YO/Prabhupada 0158 - Ilosiwaju ton fiku pa iya wan



Lecture on SB 5.5.3 -- Stockholm, September 9, 1973

Nūnaṁ pramattaḥ kurute vikarma (SB 5.5.4). ewọ nitumo Vikarma, awon iwa odaran. Iru ise meta lowa: karma, vikarma, akarma. Ise apinfunni nitumo Karma. Karma niyen. gege bi sva-karmaṇā. Ninu Bhagavad-gita: sva-karmaṇā tam abhyarcya (BG 18.46). Gbogbo wa lani awon ise apinfunni. Nibo ni imoye sayensi wa? Gege bi mose so l'ojo to oja, iyasoto ninu awujo eyan lori eto sayensi. Apa awon eyan ton longbon ju , oye kon kẹkọọ lati di brahmana. awon ti o l'ogbon to awon eleyi ele ko wan bonsele di alakoso. awon tio logbon to awon eleyi na, ele funwan lekoo lati di oniṣowo, oloko ati oluso awon maalu. Itooju awon maalu nikan ninu awon nkan fun Ilosiwaju ọrọ aje, sugbon awon oniranu wanyi o mo. Bonsele pa awon maaalu wanyi ni ilosowaju fun awon eyan bayi. Seti ri bayi. Awujo iranu. Ema bee wan. Ilana śāstra leleyi. Ema rowipe mokon fenu ba awujo awon oni ilugeeesi je. Nkan ti śāstra ti so niyen. Ati ni iriri lori awon oro yi.

Orisiri onigbawi lowa lori oro ilosiwaju oro-aje, sugbon awon eyan yi o mo wipe itoju awon maalu je ikan ninu awon eto fun ilosiwaju oro-aje. awon oniranu wanyi, kosi bonsele mo. wan rowipe eran pipa da. Sugbon idakeji loje. Nitorina kurute vikarma. Fun itẹlọrun ahon wan. Ele ni itelorun kanna lati wara, sugbon nitoripe oniranu ati asiwere lonje, wan rowipe tonba mu eje maalu daju tonba mu wara lo. Iyipada eje ni wara je, gbogbo eyan lomo. Gbogbo eyan mowipe. Lesekese teba bimo... keeto bimo na konisi wara kankan ninu omu iya re. Ninu omu awon omo-obirin kosi wara nibe. Sugbon lesekese ton ba bimo, wara ma jade nibe. Lesekese lon sele. Eto Oluwa niyen. Nitoripe omo gbudo jeun. Seti ri bi Olorun sen s'eto . Sugbon awa si s'eto ilosiwaju oro-aje wa. Lesekese teyan ba bimo, Olorun ti s'eto tojepe wara ma wa ninu omu iya re... Ilosiwaju oro-aje wa niyen. Bakanna maalu man funwa ni wara na. Iya loje siwa, sugbon ilosiwaju yi fe pa gbogbo iya wa tan. Ilosiwaju ton fiku pa iya wan. Seti ri bayi. Lati ibere aye yin leyin tin mu wara omu iya yin, nigbati iya yin ba darugbo seyin ma rowipe, " Iya yi o wulo mofunmi. Ejeka ge orun re," iru awujo wo leleleyi?