YO/Prabhupada 0135 - Kosi besele siro ojo-ori Veda



Morning Walk -- October 5, 1975, Mauritius

Ara ilu India: Swamijī, Seyin rope Brahma ni Adam ninu Bibeli? Se lati imoye India ni awon eyan yi tiṣẹ̀dà awon eto yi ton si fun ni oruko toyato?

Prabhupāda: Taba wo lati oju itan-akọọlẹ, wan seda, Aimoye odun toti koja ti Brahmā da awon iwe Veda, sugbon iwe Bibeli kosi ju odun ẹgbẹ̀wá ~ ẹgbàá Gege na agbudo mu eyito koko jade. Gbogbo awon esin ayeyi, lati Veda ni wanti mu imoye wan jade. Nitorina koseyi to pe ninu wan. Ojo ori Bibeli koju Odun ẹgbẹ̀wá ~ ẹgbàá lo. Kosi besele siro ojo-ori Veda.