YO/Prabhupada 0152 - Eyan toje elese kosi bosefe ni imoye Krishna



Lecture on BG 1.31 -- London, July 24, 1973

Enikeni, gbogbo eyan lofe ni idunnu pelu Gṛha-kṣetra-sutāpta-vittaiḥ (SB 5.5.8), ile-aye oni-ile, pelu ilẹ. Ni aye igbayen kosi awon ile iṣẹ́ ẹlẹ́rọ . Nitorina kosi'di fun awon ile-iṣẹ́ ẹlẹ́rọ wanyi. ile. teba ni'le, ele gbin ounje yin. Sugbon ni oto-oro ile aye wa niyen. Ninu abule yi, ati riwipe ile to po wa, sugbon awon eyan o le gbin ounje wan. Wanti so awon maalu d'ounje, latile pa wan je. Eleyi o da. Gṛha-kṣetra. Ele di grhastha, sugbon egbudo gbin ounje yin lati ile yin, Gṛha-kṣetra. teba de ti gbin ounje yin tan, lehin na ele ni awon omode, Gṛha-kṣetra-suta-āpta-vitta. Ni orile-ede India, awon talaka ton son ko sin s'eto yi, ti oloko na ko bale toju maalu, koni se igbeyawo. Jaru ati garu. Iyawo ni itumo Jaru, maalu ni itumo garu. gege na teyan ba fe toju iyawo ogbudo le toju maalu. nitoripe lesekese teba gba iyawo sile, awon omode ma wa. sugbon awon omode wanyi o ni dagba dada teyin o ba le funwan ni wara maalu. wan gbudo mu wara to po gan, nitorina ni maalu se dabi iya fun wa. nitoripe iya to biwa yato, eyi ton funwa ni wara yato.

Gege na gbogbo eyan loyeko mu maalu ni pataki. Iya meje lani gege bi awon iwe sastra se so. Ādau mātā, iyawa talakoko, to bi wa. Ādau mātā, iya loje siwa. Guru-patnī, iyawo oluko wa. Iya loje si wa. Ādau mātā guru-patnī, brāhmaṇī. Iyawo brahmana, iya na loje siwa. Ādau mātā guru-patnī brāhmaṇī rāja-patnikā, Iyawo Oba. Iya loje si wa na. Melo loje bayi? Ādau mātā guru-patnī brāhmaṇī rāja-patnikā, lehin na dhenu. Maalu ni itumo Dhenu. iya loje siwa na. ati dhātrī. nọ́ọ̀sì ni itumo Dhātrī Dhenu dhātrī tathā pṛthvī, ile lori tawayi. Iya na ni ile yi je siwa. Opolopo awon eyan lon toju ile tonti wa, iyen na si da. Sugbon wan gbudo toju maalu na toda bi iya si gbogbo wa. sugbon awon eyan yi o fe toju iya wan. Nitorina lon sen jiya. Wan gbudo jiya. Ogun gbudo de, àjakalẹ, ìyan. lesekese ti awon eyan ba d'ẹlẹṣẹ, lesekese na ni iseda aye yi ma fiyaje wan. kosi besele yago fun.

Nitorina egbe imoye Krsna yi ma fun wa ni ona abao fun gbogbo isoro ta ni. awa sin ko awon eyan bonsele wa lai di elese. Nitoripe eyan toje elese kosi bosefe ni imoye Krsna. To bafe ni imoye Krsna ogbudo fi gbogbo iwa ese re sile.