YO/Prabhupada 0028 - Olorun ni Buddha



Lecture on Sri Isopanisad, Mantra 1 -- Los Angeles, May 3, 1970

Gargamuni: (Nka iwe:) "O si tun wa ni aise dede lati ro wi pe ti a ba di eniti ki jèran lasan eniyan le gba ara re sile ninu yiya awon ofin adanida. Awon ewe na ni emi. Nkan elemi kan a se ounje fun imiran, ofin isebanye ni yi. A ko gbodo ni igberaga nitoripe a je eniti ki nje nkan ki nkan to lemi rara. Nkan ti o se koko ni pe lati mo Olorun. Awon eranko o ni idagbasoke okan lati da Olorun mo, sugbon omo eda eniyan..."

Prabhupāda: Iyen ni oju oro. Gege bi awon omo egbe Buddha, ti a npe ni Buddhists, awon na ki njeran. Gege bi ilana awon Buddhists... L'ode oni gbogbo nkan ti di bajé, sugbon ikèdè Oluwa Buddha se lati fe ki awon alailero ti lé fi pi-pa eranko si lé. Ahiṁsā paramo dharma. Won se alaaye ti wi wa Oluwa Buddha ninu Srimad-Bhagavatam ati awon iwe vediki miran. Sura-dviṣām. O wa lati wa tan awon èlèsu. Awon èlèsu... O se iru ofin ti o file tan awon élésu jé. Bawo lo se tan won jé? Awon élésu, won lodisi Olorun. Won ko ni igbagbo ninu Olorun. Nitori eyi Oluwa Buddha se ikèdè, "Béé ni, ko si Olorun. Sugbon nkan ti mo ba so, e gbodo té lè. "Béé ni, Alagba" Sugbon Olorun ni. "Bi o se tan won ni yi. Béé ni. Won o gbagbo ninu Olorun, subgon won gba Buddha gbo, Buddha si je Olorun. Keśava-dhṛta-buddha-śarīra jaya jagadīśa hare. Nitorina eyi ni iyatô laarin èlèsu ati onigbagbô. Onigbagbo ri bi Olorun, Kesava, se ntan awon alailero eniyan je Eyi ye onigbagbo. Sugbon awon élésu, nro wipe, "Ah, a ni olori to dara. Ko gba Olorun gbo." (Erin) Se eti ri ba yen? Sammohāya sura-dviṣām (SB 1.3.24). Gbolo oro gan ni ede Sanskrit wa ninu Śrīmad-Bhāgavatam. Eti ti ri, awon ti o ti ka: sammohāya, fun ati bo ni loju molé sura-dviṣām. Sura-dviṣām tumo si awon ti won njowu awon Vaishnava. Awon alaini igbagbo, èlèsu, won ma nsè ojowu awon onigbagbo ni gbogbo igba. Iyen ni ofin isebanye. Se e ri baba yi. Baba di ota ômô re olodun marun. Kini ésé ré? O jé oni gbagbô. Ko ju yen lô. Omo alai-lésé. Nitoripe o jé lasan, a ni pe, okan re faa si pipe mantra Hare Krishna. Baba ré gangan, wa di ota nla: "Pa ômôdè yi." Nitorina si baba kan ba le di ôta, ki a ma wulé so ti awon miran. Nitori idi eyi e gbodo lero ni gbogbo igba wipe wéré ti é ba di onigbagbo, gbogbo aye ni o gbogun ti yin. Ko ju ba yen lô. Sugbon é gbôdô ba won sé, nitoripe a ti pe yin gégé bi ojisé Olorun. Isè yin ni lati laa won loye. Nitorina éyin ko le jé. Gégé bi Oluwa Nityananda, Won se lèsè, sugbon sibé sibé O gba Jagai ati Madhai silé. Eyi gbôdô jé ilana yin. Ni igba miran a gbôdô tan yan je, ni igba miran a o ni ipa lara- orisi risi nkan. Ero kan soso ni bi a sè lè mu awon eniyan wa gba isôkan Olorun. Isé wa ni yén. Ni gbogbo ona ti a le gba, a gbôdô mu won wa si isokan Olorun, ni ôna kôna.