YO/Prabhupada 0200 - Alebu die le ba gbogbo nkan wanyi je



Lecture on CC Adi-lila 1.11 -- Mayapur, April 4, 1975

Wanti to ilana Veda yi tojepe bakanna eyan a bolowo ilana ibimo, iku, oro-arugbo ati aisan. Ni aye atijo, nogbati Viśvāmitra Muni wa ba Mahārāja Daśaratha fun Rāma-Lakṣmaṇa lati mu wan losinu igbo pe oni esu kan ton fun ni idanmu.. wan le fiku pa awon esu yi, sugbon ise lati pa awon eyan ise ksatriya niyen. Awujo Veda niyen. Konse ise brahmana. Gege na ipaade t'alakoko ti Viśvāmitra Muni gba lati Mahārāja Daśaratha, ni wipe aihiṣṭhaṁ yat punar-janma-jayāya: " Eyin eyan mimo eti fi awujo awon eyan sile. Eti lo gbe ninu igbo. Kinidi fun gbogbo eleyi? punar-janma-jayaya n'idi fun gbogbo eleyi, lati ni idari lori ibimo." Idi to wa niyen. gege na, nkankanna ni egbe imoye Krsna yi wa fun, punar-janma-jayaya, lati ni idari lori ibimo ati iku, Egbudo ranti eleyi. Alebu die ba ba gbogbo nkan yi je. Ile aye yi le gan. Daivī hy eṣā guṇamayī mama māyā duratyayā (BG 7.14). O le gan. Gege na gbogbo eyin omo-okurin ati obirin tewa lati orile-ede America, Mo dupe lowo yin gan. Sugbon ema nogere. Emu ise yi ni pataki. Nkan imi timo fe bere lowo awon omo-ilu America niwipe, America ni agbara to da lati ran gbogbo agbaye lowo, gege na teba sewaasu dada ni orile-ede yin.. gbogbo wan ko lon ma gba, sugbon ti iwonba die ba gba ni orile-ede yin, Tele je kan ya si imoye Krsna, nkan dada loma je si gbogbo agbaye. sugbon ipinnu kanna loje, punar-janma-jayaya: lati ni isegun lori ilana ibimo, iku ati ojo-arugbo. Oro-awada koleleyi, oto oro loje. Awon eyan o fe mu nkankan ni pataki. Sugbon ele ko awon eyan yin, bibeko, gbogbo agbaye yi ti baje. gege bi eranko lonseri, nipataki awon awujo kommunisti, wahala wan po gan - wan fe di eranko. Sugbon eranko ni wan.

Gege na mon ba awon ara ilu America soro nitoripe awon na o feran egbe kommunit wanyi. Wansile fi ipaari si nitoripe oro na sese bere, laipe yi. Deva asura, devasura, ija laarin awon orisa ati esu. Gege na ija yi si wan'be pelu oruko, "Kommunist ati awon kapitalist." sugbon esu po laarin awon kapitalist. Beeni. Nitoripe awon eyan yi o monipa sayensi Olorun. Ofin awon esu niyen. Gege na aye po ninu orile-ede yin lati jekon yipada lati awon iwa esu wanyi. lehin na wanma l'agbara lati ja pelu awon esu wanyi. Nitoripe tawa ba di deva.. Vaisnava nitumo Deva. Viṣṇu-bhakto bhaved deva āsuras tad-viparyayaḥ. Awon toje elesin Olorun Visnu, niwan pe ni deva tabi Orisa. awon tonje odi keji.. awon ton wa l'aapa keji awon na sini olorun wan. Awon esu feran lati s'adura si Oluwa Siva. tabi Ravana,... konsepe awon kan soro lasan. Esu nla ni Ravana je, sugbon elesin loje.... Awon eyan yi man s'adura si oluwa Siva fun awon ere ile-aye yi. ninu esin Visnu, ere ile-aye yi na wa. Sugbon Visnu fun ara re lon fun wan, konse lati karma. Sugbon awon Vaisnava, kosejo pe wan fe j'ere kankan. awon ere yi ma wa fun ara re, sugbon kon se nkan tonfe. Anyābhilāṣitā-śūnyam (Brs. 1.1.11). Lati j'ere ko ni ipinnu ile-aye wan. Ipinnu ile-aye wan ni bonsele- fun Visnu ni itelorun. Vaisnava niyen. Viṣṇur asya devataḥ. Na te... awon esu wanyi o de mowipe lati di Vaisnava ni ipo to gaju l'aaye yi. wan o mo.

Gege na nkan t'awan beere ni wipe gbogbo yin, teti gba ona Vaisanavism yi, Aye wa repete lati sewaasu egbe yi ninu orile-ede yin, gege na teyin o ba ni ilosiwaju kankan ni awon ilu toyato, ninu orile-ede yin ema ni ilosiwaju. Aye po gan. E gbiyanju lati je kon l'agbara lasi kon bale ja pelu awon ofin esu wanyi.

Ese pupo.