YO/Prabhupada 0252 - Asi rope ale se nkan to wu wa: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0252 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1973 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 5: Line 5:
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:YO-Quotes - Lectures, Bhagavad-gita As It Is]]
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
[[Category:YO-Quotes - in United Kingdom]]
[[Category:Yoruba Language]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0251 - Alabasepo t'ayeraye ni awon gopi je si Krishna|0251|YO/Prabhupada 0253 - Wan si salaaye Idunnu gidi ninu iwe Bhagavad-gita|0253}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 15: Line 17:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|vM_sJWDK2x0|We are Thinking That we are Independent - Prabhupada 0252}}
{{youtube_right|vM_sJWDK2x0|Asi rope ale se nkan to wu wa - Prabhupāda 0252}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/wiki/File:730806BG.LON_clip5.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/730806BG.LON_clip5.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 27: Line 29:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
gbogbo awon eyan ile-aye yi, asiwere ni wan je. Wan sin s'eto ile-aye yi Wan ro pe ton ba s'eto ile-aye yi wan ni idunnu. Ko le sese Durāśayā ye.. ati Ijoba wan Andhā yathāndhair upanīyamānās te 'pīśa-tantryam uru-dāmni baddhāḥ ([[Vanisource:SB 7.5.31|SB 7.5.31]]). Wan ti fi okun so gbogbo wa lat'owo de ese, sugbon arope a le se nkan to wun wa asi rope a ni iminira Awon oni sayensi, wan fe ni nkan se pelu Olorun mo. Kole sese ile-aye ti di wa mu aṣoju krsna ni ile-aye yi Mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ sūyate sa-carācaram ([[Vanisource:BG 9.10|BG 9.10]]). Prakṛteḥ kriyamāṇāni guṇair karmāṇi sarvaśaḥ ([[Vanisource:BG 3.27|BG 3.27]]). Gbogbo si ni idamu bi Arjuna. awa o mo nkan tale se Sugbon taba ni ofi pe, "agbudo se gbogbo nkan fun Krsna..." E gba ilana lati Krsna, tabi awon aṣoju krsna kode si karma-bandhanaḥ. Karmāṇi nirdaheti kintu ca bhakti-bhājām (Bs. 5.54). bibeko, agbudo jiya gbogbo nkan tati se. Ko si ba sele jade Idamu na de wa " Se kin jagun, tabi kin ma ja" beeni, Agbudo jagun fun krsna. Nigbayen lo ma da Kāmaḥ kṛṣṇa-karmārpane. gege bi Hanumān. O jagun fun Ramacandra. Ko si jagunfun ara re lori àsìá Arjuna aami hanuman si wan be O mo be Jagunjagun alagbara ni Hanuman, O si ba Ravana ja, sugbon fun ara re ko Idi fun ija ni lati gba Sita pada lowo Ravana O si pa gbogbo ebi Ravana, lati le mu Sita jade lo ba Ramacandra ilana-iṣe awon elesin niyen ilana-iṣe ravana ni lati gba Sita fun igbadun ara re ilana-iṣe Ravana niyan, Sugbon ti Hanuman ni lati da Sita pada si Rama Laksmi ni Itumo Sita ohun-ini Narayan tabi Olorun ni itumo Laksmi Gbogbo awon eyan ni ile-aye yi fe gbadun ohun-ini Olorun Sugbon awa o l'agbara lati ba awon eya bi Ravana ja Awa o l'agbara tobe, gege na ati atoro owo je " Ejo, Okurin to rewa le je, Efunwa ni nkan" Nitoripe, ema ba ile-aye yin je teba toju ohun-ini Olorun Sugbon teba di elesin ninu egbe wa, Olorun a si fun in ni igbala Ilana-ise wa niyen. Atoro owo je ko ni wa. sugbon ilana -ise lo je Awa o l'agbara lati ba Ravana ja, bibeko awa o bati fi ija gba gbogbo owo ton ni Ko le sese. Awa o l'agbara. Nitorina lase fe lo ogbon atoro-owo-je. Ese pupo
Gbogbo awon eyan ile-aye yi, asiwere ni wan je. Wan sin s'eto ile-aye yi Wan ro pe ton ba s'eto ile-aye yi wan ni idunnu. Ko le sese Durāśayā ye.. ati Ijoba wan Andhā yathāndhair upanīyamānās te 'pīśa-tantryam uru-dāmni baddhāḥ ([[Vanisource:SB 7.5.31|SB 7.5.31]]). Wan ti fi okun so gbogbo wa lat'owo de ese, sugbon arope a le se nkan to wun wa asi rope a ni iminira Awon oni sayensi, wan fe ni nkan se pelu Olorun mo. Kole sese ile-aye ti di wa mu aṣoju krsna ni ile-aye yi Mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ sūyate sa-carācaram ([[Vanisource:BG 9.10 (1972)|BG 9.10]]). Prakṛteḥ kriyamāṇāni guṇair karmāṇi sarvaśaḥ ([[Vanisource:BG 3.27 (1972)|BG 3.27]]). Gbogbo si ni idamu bi Arjuna. awa o mo nkan tale se Sugbon taba ni ofi pe, "agbudo se gbogbo nkan fun Krsna..." E gba ilana lati Krsna, tabi awon aṣoju krsna kode si karma-bandhanaḥ. Karmāṇi nirdaheti kintu ca bhakti-bhājām (Bs. 5.54). bibeko, agbudo jiya gbogbo nkan tati se. Ko si ba sele jade Idamu na de wa " Se kin jagun, tabi kin ma ja" beeni, Agbudo jagun fun krsna. Nigbayen lo ma da Kāmaḥ kṛṣṇa-karmārpane. gege bi Hanumān. O jagun fun Ramacandra. Ko si jagunfun ara re lori àsìá Arjuna aami hanuman si wan be O mo be Jagunjagun alagbara ni Hanuman, O si ba Ravana ja, sugbon fun ara re ko Idi fun ija ni lati gba Sita pada lowo Ravana O si pa gbogbo ebi Ravana, lati le mu Sita jade lo ba Ramacandra ilana-iṣe awon elesin niyen ilana-iṣe ravana ni lati gba Sita fun igbadun ara re ilana-iṣe Ravana niyan, Sugbon ti Hanuman ni lati da Sita pada si Rama Laksmi ni Itumo Sita ohun-ini Narayan tabi Olorun ni itumo Laksmi Gbogbo awon eyan ni ile-aye yi fe gbadun ohun-ini Olorun Sugbon awa o l'agbara lati ba awon eya bi Ravana ja Awa o l'agbara tobe, gege na ati atoro owo je " Ejo, Okurin to rewa le je, Efunwa ni nkan" Nitoripe, ema ba ile-aye yin je teba toju ohun-ini Olorun Sugbon teba di elesin ninu egbe wa, Olorun a si fun in ni igbala Ilana-ise wa niyen. Atoro owo je ko ni wa. sugbon ilana -ise lo je Awa o l'agbara lati ba Ravana ja, bibeko awa o bati fi ija gba gbogbo owo ton ni Ko le sese. Awa o l'agbara. Nitorina lase fe lo ogbon atoro-owo-je. Ese pupo.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 23:43, 13 June 2018



Lecture on BG 2.6 -- London, August 6, 1973

Gbogbo awon eyan ile-aye yi, asiwere ni wan je. Wan sin s'eto ile-aye yi Wan ro pe ton ba s'eto ile-aye yi wan ni idunnu. Ko le sese Durāśayā ye.. ati Ijoba wan Andhā yathāndhair upanīyamānās te 'pīśa-tantryam uru-dāmni baddhāḥ (SB 7.5.31). Wan ti fi okun so gbogbo wa lat'owo de ese, sugbon arope a le se nkan to wun wa asi rope a ni iminira Awon oni sayensi, wan fe ni nkan se pelu Olorun mo. Kole sese ile-aye ti di wa mu aṣoju krsna ni ile-aye yi Mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ sūyate sa-carācaram (BG 9.10). Prakṛteḥ kriyamāṇāni guṇair karmāṇi sarvaśaḥ (BG 3.27). Gbogbo si ni idamu bi Arjuna. awa o mo nkan tale se Sugbon taba ni ofi pe, "agbudo se gbogbo nkan fun Krsna..." E gba ilana lati Krsna, tabi awon aṣoju krsna kode si karma-bandhanaḥ. Karmāṇi nirdaheti kintu ca bhakti-bhājām (Bs. 5.54). bibeko, agbudo jiya gbogbo nkan tati se. Ko si ba sele jade Idamu na de wa " Se kin jagun, tabi kin ma ja" beeni, Agbudo jagun fun krsna. Nigbayen lo ma da Kāmaḥ kṛṣṇa-karmārpane. gege bi Hanumān. O jagun fun Ramacandra. Ko si jagunfun ara re lori àsìá Arjuna aami hanuman si wan be O mo be Jagunjagun alagbara ni Hanuman, O si ba Ravana ja, sugbon fun ara re ko Idi fun ija ni lati gba Sita pada lowo Ravana O si pa gbogbo ebi Ravana, lati le mu Sita jade lo ba Ramacandra ilana-iṣe awon elesin niyen ilana-iṣe ravana ni lati gba Sita fun igbadun ara re ilana-iṣe Ravana niyan, Sugbon ti Hanuman ni lati da Sita pada si Rama Laksmi ni Itumo Sita ohun-ini Narayan tabi Olorun ni itumo Laksmi Gbogbo awon eyan ni ile-aye yi fe gbadun ohun-ini Olorun Sugbon awa o l'agbara lati ba awon eya bi Ravana ja Awa o l'agbara tobe, gege na ati atoro owo je " Ejo, Okurin to rewa le je, Efunwa ni nkan" Nitoripe, ema ba ile-aye yin je teba toju ohun-ini Olorun Sugbon teba di elesin ninu egbe wa, Olorun a si fun in ni igbala Ilana-ise wa niyen. Atoro owo je ko ni wa. sugbon ilana -ise lo je Awa o l'agbara lati ba Ravana ja, bibeko awa o bati fi ija gba gbogbo owo ton ni Ko le sese. Awa o l'agbara. Nitorina lase fe lo ogbon atoro-owo-je. Ese pupo.