YO/Prabhupada 0144 - Nkan ton pe ni maya niyen



Sri Isopanisad, Mantra 2-4 -- Los Angeles, May 6, 1970

prakṛteḥ kriyamāṇāni
guṇaiḥ karmāṇi sarvaśaḥ
ahaṅkāra-vimūḍhātmā
kartāham iti manyate
(BG 3.27)

Kṛṣṇa ma seto fun awon elesin fun ara re, fun awon eda aye yi, māyā ma seto wan. oniiseKṛṣṇa ni māyā je. gege bi ijoba sen seto awon omo-ilu, sugbon ijoba na seto awon omo-odaran lati ile-ewon , lati eka ile-ise ewon. Ijoba na ma seto wan. ninu ewon na, ijoba asi toju awon elewon lati ri pe - wan ri ounje je; to ba ni aisan wansi mu wan losi ile-iwosan. Gbogbo itoju tofe wanbe sugbon pelu ifiyaje. gege na ninu aye yi, itoju si nwa sugbon ifiyaje to wa pelu e si po. ounkooun teba se, ema jiya fun. Isoro lona meta lon pe eleyi. sugbon nitoripe awa labe idabo māyā awa si rope awon igbati wanyi lati odo māyā pe wan da gan. Se ri bayi? Nkan ton pe ni māyā niyen. lesekese teba gba imoye Kṛṣṇa sokan, Kṛṣṇa ma toju yin. Ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo mokṣayiṣyāmi mā śucaḥ (BG 18.66). lesekese teab teriba fun Krsna, osowipe "Moma toju re. Moma fun gbogbo yin ni igbala lati awon ese teti se." aimoye ese tati se laye wa. sugbon lesekese teba teriba fun Krsna asi toju yin asi seto lati yanju gbogbo ese teti se. Ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo mā śucaḥ." Ema ṣiyemeji " teyin ba ronu wipe " moti se gan laye mi bawo ni Krsna sefe dariji mi? Rara. Alagbara ni Krsna. O le funyin nigbala. Ise teyin ni lati se ni lati teriba fun, lai ṣiyemeji, efun ni gbogob aye yin, lehin na asi fun yin nigbala.