YO/Prabhupada 0228 - Bawo lesele gbe laaye laisi iku



Lecture on BG 2.15 -- London, August 21, 1973

Gege na ibi apejọ, ati ilosiwaju ninu eto sayensi ati akeko wan, ati imoye wan, gbogbo nkan ton se, lati le ni alafi aninu aye na ni Gṛha-vratānām. Wan fe se igbadun ni ibi ko le sese. Awon asiwere wan yi ko le ye wan. Te ba fe ki inu yin dun, e yipo si Krsna Mām upetya tu kaunteya duḥkhālayam aśāśvataṁ nāpnuvanti (BG 8.15). Ti eyan ba wa si Ijoba mi, koni wa mo si ile aye yi Duḥkhālayam. Oruko ti Krsna fi juwe ile-aye yi ni yen. itumo Ālayam ni ibi, ibanuje ni duḥkha Ibanuje ni Gbogbo nkan ile-aye yi, sugbon awon eyan ton ti gbagbe ara wan ninu māyā, wan si gba ibanuje yi bi nkan to da māyā, ni eyi je. Idunnu ko Ara kurin ton se ise lojojumo ati aaro d'aale. fun iwe kekere tan ko, "Igbẹkẹle wa n'be ninu Oluwa". Si gba iwe kekere yi. mo si yanyi je Se be ko? Igbekele wa n'be ninu Oluwa. Mo ti s'adehun lati son owo fun yin. E gba iwe yi Ko si to nkankan, wan si ko ogorun meta dollar si ori e.. Mo de ro pe inumi dun. Gege na mo ti gba iwe kekere yi Otan. wan sin yan ara wan je gege na.

Ko ye ka ni isoro nipa ibanuje tabi idunnu aye yi bi ase le se itesiwajuj ninu ise imoye Krsna Bi a sele se. Caitanya Mahāprabhu si fun wa ni awon ilana to da:

harer nāma harer nāma harer nāmaiva kevalam
kalau nāsty eva nāsty eva nāsty eva gatir anyathā
(CC Adi 17.21)

Ni aye ooni, awa o si le gbawe Ekorin Hare Krsna na Eyi na , aa le se. se ri se ri bi alailoriire l aje gege bi ile aye yi se ri ni yen Mandāḥ sumanda-matayo manda-bhāgyā upadrutāḥ (SB 1.1.10). Asiwere ni gbogbo wa je. Itumo Manda ni nkan to buru ati sumanda-matayaḥ. ton ba de fe tun nkan se wan si gba Oluko to si je asiwere bi awan na Mandāḥ sumanda-matayaḥ. awon eyan yi o si ni Ofin kan kan, ni alakoko gbogbo wa lon baje, ton ba de gba nkan, nkan ton gba na ti baje kilode? alailorire. Mandāḥ sumanda-matayo manda-bhāgyāḥ (SB 1.1.10). Itumu Manda-bhāgyāḥ ni alailorire lori iyen, upadrutāḥ. wan si ni isoro ounje, ojo o si ro, wan si san owo-ori.. Ile-aye ta wa ni yen Nitorina Caitanya Mahāprabhu so wi pe.. Awon iwe mimo Veda so wi pe, awon eyan bayi o le ko Yoga wan si le s'sasaro, tabi kon gbe ebo, tabi kon ko ile-olorun, gbogbo eleyi soro ni aye isin ekorin Hare Kṛṣṇa, Hare Kṛṣṇa, Kṛṣṇa Kṛṣṇa, Hare Hare/ Hare Rāma, Hare Rāma, Rāma Rāma, Hare Hare, die die ema ni imoyo bi esele di alaiku.