YO/Prabhupada 0150 - Ema fi ipaari si orin kiko yi
Lecture on SB 6.1.15 -- Denver, June 28, 1975
Athāpi te deva padāmbuja-dvayaṁ prasāda-leśānugṛhīta eva hi, jānāti tattvaṁ na cānya eko 'pi ciram vicinvan (SB 10.14.29). Awon eyan tonni ore-ofe Krsna awon lonle ni pye nipa Krsna. awon iyoku, na cānya eko 'pi ciram vicinvan. Fun igba odun to po gan, tonba foriro tabi eniti Krsna baje, ilana yi ma ranwalowo. Awon ilana lati Veda si po gan:
- ataḥ śrī-kṛṣṇa-nāmādi
- na bhaved grāhyam indriyaiḥ
- sevonmukhe hi jihvādau
- svayam eva sphuraty adaḥ
- (CC Madhya 17.136)
Krsna, Oruko re, ogo re, amuye re, ise re... Śrī-kṛṣṇa-nāmādi na bhaved... itumo Nāmādi niwipe " nkan to bere lati oruko mimo". Taba joko sori ipo ile-aye yi, ale korin mantra yi fun aimoye odun sugbon koni sise. Nkan ton pe ni nāmāparadha niyen. Sugbon oruko mim yi si l'agbara toje wipe teba tie korin na pelu ese, eyan si le yasi mimio. Nitorina ema fi ipaari si orin kiko yi. Nigbogbo gba ni ke korin Hare Krsna. Sugbon wanti kiloo fun wa wipe taba joko sori ipo ile-aye yi, kosi basele ni oye nipa Krsna Oruko mimo re, Iwa re, irisi re, ise re. Kolese se.
Ilana bhakti niyen. lehin na leyan lede ipo toleni oye nipa Krsna, lesekese na loma muye ati wonu ijoba Orun. Krsna si salaaye ninu Bhagavad-gita wipe, tyaktvā dehaṁ punar janma naiti mām eti (BG 4.9).