YO/Prabhupada 0220 - Nkankanna pelu Oluwa ni gbogbo awon eda: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0220 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1972 Category:YO-Quotes - Ar...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 6: Line 6:
[[Category:YO-Quotes - in France]]
[[Category:YO-Quotes - in France]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0219 - Efi ironu iranu yi si le, pe efe d'oga|0219|YO/Prabhupada 0221 - Awon Mayavadis, wan rope wanti di nkankanna pelu Olorun|0221}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 14: Line 17:

<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|UKzOk_R72sY|Every Living Entity is Part and Parcel of God<br />- Prabhupāda 0220}}
{{youtube_right|UKzOk_R72sY|Nkankanna pelu Oluwa ni gbogbo awon eda<br />- Prabhupāda 0220}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/720720AR.PAR_clip.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/720720AR.PAR_clip.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 26: Line 29:

<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Omo-okurin to kẹkọọ le se iyato laarin AJa ati alufaa, nitoripe aye re ti ya si mimo Nitori awon nkan ton se tele wan ti ni ara to yato, sugbon emi kanna lo wa ninu gbogbo wan Gege na nitoripe asi wa ninu aye yi, iyato pe enikan ni ara awon Orilde-ede India ma wa so okan wa Okurin geesi ni yen, Orile-ede America lo ti wa, aja... iwoye ile aye yi ni yen ti awa ma ya aye si mimo, a leri pe gbogbo awon eda se nkanna pelu Olorun gege bi Iwe mimo Bhagavad-gītā se wi: mām evāṁśa jīva-bhūta gbogbo eda se nkanna pelu Olorun Ni le aye ta wa yi iwonba awon eda to Irinwo-Oke , sugbon gbogbo wan lo ni aso to yato Gege bi eyin te walati Orile-ede ton so èdè faransé, aso ten ma wo yato si aso ti awon lati Orile-ede Geesi ma wo. Sugbon aso na o si ni iwulo bi eyan to wa ninu aso na gege na ara ti ni yi o si wulo Antavanta ime dehā nityasyoktāḥ śarīriṇaḥ ([[Vanisource:BG 2.18|BG 2.18]]), sugbon ara-ẹda si ni ipaari sugbon emi to wa ninu ara-ẹda ko si ni'paari Nitorina igbese ara-ẹda wa lati le mo nipa emi tio nipaari.  
Omo-okurin to kẹkọọ le se iyato laarin AJa ati alufaa, nitoripe aye re ti ya si mimo Nitori awon nkan ton se tele wan ti ni ara to yato, sugbon emi kanna lo wa ninu gbogbo wan Gege na nitoripe asi wa ninu aye yi, iyato pe enikan ni ara awon Orilde-ede India ma wa so okan wa Okurin geesi ni yen, Orile-ede America lo ti wa, aja... iwoye ile aye yi ni yen ti awa ma ya aye si mimo, a leri pe gbogbo awon eda se nkanna pelu Olorun gege bi Iwe mimo Bhagavad-gītā se wi: mām evāṁśa jīva-bhūta gbogbo eda se nkanna pelu Olorun Ni le aye ta wa yi iwonba awon eda to Irinwo-Oke , sugbon gbogbo wan lo ni aso to yato Gege bi eyin te walati Orile-ede ton so èdè faransé, aso ten ma wo yato si aso ti awon lati Orile-ede Geesi ma wo. Sugbon aso na o si ni iwulo bi eyan to wa ninu aso na gege na ara ti ni yi o si wulo Antavanta ime dehā nityasyoktāḥ śarīriṇaḥ ([[Vanisource:BG 2.18 (1972)|BG 2.18]]), sugbon ara-ẹda si ni ipaari sugbon emi to wa ninu ara-ẹda ko si ni'paari Nitorina igbese ara-ẹda wa lati le mo nipa emi tio nipaari.  

Sugbon niroju, ile-eko wa ni isin won si gbe okan le ara-eda to si ni'paari imoye Krsna (Olorun) wa fun kiko ipo emi Gege na egbe nipa eto emi ni awa ti da, kon se egbe ti'joba, tabi egbe fun awujo awon eyan gbogbo awan egbe yi gbokanle ara-eda to si ni'paari, sugbon ti wa gbokan le emi Ti awon ba korin Hare Krsna yi, okan wan asi ya si mimo, lehin na gbogbo wan a ya si ipo mimo Gege bi egbe wa , awon lati orisirisi Ilu, ati Orile-ede lo wa ni be sugbon wan o ronu mo nipa ilu, tabi esin wan Gbogbo wan ti mo pe wan se ara kan pelu Oluwa ti awa ba ti de ipò yi, ta de gba ise Oluwa s'okan lehin na lale gba ominira.  

Gege na egbe wa yi egbe to se pataki ni ko de fi be rorun lati saalaye gbogbo nkan ti awan se ninu egeb wa ni iseju kekekre ta ni sugbon te ba fe ni oye nipa wa, e le gba Bí a tií kàn síni tawa boya lati lẹta, tabi lati iwe wa, tabi ke si wa si odo wa eyikeyi teba fe, aye yin ma ya si mimo Awa o kin se isasoto pe " orile India leleyi, Orile-ede Geesi ni yi, tabi Orile-ede Africa ni eyi" Awa mo pe gbogbo eda, pelu awon eranko ẹyẹ, eranko ènìà, igi, kokoro, - ara kana lon je pelu Oluwa
Gege na egbe wa yi egbe to se pataki ni ko de fi be rorun lati saalaye gbogbo nkan ti awan se ninu egeb wa ni iseju kekekre ta ni sugbon te ba fe ni oye nipa wa, e le gba Bí a tií kàn síni tawa boya lati lẹta, tabi lati iwe wa, tabi ke si wa si odo wa eyikeyi teba fe, aye yin ma ya si mimo Awa o kin se isasoto pe " orile India leleyi, Orile-ede Geesi ni yi, tabi Orile-ede Africa ni eyi" Awa mo pe gbogbo eda, pelu awon eranko ẹyẹ, eranko ènìà, igi, kokoro, - ara kana lon je pelu Oluwa.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 23:38, 13 June 2018

Arrival Lecture -- Paris, July 20, 1972

Omo-okurin to kẹkọọ le se iyato laarin AJa ati alufaa, nitoripe aye re ti ya si mimo Nitori awon nkan ton se tele wan ti ni ara to yato, sugbon emi kanna lo wa ninu gbogbo wan Gege na nitoripe asi wa ninu aye yi, iyato pe enikan ni ara awon Orilde-ede India ma wa so okan wa Okurin geesi ni yen, Orile-ede America lo ti wa, aja... iwoye ile aye yi ni yen ti awa ma ya aye si mimo, a leri pe gbogbo awon eda se nkanna pelu Olorun gege bi Iwe mimo Bhagavad-gītā se wi: mām evāṁśa jīva-bhūta gbogbo eda se nkanna pelu Olorun Ni le aye ta wa yi iwonba awon eda to Irinwo-Oke , sugbon gbogbo wan lo ni aso to yato Gege bi eyin te walati Orile-ede ton so èdè faransé, aso ten ma wo yato si aso ti awon lati Orile-ede Geesi ma wo. Sugbon aso na o si ni iwulo bi eyan to wa ninu aso na gege na ara ti ni yi o si wulo Antavanta ime dehā nityasyoktāḥ śarīriṇaḥ (BG 2.18), sugbon ara-ẹda si ni ipaari sugbon emi to wa ninu ara-ẹda ko si ni'paari Nitorina igbese ara-ẹda wa lati le mo nipa emi tio nipaari.