YO/Prabhupada 0485 - Any Pastimes made by Krishna, that is Observed in Ceremonial Form by the Devotees

Revision as of 23:42, 22 July 2015 by Rishab (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0485 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1968 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

Lecture -- Seattle, October 18, 1968

Alejo: Mefe ke salaaye nipa orisun ati itumo nkan tonpe ni ayeye oko Jagannatha.

Prabhupāda: Itumo ayeye Jagannātha yi niwipe, nigbati Krsna kuro ni Vrndavana. Krsna si dagba si ile Nanda Maharaja. Sugbon nigbato dagba, odun 16, osi pada loba baba re, Vasudeva, won si kuro ni Vrndavana, Krsna ati Balarama, awon omo-okurin mejeji, Dvaraka nijoba won. Beena ni Kurusetra - dharma-ksetra ni Kurusetra, irin ajo t'esin - oni ati osupa to sele, awon eyan to po lati gbogbo ilu India lowa lati we nibe. Beena, Krsna ti Balarama ati omo obirin aburo won Subhadra, awon na wa ninu ewu oba, pelu awon jagun jagun to po... gege bi oba. beena awon olugbe Vrndavana yi won pade Krsna, nipataki awon gopi, won ri Krsna, won si bere sini sukun pe " Krsna, o wa nibi, awa na si wa sibi, sugbon ibi yi yato. Vrndavana ko leleyi." Beena itan na po gan bi won se bere sini sukun, bi Krsna se gbiyanju lati fokan won bale. Awon olugbe Vrndavana si bere sini ronu nipa bi Krsna se ti fi won sile ni Beena.. nigbati Krsna si gun oko t'elesin, nkan ton pe ni Ratha- yatra niyen. itan akoole Ratha-yatra niyen. Beena awon akoko idaraya ti Krsna, awon olufokansi le fi s'ayeye. Ratha-yatra niyen.