YO/Prabhupada 0602 - The Father is the Leader of the Family: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0602 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1974 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 7: Line 7:
[[Category:YO-Quotes - in USA, Hawaii]]
[[Category:YO-Quotes - in USA, Hawaii]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 0601 - Caitya-guru means Who gives Conscience and Knowledge from Within|0601|YO/Prabhupada 0603 - This Mrdanga will go Home to Home|0603}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 19: Line 22:

<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>http://vaniquotes.org/w/images/740117SB.HAW_clip.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/740117SB.HAW_clip.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->

Line 29: Line 32:
Mo bi Alamodaju Kotovsky ni ibeere yi. Mo bere lowo re " Kini iyaato imoye communist teni ati imoye Krsna wa? Eyin gbodo gba olori kan, Lenin tabi Stalin, awa na ti mu olori kan, tabi Oluwa, Krsna. Eyin se nkan ti Lenin tabi Stalin tabi Molotov baso tabi eyi tabi toun. Awa sin tele imoye ati awon itosona Krsna. Beena lori ofin yi, nibo ni iyato na wa? Kosi iyato kankan." Beena alamodaju yi kole daaun. Eyin o le sise lai jepe enikan sofun yin nkan tema se. Oye ke gba bee.

Beena ofin iseda niyen. Beena nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13). Lehin na kilode teyin o se fe gba olori to gaju? Agbodo gba olori kan lati funwa ni ilana. Kolese se pe awa o le gbe laisi ijoba. Kolese se. Se apa oselu, tabi ile eko, tabi egbe kankan, wa ton sise laisi olori tabi eni ton p'ase? Seyin le fi apeere kan fihan mi ninu gbogbo agbaye? Se apeere kankan wa? Rara. gege bi egbe wa enikan ti lo,sugbon oti gba Gaurasundara tabi Siddha-svarūpa Mahārāja bi olori re. Ofin na wa nibe, eyin gbodo gba olori kan. Sugbon ogbon ori yeko sofun yin iru olori wo le fe. Imoye niyen je. Agbodo gba ipo iranse lati sise fun eyan. Beena ogbon to wa ni pe " Talo yekin gba?" Ibi t'ogbon na ti wa niyen: " Iru olori wo loye kin gba?" Beena ofin wa ni wipe oye ka gba Krsna bi olori wa, nitoripe Kṛṣṇa so ninu Bhagavad-gītā, mattaḥ parataraṁ nānyat kiñcid asti dhanañjaya ([[Vanisource:BG 7.7|BG 7.7]]). Kṛṣṇa ni olori to gaju. Eko bahū... nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām eko yo bahūnāṁ vidadhāti (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13). Gege bi baba wa. Baba ni olori ile. Kilode toje pe baba ni olori? Nitoripe oun lon pa owo, oun lon toju awon omode, iyawo, iranse ati ile-ise re: beena nitorina lose je olori ile. Beena, teyin ba Olori Nixon bi olori orile ede yin nitoripe ninu asiko ewu on funyin ni ilaana nkan tema se, ni asiko alaafia on fun yin ni itosona. On sise ni gbogbo'gba lti jeki inu yin dun, lati jeke ni ifokonbale. Ise Olori niyen. Bibeko, kilode teyin se dibo fun lati je Olori? Ele gbe aye yin laisi Olori kankan, sugbon egbodo se.  
Beena ofin iseda niyen. Beena nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13). Lehin na kilode teyin o se fe gba olori to gaju? Agbodo gba olori kan lati funwa ni ilana. Kolese se pe awa o le gbe laisi ijoba. Kolese se. Se apa oselu, tabi ile eko, tabi egbe kankan, wa ton sise laisi olori tabi eni ton p'ase? Seyin le fi apeere kan fihan mi ninu gbogbo agbaye? Se apeere kankan wa? Rara. gege bi egbe wa enikan ti lo,sugbon oti gba Gaurasundara tabi Siddha-svarūpa Mahārāja bi olori re. Ofin na wa nibe, eyin gbodo gba olori kan. Sugbon ogbon ori yeko sofun yin iru olori wo le fe. Imoye niyen je. Agbodo gba ipo iranse lati sise fun eyan. Beena ogbon to wa ni pe " Talo yekin gba?" Ibi t'ogbon na ti wa niyen: " Iru olori wo loye kin gba?" Beena ofin wa ni wipe oye ka gba Krsna bi olori wa, nitoripe Kṛṣṇa so ninu Bhagavad-gītā, mattaḥ parataraṁ nānyat kiñcid asti dhanañjaya ([[Vanisource:BG 7.7 (1972)|BG 7.7]]). Kṛṣṇa ni olori to gaju. Eko bahū... nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām eko yo bahūnāṁ vidadhāti (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13). Gege bi baba wa. Baba ni olori ile. Kilode toje pe baba ni olori? Nitoripe oun lon pa owo, oun lon toju awon omode, iyawo, iranse ati ile-ise re: beena nitorina lose je olori ile. Beena, teyin ba Olori Nixon bi olori orile ede yin nitoripe ninu asiko ewu on funyin ni ilaana nkan tema se, ni asiko alaafia on fun yin ni itosona. On sise ni gbogbo'gba lti jeki inu yin dun, lati jeke ni ifokonbale. Ise Olori niyen. Bibeko, kilode teyin se dibo fun lati je Olori? Ele gbe aye yin laisi Olori kankan, sugbon egbodo se.  

Beena Veda sowipe, nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām. Eda meji lowa. Nitya ni awon meejeji. Tayeraye nitumo Nitya. eda to wa laye nitumo ceana. Beena nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām. Ijuwe Oluwa niyen, pe bi eyan bi eyin ati emi na l'Oluwa je. Eda loun na je. teyin ba wo Krsna iyato wo lowa laarin eyin ati Krsna? O ni owo meji, eyin na l'owo meji. Oni ori kan; eyin na ni ori kan. O ni ese meji. eyin na l'ese meji. Ele toju awon maalu keba won sere; Krsna na. Sugbon iyato si wa nibe. kini iyato na? Eko yo bahūnāṁ vidadhāti kāmān. Pe Krsna kan yi, botilejepe o jowa gan lona orisirsi, sugbon iyato kan si wa nibe - Oun lon toju gbogbo wa, awa lon toju. Oun l'olori. Ti Krsna o ba peese ounje, eyin o le jeun. Ti Krsna o ba fun yin ni epo ero, lehin na eyin o le wa moto. Beena eko bahūnāṁ yo vidadhāti. ounkoun teba ni ninu aye yi - asi ni ilo fun awon nkan to po - sugbon eka lon peese funwa, eda kan soso yi. Iyatoo to wa niyen. Awa o le toju ebi kekere tani gan, agbara wa kere gan. L'asiko tawayi, awon okurin o fe se igbeyawo nitoripe kole toju ebi, iyawo ati awon omode. Kole toju won, ebi tojepe awon eyan merin si marun nikan lowa.

<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:16, 14 June 2018

Lecture on SB 1.16.21 -- Hawaii, January 17, 1974

Mo bi Alamodaju Kotovsky ni ibeere yi. Mo bere lowo re " Kini iyaato imoye communist teni ati imoye Krsna wa? Eyin gbodo gba olori kan, Lenin tabi Stalin, awa na ti mu olori kan, tabi Oluwa, Krsna. Eyin se nkan ti Lenin tabi Stalin tabi Molotov baso tabi eyi tabi toun. Awa sin tele imoye ati awon itosona Krsna. Beena lori ofin yi, nibo ni iyato na wa? Kosi iyato kankan." Beena alamodaju yi kole daaun. Eyin o le sise lai jepe enikan sofun yin nkan tema se. Oye ke gba bee.

Beena ofin iseda niyen. Beena nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13). Lehin na kilode teyin o se fe gba olori to gaju? Agbodo gba olori kan lati funwa ni ilana. Kolese se pe awa o le gbe laisi ijoba. Kolese se. Se apa oselu, tabi ile eko, tabi egbe kankan, wa ton sise laisi olori tabi eni ton p'ase? Seyin le fi apeere kan fihan mi ninu gbogbo agbaye? Se apeere kankan wa? Rara. gege bi egbe wa enikan ti lo,sugbon oti gba Gaurasundara tabi Siddha-svarūpa Mahārāja bi olori re. Ofin na wa nibe, eyin gbodo gba olori kan. Sugbon ogbon ori yeko sofun yin iru olori wo le fe. Imoye niyen je. Agbodo gba ipo iranse lati sise fun eyan. Beena ogbon to wa ni pe " Talo yekin gba?" Ibi t'ogbon na ti wa niyen: " Iru olori wo loye kin gba?" Beena ofin wa ni wipe oye ka gba Krsna bi olori wa, nitoripe Kṛṣṇa so ninu Bhagavad-gītā, mattaḥ parataraṁ nānyat kiñcid asti dhanañjaya (BG 7.7). Kṛṣṇa ni olori to gaju. Eko bahū... nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām eko yo bahūnāṁ vidadhāti (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13). Gege bi baba wa. Baba ni olori ile. Kilode toje pe baba ni olori? Nitoripe oun lon pa owo, oun lon toju awon omode, iyawo, iranse ati ile-ise re: beena nitorina lose je olori ile. Beena, teyin ba Olori Nixon bi olori orile ede yin nitoripe ninu asiko ewu on funyin ni ilaana nkan tema se, ni asiko alaafia on fun yin ni itosona. On sise ni gbogbo'gba lti jeki inu yin dun, lati jeke ni ifokonbale. Ise Olori niyen. Bibeko, kilode teyin se dibo fun lati je Olori? Ele gbe aye yin laisi Olori kankan, sugbon egbodo se.