YO/Prabhupada 0303 - Transcendental. You Are Beyond: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0303 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1968 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in USA, Seattle]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Seattle]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0302 -Awon eyan oni iwa igboran|0302|YO/Prabhupada 0304 - Maya Cannot Cover the Supreme Whole|0304}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/681002LE.SEA_clip4.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/681002LE.SEA_clip4.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 37: Line 40:
:manasas tu parā buddhir
:manasas tu parā buddhir
:yo buddheḥ paratas tu saḥ
:yo buddheḥ paratas tu saḥ
:([[Vanisource:BG 3.42|BG 3.42]])
:([[Vanisource:BG 3.42 (1972)|BG 3.42]])

Ni alakoko egbudo mowipe iye-ara ni itumo ara wa sugbon teba tesiwaju ema ripe okan wa nibi ti gbogbo ise igbadun wa afi ti okan waba bale, kosi basele rori wo. gege na indriyebhyaḥ paraṁ manaḥ Okan wa si gaju iye-ara wa lo, ogbon wa si gaju okan wa, gege na Emi wa si gaju ogbon wa lo. Egbudo ni oye eleyi. Tesiwaju.

Latest revision as of 23:48, 13 June 2018

Lecture -- Seattle, October 2, 1968

Prabhupāda: Tesiwaju.

Tamāla Kṛṣṇa: "ipo teyin lo gaju"

Prabhupāda: Lo gaju. "Eyin ju bayi lo." Bhagavad-gita ti salaaye:

indriyāṇi parāṇy āhur
indriyebhyaḥ paraṁ manaḥ
manasas tu parā buddhir
yo buddheḥ paratas tu saḥ
(BG 3.42)

Ni alakoko egbudo mowipe iye-ara ni itumo ara wa sugbon teba tesiwaju ema ripe okan wa nibi ti gbogbo ise igbadun wa afi ti okan waba bale, kosi basele rori wo. gege na indriyebhyaḥ paraṁ manaḥ Okan wa si gaju iye-ara wa lo, ogbon wa si gaju okan wa, gege na Emi wa si gaju ogbon wa lo. Egbudo ni oye eleyi. Tesiwaju.

Tamāla Kṛṣṇa: Mimo ni agbara Krsna to gaju, t' aye yi ni agbara re to kehin. Awa wa laarin agbara meejeji, nitorina ni awa se je iwonba die agbara meejeji. Itumo re ni wipe, asepelu agbara Krsna to wa laarin Nkankanna pelu iyato laje si Krsna Nitorrpe Emi laje, kosi yato laarin wa ati Krsna, sugbon nitoripe iwonba kekere to wa lati Krsna laje, iyato wa laarin wa.

Prabhupāda: Oro to wa ni agabara taarin. taṭastha ni itumo agbara taarin ni ede Sanskrit ibi ti ile paari si, l'okun ti bere. Ile bayi wa laarin nigbami teba losi Okun ele ri ile die nigbami omi lebo ile na tabi ko si wa laisi omi. Gege na emi ni gbogbo je, nkankanna pelu Olorun sugbon nigbami māyā le diwamu, nigbami ale tu ka lowo re Nitorina aarin ni ipo wa. taba ba ni oye ipo wa.. Gege bi apeere ti ko fun yin, ni eti -okun eleri ile toje pe nigbami omi le bo, toba de ya omi na ma kuro gege na, māyā le diwamu nigbami. agbara kekere, nigbami ale tu ka. agbudo tu ka lowo re gege bi ile to si kale, ko le s'omi nibe. teba kuro leti-okun kole s'omi mo. ile lasan lowa. gege na, teba fi nkan aye yi sile tewa si ile imoye awon nkan mimi, tabi imoye Krsna, nigbana lema ni igbala. sugbon teba duro si ipo aarin tewa, nigbami maya le dabo wa, nigbamo a le tka. ipo wa niyen.