwuolo pe afe di Oga Te ba fe fun mi ni ibukun, e se mi ni iranse yin Ibukun to dara leleyi je gege na eyan to ti ko lati di iranse Oluwa, eni na ti se aseyori Nitorina Caitanya Mahāprabhu so wi pe, tṛṇād api sunīcena taror api sahiṣṇunā. Iranse ni lati faramo nkn to po Igbami Oga wa le beere nkan to po, iru nkan bayi le di isoro fun iranse sugbon o gbudo faramo. Itesiwaju ni yen Ni Orile-ede India , ti eyan ba fe gbe iyawo Asa lo je ni be Iya re a si bi leere," Omo mi ibo ni won lo? Idaaun re ni pe " mama mi mo fe lo gbe iranse kan wa fun yin" Asa to wa ni yen " Mama, mo fe lo gbe iranse kan wa fun yin" itumo yen ni wi pe " iyawo mi, aya yin lo je, o ma se ise fun yin gege bi iranse" Asa Veda ni eyi je.  

Nigbati Krsna lo si ilu Hastinapura pelu awon iyawo egberun merindilogun asa awon obirin ni wi pe won man soro laarin ara wan ni pa oko won.. Gege na Draupadi se ibeere lati gbogbo iyawo Krsna Sugbon gbogbo wan ko ... wan ti poju amo a e so wipe o beere lowo awon iyawa t'alakoko kini.... Rukmini.. beeni Gbogbo wan ni wan saalye igbeyawo wan.. Rukmiṇī saalaye pe " baba mi fe kin je iyawo si Krsna sugbon egbon o gba" Egbon mi fe kin di iyawo fun Śiśupala. Emi o de fe mo si ko lẹta si Krsna, ninu re mo saalaye fun pe mo ti fun ni aye mi" Jo wa be mi kuro ni bi Gege na Krsna si wa gbe mi, O si se mi ni iranse re Eyi je omo alade ... gbogbo iyawo Krsna omo-alade lon je kon se pe omo talaka lon je, sugbon gbogbo wan fe di iranse Krsna Ipo to ye k atele ni yen. pe afe di iranse awon iranse Oluwa Awujo eda eniyan to da niyen Ki gbogbo awon Obirin si di iranse Oko won gege ki gbogbo Okurin di iranse Olorun Asa Orile-ede India ni yen. Kon se pe ki oko ati iyawo di egbe Nkan ton sele ni Orile-ede America ni yen. won fe ki oko ati iyawo d'egbe. Eleyi oun se asa Veda Asa Veda ni wi pe Oko lati di iranse t'okan t'Oluwa(Krsna) geg na iyawo lati di iranse oko re
Nigbati Krsna lo si ilu Hastinapura pelu awon iyawo egberun merindilogun asa awon obirin ni wi pe won man soro laarin ara wan ni pa oko won.. Gege na Draupadi se ibeere lati gbogbo iyawo Krsna Sugbon gbogbo wan ko ... wan ti poju amo a e so wipe o beere lowo awon iyawa t'alakoko kini.... Rukmini.. beeni Gbogbo wan ni wan saalye igbeyawo wan.. Rukmiṇī saalaye pe " baba mi fe kin je iyawo si Krsna sugbon egbon o gba" Egbon mi fe kin di iyawo fun Śiśupala. Emi o de fe mo si ko lẹta si Krsna, ninu re mo saalaye fun pe mo ti fun ni aye mi" Jo wa be mi kuro ni bi Gege na Krsna si wa gbe mi, O si se mi ni iranse re Eyi je omo alade ... gbogbo iyawo Krsna omo-alade lon je kon se pe omo talaka lon je, sugbon gbogbo wan fe di iranse Krsna Ipo to ye k atele ni yen. pe afe di iranse awon iranse Oluwa Awujo eda eniyan to da niyen Ki gbogbo awon Obirin si di iranse Oko won gege ki gbogbo Okurin di iranse Olorun Asa Orile-ede India ni yen. Kon se pe ki oko ati iyawo di egbe Nkan ton sele ni Orile-ede America ni yen. won fe ki oko ati iyawo d'egbe. Eleyi oun se asa Veda Asa Veda ni wi pe Oko lati di iranse t'okan t'Oluwa(Krsna) geg na iyawo lati di iranse oko re.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 11:47, 21 September 2017

Lecture on SB 7.9.24 -- Mayapur, March 2, 1976

Ni Orile-ede yin, opolopo awon ni aaarun iba ki wa ni iyato? gege bi eyan ton s'iṣẹ oogun, kilode ten fi so wi pe aarun da ju ikeji lo? ko si iyato larin aarun. Eyin so wi pe ani aarun iba, sugbon ko ba ti da boba je pe syphilis la ni. rara. gege, boya Brahma tabi kokoro, aarun wa ni wi pe afe di Oga Krsna de ti wa lati fi ipaari si aarun yi Asiwere, ogo ko lo je, iranse ni ye. Teriba fun mi. iwosan aarun yin leleyi ti awa ba si gba pe awa o fe d'oga mo, āra nāre bapa iwosan ta gbudo gba ni yen.

Nitorina Caitanya Mahāprabhu wi pe, gege bi Prahlāda Mahārāja ti so nija bhṛtya-pārśvam: (SB 7.9.24) E fi mi se iranse to kere ju laarin awon iranse yin nkan na ni Caitanya Mahāprabhu so, gopī-bhartur pada-kamalayor dāsa-dāsa-anudāsaḥ (CC Madhya 13.80). Bakanna egbe Krsna wa yi itumu re ni wi pe agbudo gbagbe eto pe afe di Oga Agudo ko lati di iranse Oluwa Sugbon iranse ni kan ko, agbudo di iransi si awon iranse Oluwa Nitorina Prahlāda Mahārāja so wi pe, O si ti ye mi pe agbudo fi gbogbo iranu pe afe di Oga si le Baba temi na seto lati di Oga. Ko si iwuolo pe afe di Oga Te ba fe fun mi ni ibukun, e se mi ni iranse yin Ibukun to dara leleyi je gege na eyan to ti ko lati di iranse Oluwa, eni na ti se aseyori Nitorina Caitanya Mahāprabhu so wi pe, tṛṇād api sunīcena taror api sahiṣṇunā. Iranse ni lati faramo nkn to po Igbami Oga wa le beere nkan to po, iru nkan bayi le di isoro fun iranse sugbon o gbudo faramo. Itesiwaju ni yen Ni Orile-ede India , ti eyan ba fe gbe iyawo Asa lo je ni be Iya re a si bi leere," Omo mi ibo ni won lo? Idaaun re ni pe " mama mi mo fe lo gbe iranse kan wa fun yin" Asa to wa ni yen " Mama, mo fe lo gbe iranse kan wa fun yin" itumo yen ni wi pe " iyawo mi, aya yin lo je, o ma se ise fun yin gege bi iranse" Asa Veda ni eyi je.