YO/Prabhupada 0215 - Egbudo ka iwe lehin na lo le ye yin
Interview with Newsweek -- July 14, 1976, New York
oni-ifọrọwanilẹnuwo: Se E le soro die lori ibi te ti wa, ati nkan tese nigbate kere.
Prabhupāda: Kini idi lati so fun yin?
oni-ifọrọwanilẹnuwo: E jo kile so?
Prabhupāda: Kini idi lati so fun yin?
oni-ifọrọwanilẹnuwo: te ba fe.
Prabhupāda: Kilode ti ma se fe?
oni-ifọrọwanilẹnuwo: awon ton se iru ise bi temi wan gbudo bi yin ni ibeere, bibeko ko ni si ise fun wa mo.
Hari-śauri: Oluko wa (Prabhupāda) fe ke bi wan ni ibeere to ni asepo pelu nkan ti awan so
Rāmeśvara: Awon eyan fe mo nipa yin, Śrīla Prabhupāda. Gege na ton ba de ni inifẹsi fun yin, lesekese lon ma ni ife fun awon iwe te ko Won si fe mo nipa olùkọ̀wé to ko gbogbo awon iwe ti awan ta
Prabhupāda: Eje ka soro nia awon iwe na Se awon iwe yi gbarale nkan ti olùkọ̀wé se tele.
oni-ifọrọwanilẹnuwo: Bo se ye mi, mo gbo pe onitumo ni eyin je fun iwe to po
Prabhupāda: Beeni. Iwe na ma soro gege bi mo se fi itumo si
oni-ifọrọwanilẹnuwo: Mo sin ro nu...
Prabhupāda: Ka iwe na, wa de ni oye. Dipo to ma fi bi mi, kon ka iwe na Ibi ti oye gangan wa ni yen
oni-ifọrọwanilẹnuwo: Mo kon fe mo bi won se ni igbagbo ninu esin yin, kilona ton gba ati de sinu imo yi
Rāmeśvara: O yee mi. Obirin na fe mo ibasepo laarin eyin ati Oluko yin Kilo fun yin ni atilẹyin lati bere egbe yi tabi lati ko gbogbo awon iwe te ko.
Prabhupāda: Awon ibeere wonyi elomi le daun. Ko fi be ni yi fun gbogbo eyan
Rāmeśvara: O da bi wi pe awujọ ẹda fe mo eni to da egbe wa yi
alejo obinrin: Beeni. A ronwa lowo. Awon eyan fe mo Awon eyan fe mo ni pa Okurin be teyin, nitoripe won ni ifara si yin Gege na won le bere lati ka iwe te ko.
Prabhupāda: Nialakoko teba beere sini ka awon iwe wonyi, o ma ye won.
oni-ifọrọwanilẹnuwo: wan ma mo nipa yin ton ba ka iwe na?
Prabhupāda: beeni
oni-ifọrọwanilẹnuwo: Se nkan te so ni yen.
Prabhupada: Beeni
oni-ifọrọwanilẹnuwo: Se nkan ti Oluko yin so ni yen?
Prabhupada: A le mo eyan to ba soro. Tāvac ca śobhate mūrkho yāvat kiñcin na bhāṣate: Laisi pe eyan to je omugọ laanu ko soro ko seni to le mo. To ba ti soro, oma ye yin nkan to je Gege na awon nkan ti mo so wa ninu iwe ti mo ko, te ba gbon oma ye yin Kosidi pe ke beere Ninu ile-ẹjọ, teba fe da agbẹjọro mo, asiko to ba laanu lema mo. Bibeko, agbẹjọro to da ni gbobo eyan je sugbon to ba soro ni ile-ejo, igbyen lema mo boya agbẹjọro to da ni tabi rara. Gege na egudo fe ti sile. E ka iweti mo ko. O ma ye o. Oye to daju wa ninu awon iwe na