YO/Prabhupada 0125 - Awujo eyan nibi ti baje



Lecture on SB 1.5.23 -- Vrndavana, August 4, 1974

Gbogbo awon eniyan ti won kere ju awon śūdra. Pañcamas ni won npe won, ni ipo karun. Ipo kini brāhmaṇa, ipo keji kṣatriya, ipo keta vaiśya, ipo kerin śūdra, awon iyoku -lori ipo karun lonwa. Caṇḍāla ni won npe won. Awon a- gbalẹ, awon a-tun-bata-se, ati awon ...ti won kere ju. Sibe ni orile-ede India awon eniyan onipo Karun yi, won njeran, elede, nigba miran maalu pelu. . Nisin iwa bayi ti d'asa. O si n je eniyan onipo kini. E ma wo. Ohun ti o je owo awọn - eniyan onipo karun, ti wa di owo ti ki-la ti npe awon oloselu. Ṣe e ti ri. Nitorina ti awon eniyan onipo karun ba n ṣàkóso lori yin - nigbana bawo ni eyin se le ni idunnu? Ìyẹn ko ṣee ṣe. Bawo ni ifokanbale awujo kankan se le wa nibẹ ? Iyen ko le ṣee ṣe. Sugbon ani awọn - eniyan onipo karun paapa , o le wa ni yà si mimo nipa egbe ifokansin Olorun. Nitorina ilo nla wa nibẹ fun egbe yi. nitoripe lasiko ti awa yi, ko si awon eniyan lori ipo kini tabi keji mo. Boya ipo keta, ipo karun, ipo kefa,.. Sugbon won le se yasi mimo. Ìyẹn ni pé ... Ilana kan soso ni egbe ifokansin Olorun yi. Gbogbo eniyan lo le di mimo. Māṁ hi pārtha vyapāśritya ye 'pi syuḥ pāpa-yonayaḥ (BG 9.32). Wọn npe won ni Papa-yoni, ti won bí ninu ipo irele-, ìdílé ẹlẹṣẹ . Papa-yoni. Kṛṣṇa sowipe, ye 'pi syuḥ pāpa-yonayaḥ. Ma še yonu Iru Papa-yoni ti o je. Māṁ hi pārtha vyapā... " Ti o ba gba àbo Mi, nigbana .. Aabo na le se ri gba nitori asoju Olorun asoju nse ikéde .

Nitorina ko si isowon. Kan nìkan ni lati gba àbo Rẹ. Ko ju yẹn lo. O kan da bi ise pataki Caitanya Mahāprabhu ni lati ṣẹda awọn ti won nse ikéde yi. "Ẹ lọ si ibi gbogbo." "Āmāra ājñāya guru hañā tāra' ei deśa (CC Madhya 7.128)." "Ẹ jade lọ." Be ni O se ma nfi Nityānanda Prabhu, Haridāsa Ṭhākura ranṣẹ ati, lati se ikéde , "Jọwọ képe Hare Krishna. Jọwọ képe Hare Krishna. Jọwọ se jowo re fun Olorun." Bákan náà awọn eniyan wa lori ita. Nityānanda Prabhu ati Haridāsa Ṭhākura si ri on, nwọn si beere, "Kí ni ijọ enia yi?" Rara, awon arakunrin meji Jagāi ati Mādhāi ni won wa nibẹ, won si je onijangbon gidigidi. ọmùti ni won, won nko obinrin kiri ati pe ajeran niwon, wọn si wa n ṣẹda gbogbo ni wahala. " Nítorí náà, Nityānanda Prabhu se pinnu lẹsẹkẹsẹ , "Kilode ti a ko ni gbà awọn wọnyi sile l'akọkọ? Nigbana ni orukọ Oluwa mi yio o wa logo. Orukọ Oluwa Chaitanya Mahaprabhu yio o wa lógo. "

Ati yin Oluko, paramparā l'ogo ni iṣowo awon akeko. Mo yìn oluko igbala ẹmí mi , iwo yìn ti rẹ . Ti a ba kan ṣe eyi, yìn logo, nigba na ni Olorun O se wa logo. Iyen je ipinnu Nityānanda Prabhu, wipe "Kilode ti a ko ni gbà awọn alabuuku eda wọnyi silẹ l'akọkọ?" Nitori Oluwa Chaitanya Mahāprabhu so kale lati orun wa lati gbà awọn emi alabuku silẹ . Ati ni ... Bee ni kò si iwonsi awon emi alabuku ní igbà aye wa yi

patita-pāvana-hetu tava avatāra
mo sama patita prabhu nā pāibe āra

Narottama dāsa Ṭhākura ti wa n fi ara rẹ si ẹsẹ o'lojuoro Oluwa Chaitanya Mahāprabhu, "Oluwa mi, eyin tiwa lati fun awon elese nigbala. sugbon elese to tobiju mi lo, eyin o leri. Gege na emi loyeke fun nigbala nialakoko." Mo sama patita prabhu nā pāibe āra. "Awon elese to buruju leyin fe fun nigbala, sugbon elese tojumi lo kosi. Edakun egbami la".

Ninu asiko Kali-yuga tawayi, awon eyan jiya. Elese nigbogbo wan, gbogbo wan lon jeran, wan moti, awon okurin lati ipo karun, kefa. Lati ipo aye to kereju lonti wa sugbon wansi ni igberaga to po gan. Nitorina Guru Mahārāja man sowipe "Ko s'okurin jeje tole gbe nibi. Awujo eyan nibi ti baje". Sugbon awa si l'anfaani ati sise fun Caitanya Mahāprabhu. Anfaani ati sise fun Caitanya Mahāprabhu si wa nitoripe awujo eyan nisin ti baje gan. Nitoripe Śrī Caitanya Mahāprabhu tiwa lati fun awon elese wanyi nigbala. Eyinna tini alábàpàdé ati sise fun Śrī Caitanya Mahāprabhu nitoripe osi fe fun gbogbo awon elese nigbala. Nkan ti Kṛṣṇa fe niyen. Yadā yadā hi glānir bhavati bhārata, dharmasya glānir bhavati bhārata. Ise Olorun n'lo bayi. Osi l'anfaani ati fun awon asiwere wanyi nigbala, gbogbo wan ton jiya ninu ile-aye yi. Krsna sini anfaani alti fun gbogbo wa nigbala. Nigbami awa fun ara re, nigbami asi wa bi elesin nigbami aran awon iranse re, Omo-Okurin re.

Ati fun awon elese yi nigbala ni anfaani Kṛṣṇa. Awon yoginīs ati yoginaḥ, awon lonse irin ajo gbogbo agbaye. asiko ojo nikan loni isimi. Konsepe ka jeun ka sun ni asiko iyoko. Rara beko. Ni osu merin t'ojo maro, ko rorun rara lati se irin-ajo. Nigbana ni osu merin t'ojo maro, ibikibi ton bawa, ti awon ba sise fun wan wanle ni'gbala na. Kosejo pe wanfe se iwaau, wanni lati fun awon eyan ni aye ati sise, lehin na awon else wanyi leni igbala na. sugbon egbudo ni agbara ati fun awon eyan ni'se. Bibeko ti awon eyan ba sise funyi, ema lo si Orun apaadi teyin bani ipo toda ninu emi, teba jeki awon eyan sise fun yin wanle ni igbala bayi. Kosejo pe wanfe ni oye imoye wa. Awon Elesin gbudo daju bayi. nitorina taba ri awon elesin agbudo teriba kasi fowo kan ese wa Ilana towa niyen, nitoripe taba fow kan ese wan Mahat-pāda-rajo-'bhiṣekam. teyan bani ipo toga ninu aye mimo awon eyan le gb'aye lati fowo kan ese onitoun, lehin na enina ledi elesin. Boseri niyen